Transcript
Page 1: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

• NAER\..S

lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI.

Nl ORILE EDE NIGERIA

RECOMMENDED PRACTICES NO. 5 (Yoruba Version)

Page 2: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

lLANA Tl 0 PEYE

FUN

OGBIN IRE:SI

Nl ORILE EDE N '~GERIJ'~

EXTENSION RECOMMENDED PRACTICES NO.5 (Yorubet Version)

Page 3: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI

lresi gbigbin je ise ti o se pataki ni ile Nigeria nitori

wiwulo iresi fun jije ati fun tita. Kosi ibikan ni ile Nigeria

ti a ko ti le gbin iresi. Nitorina awon agbe ni lati mo

ilana ti o peye fun iresi gbigbin.

A won onimo ijinle ninu ise oko ti fi ilana ti o dara ti a le

gba gbin iresi fun ikore yanture ati fun iresi ti o peye

koda ti a le fi yang an Iarin iresi ti nti ilu okere wo ile wa

lele. Nitori idi eyi, yio dara pupo bi awon agbe olugbin

iresi ba ntele ilana inu iwe yi dada fun gbigbin iresi ati

titoju lehin ti a ba ti kore re tan.

ILE Tl 0 DARA FUN OGBIN IRESI

Orisi ile ti o dara lati gbin iresi si :

• lie akuro: lresi se gbin si eteti akuro tabi adagun

omi. !ru ile bee gbodo le gba ami duro tabi ki omi

wa nibe fun osu merin si marun. Ni awon agbegbe

miran, ami le wa nibe ju osu marun lo.

• lie akuro inu omi: lie akuro ti omi le dagun si fun

osu mefa fun ogbin iresi.

• A take ile ti o ni ora ati ami ojo fun bi osu meta si osu

meje.

2

Page 4: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

IRUFE HORO IRESJ Tl 0 DARA LATI MA GBIN

lie akuro:

FARO 12: lresi Faro 12 se gbin si ile akuro ti ole gba

omi duro fun osu merin si marun. lru iresi Faro 12 yi ni

ale kore lehin osu merin abo.

FARO 10: lresi Faro 10 dara lati gbin si ile akuro,

nitoripe iresi yi lese dada ninu ile akuro ti omi re tutu.

Eyi ni kan ko, iresi yi tun se gbin ni agbegbe ti o tutu bi

Jos. lresi yi se kore lehin osu merin si osu marun.

FARO 13: Faro 13 ni awon onimo ijinle fi owo si lati

gbin si ile akuro gege bi Faro 12. Eyi si se gbin si ile ti

a fa omi si lati je ki ile tutu tabi re gege bi oko iresi

abomirin ti o wo po ni apa oke oya fun ogbin iresi lemeji

ni odun kan. 0 se kore leyin osu merin abo si marun.

Awon iresi ti a re tete kore ni Faro 27 ati 44. t i awon

iresi ti yio pe ki a to le kore won je Faro 8, 12 ati 15.

A won iresi ti o rna npe die ki a to kore won ni iresi Faro

29,35,37,50,51 ati 52.

Faro 15 ni awon onimo ijinle fowo si pe o se gbin si

oko akuro ati oko ti a le fi omi won. lrufe iresi yi nilo

ajile oniyo lati se dada. A si le kore re ni osu merin abo . si marun abo.

..,

.)

Page 5: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

Faro 16 ni awon animo ijinle fi owo si pe o se gbin si

ibi ti ale gbin Faro 15 si. 0 rna nse kore lehin osu

merin abo si osu marun abo.

Faro 19 ni awon animo ijinle fi owo si pe o se gbin si

oko akuro ati ile akuro atowoda ni apa Oke Oya. 0 rna

nse kore lehin osu merin abo si osu marun.

Faro 21 ni awon onimo ijinle fi owo si pe o se gbin si

akuro ati ile ti a ti bomin rin (akuro atowoda} ti ale fi

omi won irugbin won gegebi eyi ti o wa ni Niger,

Kaduna,Zamfara ati Sokoto states ati awon ile ise to

nri si idagbasoko ibomirin ise ogbin (River Basins)

lagbegbe re. lrufe horo iresi yi nilo iwonba ajile oniyo o

si rna ngbomo dada. Eyi ni kan ko, o tete rna ndagba,

kii si se tabi da lule. 0 rna nse kore lehin osu meta si

merin.

Faro 24 dara lati gbin si akuro ati oko ti a ti bomirin

tabi bomi won ni awon agbegbe gege bi Wurno ni ipinle

Sokoto ati Yau lagbegbe Ngala ni ipinle Barno. 0 rna

nse kore lehin osu merin abo si marun.

Faro 26 dara lati gbin si ile ti a ti bomi rin ati ile akuro.

Ale kore re lehin osu merin abo.

4

Page 6: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

Faro 27 dara lati gbin si ile akuro ati ile ti a ti fa omi si.

Faro 27 ma ntete dagba, o si se kore lehin osu meta

abo si merin.

Faro 28 se gbin si ori ile ti o dara fun Faro 27. 0 si se

kore lehin osu merin abo .

Gbogbo awon irufe horo iresi ti a ti menu ba ni o je

dandan lati gbin si oko akuro. Nigbati a ba ngbiyanju

lati wa irugbin ti o dara fun ile akuro oni erofo. a gbodo

gbe ojo ikore yewo lati ni idaniloju pe omi wa ni arowoto

lakoko ogbin iresi yi.

Faro 13, 15, 16, 17, 26, 28, 44, 47, 48, 49, 50, 51 ati

52 je iresi igbalode ti o peye ju awon ta ti mo tele lo.

Awon eya irufe Faro wonyi yato si awon eya iresi

abafaiye ti o ti wa tipe ,ti o je wipe won ma nga, ti won

si ma nda lule.

lrugbin iresi ti o dara fun akuro oni erofo:

Faro 4 dara lati gbin si oko akuro inu erofo pelu ojo ti

nro fun osu marun si meje. lresi Faro 41e farada om.i to

jin to ese bata meta si mefa. 0 se kore lehin osu mefa

si meje abo.

5

Page 7: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

Awon eya iresi ti o tun dara fun akuro inu erofo gegebi

Faro 4 ni Faro 7, 14 ati 15.

lrugbin iresi ti o dara fun agbegbe ekun omi:

Faro 6: lrugbin yi ni ale dape gegebi iresi ti o nlefo

loju omi. Faro 6 ni awon onimo ijinle fowo si pe o se

gbin si agbegbe ti ekun omi saba ma nwa. lru ekun

omi bee le jin to ese bata meta abo .. Faro 6 manse

dada ninu iru ekun omi bayi, papa julo ni agbegbe bi

atonutoji Rima (River valley) ati ni Birni Kebbi ni ipinle

Sokoto ati Kebbi. 0 se kore ni osu meta si meta abo.

Faro 7: I rug bin yi nse dada ni ibikibi ti Faro 6 ba ti se

gbin. Sugbon o ma ngbomo ju Faro 61o. A won animo

ijinle ti fowosi gbigbin re. 0 se kore lehin Osu marun si

meje.

Faro 4: Gegebi Faro 7, Faro 4 se gbin bakanna. 0 si

tun se kore lehin osu marun abo si osu meje.

lrugbin iresi to dara fun ori ile papa (atake):

Faro 1: Faro 1 manse dada pelu ojo ti o nro dede ni

agbegbe Oke Oya ni ile Nigeria. Osi tun ma ntete

dagba. Awon irugbin ti o dabi Faro 1 ni Faro 40, 45,

54 ati 55. 6

Page 8: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

Faro 48, 49 ati S3 ma npe die bi o tile je pe awon na

ma nse dada lagbegbe Oke Oya ti ojo ti ma nro dede.

Awon onirno ijinle fowo si pe awon irufe iresi t i a ti

menuba wonyi se fi ropo Faro 3. Osu merin si marun

ni a lese ikore iresi yi.

Faro 25: Gege bi Faro 11, irufe iresi yi le farada arun

ewe alawo ile (brown spot disease) ti o ma nda iresi

afojo dagba (upland rice) lamu. 0 si ma nse bo dada

pelu ero. lrufe iresi bi eleyi ma ndagba fun ikore lehin

osu meta abo si merino le die.

Awon ibi ti a ti le ri irugbin iresllgbalode

E kan si a won ile ise wonyi fun irugbin iresi ti o dara:

a) Akowe agbe ni agbegbe re (Extension Agent)

b) lie ise idagbasoke ise ogbin (ADP) ti o wa

lagbegbe re.

c) lie ise ogbin ti o nri si idagbasoke ati ibomirin

(River Basins Authority) lag beg be re.

d) Eka ile ise National Seeds Service ti o wa

lagbegbe re

e) lie ise ti ijoba fowo si lati rna ta irugbin iresi

(Seed companies)

7

Page 9: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

ITOJU ILE FUN OGBIN IRES!

Fun iresi akuro: Pese ojuba pelu ebe ti o te rere

kekere (nursery beds)ninu osu karun si ikefa. Eleyi wa

lowo bi ojo ba se nro dada si. Ti o ba nlo akuro

alabomirin (irrigation) nibi ti omi wa fun iresi ninu osu

karun, pese ebe re (nursery beds) ninu osu kerin odun.

A won ebe ti o te rere kekere ti a ti pese gbodo ga ju ori

ile lo. Awon poro (alafo) ti o wa ni aarin awon ebe wonyi

gbodo kun fun omi. Ori awon ebe wonyi gbodo se

lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo

de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) aj ile

oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan (42.6g) ajile

onihoro (super phosphate) ti a ti popo si iwon mita meta

Iori ebe ti a ti pese sile. Rii wipe o po ajile yi mo ile ni

kete ti o ti fi sii, ki o to dipe o gbin iresi si ori ebe fun

biba.

Osuwon iresi ti a gbodo gbin

Fun Akuro: Lo iwon horo iresi kongo mewa si metala

(Swamp Ricce) (40-50kg) fun saare oko meji abo (1

hectare)

Fun akuro inu omi: (Floating rice) Lo iwon kongo

medogbon (1 OOkg) horo iresi fun saare oko meji abo

(1 hectare). Sora lati gbin opo omo iresi re soju kanna.

8

Page 10: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

Eieyi yo dena a run Kokoro ti a n pe ni pyncuieria rna

nfa.

Fun ogbin ori ile Atake/papa (Upland): Lo iwon

kongo metala si medogun horo iresi lati gbin saare

meji abo (1 hectare. Ti o ba je pe o fe fon horo iresi

sari oko, lo iwon ogun kongo si kongo medogbon horo

iresi lati gbin oko saare meji abo (1 hectare).

Asiko ogbin iresi (Time of Planting)

Fun Akuro: - Gbin horo iresi re ni osu karun odun, o

pe ju ni ibere osu kefa. Eleyi wa lowo bi omi ba se wa

larowoto sii. Tu awon odo iresi re lo ni ipari osu kefa

lehin igbati odo iresi re bati to ose meji si ose merin.

Rii wipe awon omo iresi toga daada lo tu fun lilo.

Fun akuro inu omi- Nibiti o ba ti seese, gbin iresi si

oju iba ti a ti pese sile. Tu odo iresi re lo ni kete ti omi

bati wa Iori oko. Ti ojuba (nursery) ko base pese, fon

horo iresi re sori oko ni iwon kongo merinla fun saare

oko meji abo. Se itoju ile re nigbati ojo akoko ba ti ro.

Eeleyi yio fun o ni anfani lati dena epo. Fon horo iresi

nigbati ojo ba ti fese mule.daada. Gbin iresi re ni o ku

die ki osu karun pari tabi ni ibere osu kefa nigbati ojo

ba ti fese mule. Ni asiko yi, ile yio li rin daada. Ti o ba

seese gbin oko re ni kete to'jo bati fese mule.

Page 11: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

Alafo Iarin odo igi iresi kan si ekeji

Lo odo iresi re ni ori poro sisentele (rows) ni ese bata

kan (30 em) si ara won pelu horo iresi meji-meji ninu

iho kokan.

OGUNAJILE

Awon animo ijinle nipa ise ogbin ti fowo si awon ilana

wonyi ni sisentele ana ta le gba lati ma fi ajile si oko

iresi akuro elerofo (swamp rice) ati awon oko t i a ti bu

ami rin (irrigated rice).

• lresi Akuro (swamp rice): Fi iwon apo ajile (oniyo)

kan abo (80kg) pelu ilaji apo o le die ajile onihoro

(phosphorous (30kg) ati ajile ani kaun (potassium (30kg)

si saare oko meji abo.

Ajile onihoro (super phosphate) se fi si oko iresi .. Fi

iwon apo ajile meta ati abo (188kg/ha) ajile oni horo

Super phosphate ni ose kan ki o to lo odo iresi re. Ri

wipe o po ajile re yi mo ile daada.

Ajile oni Kaun (Potassium): Fi apo kan ajile oni kaun

(50kg) si iwon oko saare meji abo. Ri wipe o po mo

ile daada ni igbakanna ti o ba f i ajile onihoro super

phosphate sinu oko re.

10

Page 12: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

Ajile Oniyo (Urea): Fi apo merin ajile oniyo (200kg) si

oko re ni ipin meji (2 bags). Je ki eleyi je asiko ti iresi re

nilo ajile oniyo. A gbodo fi ipin alakoko (2 bags) si oko

iresi nigbati a ba se akiyesi pe awon iresi wa fe ma

peka .. I pin keji Ia gbodo fi soko nigbati iresi wa ba pe

ose mejo lehin igbati a ti lo iresi si ori oko. Eleyi ni

awon animo ijinle fowo si peale lo, paapa julo fun awon

iresi to ma npe Iori oko bi iresi Faro 12. Fun awon ti kii

pe dagba gegebi ires( Faro 13, a gbodo fi ipin Keji

ajile si oko lehin ose kefa ti a ti lo omo iresi si ori oko.

lresi bi Faro 15, 19, 23 , 27 ati 28 ti won je awon iresi ti

o ma ngbomo daada ti o si tun ma nse daada, pelu

ajile oniyo nilo ajile oniyo ju awon yo~u lo. Apo meji

abo ajile oniyo ammonium sulphate tabi apo meta abo

ti ajile on iyo urea lagbodo lo fun saare meji abo.

Ajile Alapapo (15-15:15): Apo merin ajile alapapo (15-

15 -15) ati apo marun, ajile oniyo (urea), di lilo ni

sisentele. Eyi ni awon onimo ijinle fowo si lati lo fun oko

iresi. Ona meji Ia le gba lati fi ajile si oko iresi :

• Fun oko ti kopo, ri wipe o di ona ti omi ngba wo inu

oko ati ona ti omi ngba jade lati inu poro ebe. Fi

ajile re si poro ebe yi . Lehin eleyi si omi ti o ti daduro

i 1

Page 13: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

lati wole fun igba die, se enu on a mejeji ti omi ngba

wole at eyi ti ngba jade fun ajo mew a, eleyi yoo fun

ile ni anfani ati gba ajile sara daada.

• Ona miran ti a tun le gba fi ajile si iresi, ni wipe ki a

fa omi to wa ninu oko kuro. Lehin eyi, a o fon ajile si

ori ile oko iresi. A gbodo po ajile yi mo ile daada.

Ni kete ti a se eyi, a gbodo fi aye gba ekun ami lati

wo inu oko. Eleyi ko ni je ki a padanu ajile ta sese fi

si oko. Ninu ako iresi ti a ti bu ami rin, ajile oniyo

Ia gbodo fi si oko ni ipin meta dedee, a si gbodo je

ko jinle daada nigba ti aba nlo odo iresi wa. Fon

ajile si oko iresi re lehin ose merin ati lehin ose mefa

si mejo lehin ti a ti lo odo iresi si inu oko. Eleyi ni

awon onimo ijinle fowo si pe ki agbe rna mulo.

• Fifi ajile si oko iresi akuro inu omi (Floating

Rice): Fi apo kan (50kg) ajile oniya (urea) ati (30kg)

idaj i o le die apo ajile onihoro phosphorus ati ajile

oni kanun potassium si saare oko meji abo (1 ha).

• Fifi ajile si oko akuro elekun omi (Floating Rice).

Fi apo ajile oniyo kan ati abo o le die (80kg) ati

idaji apo ajile kan o le die ti phosphorus (30kg) ati

12

Page 14: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

ajile oni kaun potassium (30kg) (50:30:30) si saare

oko meji abo (1 ha).

• Fi apo meji abo ajile oniyo ( Urea ~ ( 125kg/ha) tab;

apo merin ajile aiapapo ( 15 15 15} si okc ires; ~E.

Lehin eyi, fi apo meji ajile oniyo ammonium sulphate

si iresi. Eleyi Ia gbodo fi si ori ebe. Fi apo ajile super

phosphate meta abo o le die (188kg) si saare oko

meji abo tabi apo ajile oni kaun (Muriate of potash)

nigbati oba ku ojo die t i a o lo odo iresi tabi gbin

iresi wa. Adapo awon aj ile mejeji yi ni a gbodo po

mo ile daada. Agbodo tete fi omi fun ile oko ires i yi

ni kete ti a ba ti fi ajile sii tan.

• Fifi ajile si oko iresi a fi ojo gbin (Upland Rice)

Apo ajile kan o le die si apo kan abo ajile oniyo

urea (60-80kg) ati idaji apo ole die ti ajile onihoro

phosphorus (30kg) ati t i oni kanhun (potassium)

{30kg) si saare oko meji abo

lresi afojo gbin manse daada pelu ajile ti o bani nitorgen

\ehin odun kan si ekeji ti a ba ti fi oko wa sile lai da oko

na. Fi ajile si oko iresi ni ipin meji deede lehin ose keji

ati ose kefa ti iresi ba ti hu. Ni akoko yii, wa fi apo

merin ajile 15- 15 15 (200kg/ha) si saare meji abo.

13

Page 15: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

Lehin eleyi, fi ajile oniyo yi kanna ni iwon apo meji abo

si oko sare meji abo. Lehin eleyi fi apo kan ajile oniyo

ammonium sulphate si egbegbe omo iresi re. Ni ori ile

ti ati nda fun igba pipe, fi ajile oniyo apo merin ati apo

meji (115kg/ha) ajile super phosphate ati idaji apo ole

die ajile onikahun (33kg) si oko iresi. Awon ajile yi Ia

gbodo fi si oko ni arin ose kan si ekeji.

AJILE ADAYEBA (ORGANIC MANURE)

lgi iresi ti o ti gbe ati iyangbo iresi_ (rice bran) ni a le lo

gegebi ajile adayeba fun ile ti ko ni ora to. Ko awon igi

iresi ti o ti gbe jo lehin igba ti o ti kore iresi re, ki o si ma

fi omi si lorekore ti o ba seese bee. lgi iresi yi a jera,

yio si di ajile. Lehin eleyi, ajile adayeba yi ti di lilo. Fi

awon igi ti o ti jera yi (ajile adayeba) si inu oko iresi ni

odiwon apo mewa ajile (500kg/ha) si oko saare meji

abo. Ri wipe o po mo ile daada.

Ona miran ti a le gba ni pe ki a bo igi iresi ti ko jera

moledada. Ri wipe o fon awon igi iresi t i o ti gbe ka inu

oko, ni kete lehin eleyi, faye gba ekun omi lati wo inu

oko daa da. Lehin osu kan ti a ti se eleyi, po igi iresi ti

o ti gbe yi mo ile daada ki o to di pe o f i ajile si. Ajile ti a

gbodo fi si gbodo mo ni iwon t i awon onimo ijinle fowo

si. Dajudaju, fifi ajile adayeba si oko, a je ki ile wale

gba omi ati awon ora ti o wulo tun iresi duro daada,

eleyi a je ki ere po daada Iori ile ti ko lora to. 14

Page 16: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

EPO PIPA NINU OKO IRESI Ri wipe o nro oko iresi re daada, papajulo lasiko ti iresi

wa ba sese nhu. Fun oko akuro, ri wipe o nko awon

epo ti o ba ro jo segbe kan, ki o si se itoju awon be be t i

o ngba omi duro lodiwon ekun omi ninu oko iresi. Ri

wipe omi ti ko jin ju iwon kokose re lo nwa ni oko re

kakiri. lresi ti o wa ni c:>ko akuro elekun omi (floating

rice) gbodo rna ni ekun omi ni igbati iresi ba sese nhu.

Epo Pipa Pelu owo Epo pipa ninu oko re ko nidi ohun ti owo ko ni ka t i o ba

je wipe oko ti a lo iresi wa je eyi ti a ntoju daada tele.

Sibesibe a gbodo mo ro oko iresi lemeji, ni akoko, ni

ose meji si meta ati ni ekeji, ose marun si mefa lehin

igba ti a ti lo omo iresi sori oko. Epo inu oko iresi ni a

gbodo fi owo tu ki a si ko won jo segbe kan. A won oko

ti a ko jo wonyi gbodo wa nibe titi iresi yio fi dagba,

elelyi yo je ki omi ati ajile wulo dada fun ile oko iresi wa.

Ogun Pakopako (herbicides) Ninu oko iresi ti o tobi tabi oko ti a nfi pese horo iresi,

ogun pakopako wulo gidigidi paapa julo nibiti alagbase

ko ti po rara. Orisirisi epo ni ole hu ninu oko iresi gegebi

ti awon ohun ogbin yooku. Li!o ogun pakopako kan

tabi ka papo mo miran wulo gidi !ati pa orisirisi epo ti o

le wa ninu oko iresi.

15

Page 17: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

Ogun Pakopako TaLe Po Mora Won

Ona bi a se le lo ogun apako fun saare oko meji ati abo

ati igba ti a le lo ni yi .

a. Propanii+Bentazon 3.0 : Fin oko •e lehin ti iresi

bati hu jade. Fun ogun ta ti po po, fin iresi lehin ose

meji si meta ti o ti gbin iresi re.

b. Propanil + 240 3.0: Fin oko re lehin ti iresi bati hu

jade. Fin oko na lehin ose meji si meta ti omo iresi

ba ti hu tabi ti o ti lo won

c. Propanil+thiobecarb 3.36: Fin oko re lehin t i iresi

bati hu jade. Fin oko na lehin ose meji si meta ti

omo iresi ba ti hu tabi ti o lo won.

d . Oxadiazon 10: Fin oko re ki oto di pe iresi t i o

sese gbin hu jade . Fun iresi ta sese gbin, fin oko

na lehin ojo meta ti o ti gbin.

e. Butachlor 10: Fin oko re ki oto di pe horo ti o se

se gbin hu jade. Fin oko na Iarin ojo meta lehin igba

ti o ti gbin iresi.

16

Page 18: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

Ona Ti ALe Gba Lati Kapa Kokoro Ati Arun Ninu

Oko lresi

KOKORO Tl 0 NDA IRESI LAAMU:

Kokoro ti o ma nda iresi laamu ko se bee po to ti awon

ohun o9bin miran ti a ngbin ni Oke Oya. Awon a run meji

ti o se Koko lati gbogun ti ni Sunmunu (borers) ati

tamukoro (army worms).

a. Kokoro sunmunu (borers):

Sunmunu je okan lara awon kokoro ti o ma nba

iresi finra. Kokoro sunmunu rna nba iresi finra lati

omo iresi titi di igba ti yio to koore. Kokoro

sunmunu ma nye eyin si ori tabi odikeji ewe :res1

tabi Iori ewe iresi ti o korajo. Awon omo kokoro ti

o bajade lati inu eyin wonyi ni rna n wo inu igi iresi

lo, ti won yi o si baje kanle.

lpalara ti orisirisi kokoro sunmunu manse fun iresi

ri bakanna. Awon kokoro sunmunu yi rna ngbe ibi

ti igi iresi ti ndagba lati isale. A ma je igi iresi yi lati

inu tlti ti igi iresi tabi eka re y!o fi ku. Bi o se le mo

bi kokoro yi nse se ose ni wipe omunu igi iresi a

bere si gbe. Kokoro sunmunu ti o ba digbolu iresi

nigba ti iresi ba ntanna buru jai, o si rna nyori si

17

Page 19: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

ofifo eya ara iresi ti o ye ko gbomo, eleyi a si mu ki

ori iresi funfun. Awon eya kokoro sunmunu miran

kii sose lona meji ti a ti menu ba, sugbon won kije

ki iresi gbomo dada bi o ti ye.

ONA IDENA KOKORO SUNMONU

• On a lmototo: Ona ti ale gba dena kokoro sunmonu

lai lo ogun apakokoro ni wipe: lehin igbati o ba ti

kore iresi, ri wipe o jo ageku igi iresi ti o wa ninu

oko. Sise eleyi a pa awon omo kokoro sunmunu ti o

fi ara pamo si inu won fun abo. Ona miran ti a le gba

ni wipe a fe je ki ekun omi wo inu oko iresi ti a run yi

ti nba finra tele. Eleyi le waye lehin ose kan ti a ti

kore oko iresi. Ekun omi yi abo awon igi iresi mole,

eleyi a je ki kokoro sunmunu ti o wa ninu igi iresi

segbe sinnu omi.

• Lilo ogun apakokoro: Fin ogun apakokoro

carbonfuran ni iwon 1.0 a.i/ha tabi iwon 15.25kg/ha

si saare oko meji abo, o si le lo vetox 85 (carba ryl)

ni iwon 1.65kg ninu 2.2.5kg/ha.

B. Tamukoro (army worms):

Kokoro tamukoro je kokoro kan ti o ma nsose ni

oko iresi ti a gbin si ori ile ti ki se akuro. Kokoro

18

Page 20: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

ikan nama nsose ninu oko ires i afojo gbin. Ogun

apakokoro vetox 85 (carbaryl), ogun apakokoro

cypermetrin tabi landacyhalotrin ma nsise dada lati

pa kokoro tamukoro. Lita kan awon ogun apakokoro

yii (cypermetrin tabi lamdacyhalctin ) ni a o io si ori

saare oko meji abo oko iresi.

ARUN Tl 0 NDA IRESI LAAMU

Orisi a run meji lo ma nda resi laamu. Awon naa ni arun

ti a npe ni Brown leaf spot ati eyi ti anpe ni Blast.

• Helminthosporium oyzae ti o je olu alarun (fungus)

ni ma nfa a run ti anpe ni (Brown leaf spot). Aarun yi

ma ngberan ninu oko iresi ni apa Oke Oya ile

Nigeria. Bi a run yi se nsose yato lati adugbo kan si

ekeji. Arun yi je eyi ti o rna nwa lara horo iresi, o si le

gbeeran lara horo iresi odun to koja si ara omo igi

iresi tuntun ti o wa Iori oko. 0 si le wa lara awon epo

iresi ti o fara jo iresi. 0 si tun le wa ninu omi ala run

ti a fe lo fun ibu omi rin ile. Arun ti a pe ni Brown leaf

spot yato si a run t i a npe ni blast nip a bi o ti se nda

iresi laamu. Arun ti a npe ni Brown leaf spot ma

nsose lara awon iresi ti o ti dagba daada. Ewe iresi

ni arun yii ma nda laamu. Arun yi ma mu ewe iresi

gbe. Awo kaaki tototo a ma wa Iori ewe iresi ni

19

Page 21: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

iwon centimeter merino din die (3.8cm). Awo tototo

ti o wa ni ori eya igi iresi ti a npe ni (ghimes) rna ni

awo kaaki ti o dudu. Nigbamiran, gbogbo eya igi yi

(ghumes) ani awo dudu kirimu pelu iho fofofo

• Nigbati oko dida oju odun ba ku die ko pari, olu

alarun fungus rna nsose lara koko igi t i a npe ni

nodes of rachis ni ede gesi, eleyi a fi ayegba a run ti

a npe ni blast eyi ti o yato si a run ti a npe ni pyrakularia

rna nfa. Awo kaaki ati awo ofeefe (velvety) ma nwa

ni ogangan ibi ti arun yi ti nsose.

Ona ti ale fi dena arun yi (control}

Ona ti a file dena arun lai lo ogun apakokoro ni wipe ki

o jo gbogbo awon epo ti ole gbabode ati awon ohun

ogbin ti ko wulo mo lehin ikore, ki o silo horo iresi ti o

dangajia ti ko ni arun. Ri wipe o fi ajile ti awon animo

ijinle fowosi ni iwontun wonsi si oko iresi re.

Ona ti ale fi dena a run nipase ogun lila ni wipe ki o po

apron star tabi super homoid ni iwon ideri oti meji

sikongo horo iresi kan. Ogun apakokoro Diethane m45

tabi mancozeb se lo. ldaji kongo ogun yi se lo fun saare

meji abo losose fun ose meta.

• Blast: Arun ti anpe ni blast ni olu (fungus) alarun

(Pyricularia oryzae) ma nfa. Arun yi je arun kan

20

Page 22: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

gbogi ni agbegbe ti a ti ngbin iresi akuro ni orile

ede wa Nigeria. Arun blast yi ma nsose ni akoko ti

odo iresi banda gba. Arun yi ma nsose nigbati iresi

ba titan ina tan, o ma nmu eya iresi ti o ngbomo ra.

Arun yi ma nfoju han iakoko iara ewe ()dO iresi

gegebi awo kaaki ti koju ori abere lo ni ibere ti yio

si dagba ti yio fe gba gbogbo oju ewe iresi. Aarin

awo kaaki yi yio yipada si awo eeru ti yio si tutu

pelu omi. Lehin igba die, iresi yi yio gbe, a si yipada

si awo kaaki . Nibiti aye bati gba arun blast yi, awon

iho ti o lu foofo le parapo, eleyi a je ki ewe iresi ro.

Awo kaaki tototo lara ewe nipase arun blast ma

nsose lara odo iresi ni gbati o ba wa ni ojuba. ,Arun

yi le pa gbogbo odo iresi patapata.

Arun yi ma nse ose ju nigbati o ba digbolu enu koko

ti igi iresi fi ntanna. Enu koko (node) yi ma saaba

bo sowo arun yi paapa julo nigbati eya igi iresi ti o

ngbomo (panicle) ba sese nyo. Bi eya igi ti o

ngbomo ba ti ndagba, arun yi ko se bee lagbara

mo taara. Enu koko (node). a bere si gbe diedie

pelu awo kaaki rakorako. Eleyi tete ma nje ki koko

iresi jabo. Ti a run yi ba sele ki o to di wipe omo iresi

ni wara ninu (milk stage), irufe iresi bayi ki lomo rara.

Ti o ba je pe arun yi sose lehinwa, horo iresi ko ni

gbomo daada. lru omo bee ma ngbon danu, a si ri

21

Page 23: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

lubulubu. Arun yi le fi oju han lara koko (node). Ti

eleyi bari bee, koko a yipada si awo dudu a si rna

gbon danu

Bi a ti se le dena arun blast

Ona ti a le fi dena arun lai lo ogun apa kokoro pin si

meji. Ekinni, rii wipe o gbin horo iresi ti o laje sara .

Ekeji , ni wipe, ki o gbin iresi lai lalafo ni ajuba. Nipari,

lo ajile NPK ni ana ti awan onimo ijinle fowo si.

Ona ti a le fi dena arun nipase agun li la ni wipe ki a fin

ogun apakakoro mancozeb tabi Diethane tabi benomyl

ni iwon 1.5kg/ha nigbati ami arun yi ba fi aju han. Tun

oko yi fin losose fun ose meji

IKORE

lresi t i di kikore nigbati a ba kiyesi pe omo re ti le tabi

gbo daada. Awo iru iresi bee, a yipada si awo ofefe

(yellow), eyi ni igbati a ba pe osu kan abo lehin ti iresi

wa ti ntanna. Ri wipe a ge igi iresi pelu obe akoro ti a

npe ni donge ni iwon centimeter mewa si medoogun

(10-15cm) si ori ile. Di iresi ti o ti korejo loro, eyi a fun

iresi wa ni anfanni lati gbe daada ki ata gban kuro lara

igi iresi.

22

Page 24: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

IRESI GBIGBON ATI FIFE Gbon iresi re ni oiisa nipa lilu omo iresi kuro ni ara igi

iresi. Lehin eyi, fe iresi lati mu epo ati iresi ti ko ni omo

ninu kuro ninu iresi. Sa iresi ninu orun titi ti omi ti o rna

wa lara re yio fi mo niwonba bi iwon metala si merinla

ninu ogorun (13-14% moisture content).lresi ti a sese

kore ki saaba se fi pamo ti oju ojo ba gbona gan.

Rii wipe gbogbo awon idoti ti o wa ninu iresi ni a sa

kuro, eleyi ko ni je ki iresi sa deede ma gbona. A gbodo

sa iresi wa sorisa tabi ori eni ni diedie fun awon ojo

melo kan. Eleyi ko ni je ki iresi ma da kekeke tabi run

nigbati a ba nboo pelu ero (milling). Ma se sa iresi re si

ori ile lasan. Eleyi a dena okuta ati kanda inu iresi.

Kanda ati okuta a rna s'akoba fun ires! ti nwon ba we

nibe

IRESI BIBO PELU OMI GBIGBONA

Gbogbo iresi ti awon onimo ijinle ti fowo si ti a si ti

menuba ni omo won ma ngun daada. Nitori idi eyi,

gbogbo won ni o ye ki a bo ninu omi gbigbona. lresi

bibo ye ki a koko da si inu omi gbigbona. Eleyi wa

lowo irufe iresi ti a fe bo. Fun iresi ti at: nsoro re, bibo

re bere nipa ki a da sinu omi gbigbona (70°C). Eley! ti

o je wipe ti a ba towoboo fun iseju ago meji, ko ni pa

Page 25: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

wa lara. lru iresi (paadi) bee e yio wa ninu omi gbigbona

yi fun wakati marun si mefa. Wayi o, a o jeki iresi (paadi)

yi gba oru sara laarin iseju marun si mewa titi di igbati

eepo paadi yio fi ta jade. lru oru ti iresi paadi gba yi ni

rna nmu iresi ti o wa ninu paadi le daada. Osi rna nfa

awon afaralokun vitamin, thamine ati awon nkan eroja

miran si ara iresi.

lresi ti a ti bo rna nse fi pamo daada, o si tete ma njinna.

0 ni awon eroja kosemani. Kii run, ki si da kelekele

nigbati a ba boo lenu era. lresi se bo ninu ikoko tabi

gorodomu. eyi wa lowo bi iresi wa ba se po si

PIPA IRESI MO FUN OJO IWAJU

• lresi ti a ti bo pelu ero: Lehin igba ti a ti boo iresi,

ri wipe o sa iresi re daada ki o to fi pamo si ile iko

nkan pamo si. lresi ti a ti boo, ti a si fe ta dara lati fi

sinu apo ti o mo daada ninu ile- iko nkan pamo si,

titi di igba ti owo oja ori iresi a mu ere goboi wa

• lresi Paadi: lbi ti ko ba ti si aye lati bo iresi, ri wipe

iresi paadi re di gbigbe lo si oja ni kiakia lati yago

fun adanu ti o wa Iori kiko pamo.

24

Page 26: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

ERE (YIELD)

Ere ori iresi ki saaba ma npo pupa sugbon, aye si wa

lati jeki ere ori iresi po yanturu nip a ti tele awon ilana ti

o ba ode oni mu. A gbodo lo ajile ju ti atehinwa lo, a

gbodo ri wipe a se odiwon omi lila Iori oko. Ai to omi

fun ogbin iresi paapa julo nigbati o ba ndagba, tabi

nigbati o ba ngbomo ati nigbati o ba ntanna ma ndin

ere iresi ku pupo.

Ere ti o ma nwa Iori iresi akuro ati iresi elekun omi wa

laarin apo idoho mewa si adota apo idoho iresi paadi

Iori oko saare meji abo (1000 5000kg paddy/ha). Ni ti

iresi ori ile afojo gbin, ere rewa laarin apo idoho mewa

si ogbon apo idoho Iori oko saare meji abo (1 000

3000kg/ha).

25

Page 27: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

AWON KOKO ORO TO YE KA Fl SOKAN

Lati gbin iresi ti yio mu ere goboi wa, tele awon

ilana wonyi:

• Rll WIPE ILE Tl 0 DARA Nl 0 YAN LATI GBIN

IRESISI

• SE ITOJU OKO IRES! RE DARADARA

• BA TABI GBIN HORO IRESI IGBALODE Tl

AWON ONIMO IJINLE FOWO Sl

Rll WIPE 0 GBIN HORO IRES! NIWONBA Tl

AWON ONIMO IJINLE FOWOSI

• GBIN IRUGBIN IRES! RE Sl OJUBA FUN OKO

AKURO

• LO ODO IRES I RE LASIKO PELU ALAFO Tl 0

YE LATIIDI KAN Sl EKEJI

• FIAJILE Sl OKO IRES! GEGEBIAWON ONIMO

IJINLE SE FOWOSI

• PA EPO INU OKO IRES! RE LASIKO

26

Page 28: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

• DENAKOKOROATIARUN NINU OKO IRESI

• SE IKORE OKO IRESI RE NIGBATI 0 BA Rl

WIPE IRESI Tl GBO DAADA

• 80 IRESI RE, Kl 0 Sl BOO DAADA

• Rll WIPE 0 SA IRESI GBE LABE IBOJI Kl 0

TO GBE LO SIIDI ERO ABOYANGBO.

• KO IRES I PAMO SIINU APO Tl 0 MO DAADA

E ma gbin lresi fun anfaani ti o po repete

fun yin ati fun Orile ede wa

27

Page 29: lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. · lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) ajile oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan

-SPPONSORED BY:

PRESIDENTIAL INITWIVE ON INCREASED RICE PROOUCOON Federal Ministry of AgricuHure &. Rural Development, Abuja

PRODUCED BY: National AgricuHural Extension and Research Uabon Services

Ahmadu Bello UniversifV, Zaria Htderal Ministry of AgricuHure &. Rural Development, Abuja

DESIGNED AND PRINTED BY: NAERlS PRESS