2
Bawo ni mo se le mo nipa awon omiran oofa eto? Lo si ayelujara ile-ise awon oofa eto (www.bcps.org/ offices/omp) lati ri awn apejuwe eto, awon iwe-ise ati awn imo-eri. Omo ile-iwe ati awn ebi won tun le lo si awon apewo oofa ododun ati eto oofa lati ko eko nipa eto ti won se ni ile-iwe onikalukuluku. Imo-eri tun wa ti e ba baa won akeko ile- iwe soro abi ki e pe offiisi oofa ni 443-809-4127 APERE GBOLOHUN : Awon igbimo ti eto eko ti Baltimore County ko ni shei ase mase lori ojo- ori, awo, aigbadun, eya, orile-ede ati eya abinibi, iran, esin, isa-aye ibalopo, ologun tabi eyikeyi miiran ti o wa ninu iwe eto eko,awon ise ti won pese fun ninu ofin ipinle yi. Kini awon oofa ilana-Ipade? Awon BCPS oofa eto ni koko-oro curricula ati eto ipase ti ko wa ni nu okeere ile-iwe eto kan-kan. Won mu omo ile iwe eko ri ipase aseyori eko, ile eko to ya to, eto eko agbegbe ,ati eto eko lamoja. Awon eto oofa yi mu omo ile-eko lati ile- iwe deede koja aala ati ti wa ni wole ni pase a si aarin elo ati Agbani si ile-eko ilana. Ni pelu awon ebun iyi lati ja de Ile-iwe keji ati wo ile-iwe giga, awon omo ile-iwe keji ni nu oofa eto yi wa ni anfani lati dagbasoke ni nu awon nkan ti won ni ife si ati talenti jakejado specialized iwe ile-ise ati ijinle iriri. Awon ile-iwe igboro ilu Baltimore County ni eto oofa Ogoji ni ile-iwe arundinlogun kaakiri County. Awon oota yi ni eto alagbede, eto isiro, eto imon-ijinle ati imo sise ati iriran ona pelu eto ise-ori ati eto nipa imon-iro. Bi omo re ba ni ife si tabi talenti to jo mo ikan ninu awon eto oofa ti won ni ni awon ile-iwe igboro Baltimore County. Lo si www.bcps.org/offices/omp lati mo ni pa awon eto ati awn ohun elo ilana. Ile-ewe Baltimore Country to gba alejo eto oofa ile-ewe giga Office of Magnet Programs Baltimore County Public Schools 105 W. Chesapeake Avenue Towson, MD 21204

Bawo ni mo se le mo nipa awon omiran oofa Kini awon oofa ... · PDF fileOmo ile-iwe giga ninu awon eto oofa ma se oju-ise ninu awon eto ara tuntun pa pa ju lo ninu eko ayika. Pelu

Embed Size (px)

Citation preview

Page 1: Bawo ni mo se le mo nipa awon omiran oofa Kini awon oofa ... · PDF fileOmo ile-iwe giga ninu awon eto oofa ma se oju-ise ninu awon eto ara tuntun pa pa ju lo ninu eko ayika. Pelu

Bawo ni mo se le mo nipa awon omiran oofa

eto?

Lo si ayelujara ile-ise awon oofa eto

(www.bcps.org/ offices/omp) lati ri

awọn apejuwe eto, awon iwe-ise ati

awọn imo-eri.

Omo ile-iwe ati awọn ebi won tun le

lo si awon apewo oofa ododun ati

eto oofa lati ko eko nipa eto ti won

se ni ile-iwe onikalukuluku. Imo-eri

tun wa ti e ba baa won akeko ile-

iwe soro abi ki e pe offiisi oofa ni

443-809-4127

APERE GBOLOHUN : Awon igbimo ti eto eko ti Baltimore County ko ni shei ase mase lori ojo-

ori, awo, aigbadun, eya, orile-ede ati eya abinibi, iran, esin, isa-aye ibalopo, ologun tabi eyikeyi

miiran ti o wa ninu iwe eto eko,awon ise ti won pese fun ninu ofin ipinle yi.

Kini awon oofa ilana-Ipade?

Awon BCPS oofa eto ni koko-oro curricula ati eto ipase ti ko

wa ni nu okeere ile-iwe eto kan-kan. Won mu omo ile iwe

eko ri ipase aseyori eko, ile eko to ya to, eto eko agbegbe

,ati eto eko lamoja. Awon eto oofa yi mu omo ile-eko lati ile-

iwe deede koja aala ati ti wa ni wole ni pase a si aarin elo

ati Agbani si ile-eko ilana.

Ni pelu awon ebun iyi lati ja de Ile-iwe keji ati wo ile-iwe

giga, awon omo ile-iwe keji ni nu oofa eto yi wa ni anfani lati

dagbasoke ni nu awon nkan ti won ni ife si ati talenti

jakejado specialized iwe ile-ise ati ijinle iriri.

Awon ile-iwe igboro ilu Baltimore County ni eto oofa Ogoji ni

ile-iwe arundinlogun kaakiri County. Awon oota yi ni eto

alagbede, eto isiro, eto imon-ijinle ati imo sise ati iriran ona

pelu eto ise-ori ati eto nipa imon-iro.

Bi omo re ba ni ife si tabi talenti to jo mo ikan ninu awon

eto oofa ti won ni ni awon ile-iwe igboro Baltimore County.

Lo si www.bcps.org/offices/omp lati mo ni pa awon eto ati

awọn ohun elo ilana.

Ile-ewe Baltimore Country to gba alejo eto oofa ile-ewe giga

Off

ice

of

Ma

gn

et

Pro

gra

ms

Ba

ltim

ore

Co

un

ty P

ub

lic S

ch

oo

ls

10

5 W

. C

he

sa

pe

ak

e A

ve

nu

e

To

wso

n, M

D 2

12

04

Page 2: Bawo ni mo se le mo nipa awon omiran oofa Kini awon oofa ... · PDF fileOmo ile-iwe giga ninu awon eto oofa ma se oju-ise ninu awon eto ara tuntun pa pa ju lo ninu eko ayika. Pelu

Bawo ni mo shei le je ki omo mi wo eto oofa?

Bere ni Osuu Setemba, ibewe eto oofa fun odun ile-iwe to

bo ma wa ni offiisi awon e le eto oofa ati ayelujara won ni

(www.bcps.org/offices/omp). Awon obi le yan okan lati bere

fun ibewe ni ori ayelujara. Ibewe tite na wa ni gbogbo ile-

iwe BCPS arin ati giga ati awon isele eto oofa. Ibewe won

lati mun lo si Offiisi awon Eto Oofa ni ijo to pari to le je ipari

osuu Nofemba.

Ni osuu Januari, omo re you ni lati shei iwon iye lati loyeto

fun awon eto. Awon iwon iye yi le pelu idanwo, ifojukoju,

aroko itan tabi afenuka. Awon eto yi yoo pese ofin fun iwon

iye yi lati ran e lo wo lati mura

omo re fun awon iwon iye. Awon

eto mi le ni ki awon omo ile-iwe

shei idawole tabi nkan

orisirisi ki won to shei iwon

iye. Opolopo awon eto yi ni

Iroyin kaadi pelu ohun imọ to

wa po gbogbo ana ibewe wo

awon eto yi. Fun imo-eri pupo

nipa oofa iwon-iye fun ile-iwe

giga, e lo si offiisi oofa ayelujara

ni (www.bcps.org/offices/omp).

Ni Maasi, wa gbo ni pa bo ya won gba omo re si eto oofa

kan. Omo ile-iwe ti won ba gba si inu awon eto yi, won le fun

ni ijoko ninu eto oofa tabi ki won fi si ori iwe iduro ti o wa ni

aarin alaileto lotiri.

Bawo ni omo shei ma ni anfani to ba wa ninu

eto oofa?

Omo ile-iwe giga ninu awon eto oofa ma se oju-ise ninu

awon eto ara tuntun pa pa ju lo ninu eko ayika.

Pelu gbogbo iriri ile-iwe giga, awon omo ile-iwe yi yo ni aye

lati dagbasoke ati ko ogbon ninu nkan to ba ni ife si.

Awon omo ile-iwe ti won wa

ninu awon eto oofa yi ma

ni olomowe aseyori ati

ayeye ju awon ti won si

ninu eto oofa. Won tun ni

idagbaoke ara orunodun

21st to jo mo iwa, ogbon

lati ro inu jinle ati ore

orisirisi. Pelu awon eko kan

ri wipe awon ile-iwe ti won

gba alejo eto oofa ni ajumose

giga pelu awon obi ati awon ara ilu.

Nitori awon eto oofa to wa ninu awon ile-iwe BCPS ni asepo

pelu ara ilu ati awon ile-ise to be ni ilu, awon omo ile-iwe ni

anfani lati ku ro ni ile-eko giga pelu ara ati ogbon orisirisi,

iwe eri tabi iwe ise, iriri ise ati iyi ile-eko giga.

* Bi alayee soki ti awon igbimo Pataki ti eto eko so gbobgo yan pelu eda,

eya, eto-oro, irin-eran ati awon oni aigbadun.

Shei eyikeyi akeko le bere fun?

Eto oofa pese orisirisi eto-eko fun gbogbo awon omo ile-iwe

Baltimore County. Gbogbo omo ile-iwe to lo si awon ile-iwe

igboro Baltimore County le bere fun awon eto oofa to jo mo

nkan ti wan ni ife si tabi talenti won. Awon eto yi le ni awon

idiwo kan, opolopo eto wa fun awon omo ile-iwe ti won wa

ni ite esan (9). Opolopo eto tun wa fun awon omo ile-iwe to

lo si awon ite oke.

Ti omo mi ba ni aigbadun ko?

Awon omo ile-iwe ti won ni aigbadun ni ona lati se eto-eko

to ya to, apa 504 ati awon eto toju ojise ni owo ESOL ni

gbogbo eto oofa. Lati ran awon ebi lo wo bo ya oofa eto kan

bara mu fun omo re, tabi ki ni omo ma ba abi se ni nu awon

eto oofa yi, ba alakoso eto oofa ati ojogbon omo re soro

nipa awon nkan agbara ati eko ti omo re koseemani.

Bi omo re ba gba ibugbe idanwo ni ara akosile eto eko re,

wan pese awon ibugbe yi ko je ara eto oofa iwon iye. Fun

awo abewe ti won wa ni abi ti won lo si ile-iwe igboro ni ilu

Baltimore County, offiisi eto oofa yo baa won abewe yi lati

gba awon eto eko. Awon abewe ti won o lo si ile-iwe igboro

ni ilu Baltimore County lati mu iwe ibugbe idanwo wa pelu

ibewe eto oofa.

Shei igbekoja wa? O ye ki e wo bo ya Adugbo ibi ati igbekoya wa ki e to bere

fun awon eto oofa. Kaluku eto oofa ni ile-iwe giga ni adugbo

ti won ni igbekoja to da ati Ile-iwe igboro ni Baltimore county

ma pese igbekoya lati lo ati bo ni eto oofa ni awon ile-iwe

giga fun awon omo ile-iwe ti won gbe ni laarin awon adugbo

ti igbekoja wa.

Won pese igbekoya lati awon iwonkan ni adugbo* to su mo

awon ile-iwe giga kan. Awon obi ni o wa di di pese igbekoya

fun awon omo ile-iwe lati lo ati bo adugbo ti Igbekoya ma du

ro si.

(Jowo lo si www.bcps.org/offices/omp fun imo-eri pupo.)

*awon iwonkan ni adugbo yi ko bo si abe ofin ti o wa fun ibi ti awon oko

akero ma duro si, ni pa to ibi ti o jinna si ati irin na. Pelu re, ko si

alabojuto kan kan lati awon ile-iwe ni awon iwonkan ni adugbo won yi.

Ti ba ni ibere pupo nko?

Ti e ba fe imo-eri si, jo lo si ayelujara offiisi awon oofa eto

(www.bcps.org/ offices/omp) tabi ko pe ago wa ni (443)

809-4127.

Offiisi awon Eto Oofa

Baltimore County Public Schools

Jefferson Building

105 W. Chesapeake Avenue

Towson, MD 21204 Wo bi fun

imo-eri pupo

Scan Here for