Awon leta ti o wa fun awon Alhaji ati awon oni Umrah

 • View
  449

 • Download
  75

Embed Size (px)

Text of Awon leta ti o wa fun awon Alhaji ati awon oni Umrah

 • AWON LETA TI O WAFUN AWON ALHAJI ATI AWON ONI UMRA

  Lati owo

  DR. SHEIK YAHYA BIN IBRAHIM ALYAHYA

  Olutumo re si ede Yoruba ni:

  Abu Maalik N. Alimaam

 • Umrah ati awon oni AlhajiAwon leta ti o wa fun awon

  1

  NI ORUKO OLOHUN ALANU JULO OBA ONI IKE.

  Ope ni fun Olohun Oba gbogbo aye,mo njeri pe kosi eniti oye ki a josin fun ni toto ayafi oun, ore awon eni rere, mosi tun jeri wipe Anabi Muhamad eru Olohun ni ojise re si ni, asiwaju (ALGURRUL MUAJJALIIN) awon ti gbogbo orike ara won yo maa tan imole ni ojo Al qiyamo, O jise tiwon ran,osi pe adehun pelu,koda ose waasi ati ikilo fun ijore,o si fiwa sile lo lori imole gbo,ti oru re da bi osan re,enikankan kowa le sonu mo ayafi olori kunkun(eni iparun).ki Olohun se ike fun ati ara ile re pelu awon Sabe re lapapo,bakanaa ki ikeyi tun lo ba gbogbo eniti o ba pepe si oju ona re,ti o si ntele ilana re,titi di ojo esan,lehin naa:

 • Umrah ati awon oni AlhajiAwon leta ti o wa fun awon

  2

  Omo iyami Alhaji,iwo ti Olohun sa lesa lati wasi ile Olohun laarin ogunlogo awon musulumi,mo nbe Olohun ti o ga pe ki o duro ti o ni aye ati ni orun,ki o si se o ni alalubarika nibi yowu ti o bawa. Omo iya mi alaponle:se bi iwo naa ni o farada opolopo wahala,ati isoro pelu inawo ,ti o si tun fi ile ati ara ati omo sile, o se gbogbo eleyi titori ki o le se ise Haji Oranyan ni,mo wa nbe Olohun ki o se Haji re ni atewogba,ki o si se aforiji ese re,ki o si bo asiri asise re. Omo iyami Alhaji alaponle: ife ti moni si o,ati idunu mi si didere ni alaafia ni o mu mi ko awon leta yii si o,ati lati se die ninu ojuse mi si o,leyiti o je oranyan,bakanaa ni itele ase Olohun ti o sope:

  3/ ) ( (Won si ma nso asotele ododo ati suru sise) Al-asr /3. Mosi tun nfi eleyi ti mose yi tele ase Ololufe wa,asiwaju wa,awokose wa,Anobi wa

 • Umrah ati awon oni AlhajiAwon leta ti o wa fun awon

  3

  Muhammed- salalahu alaehi wassalam- nigbati o so wipe:

  (

  ). (Apejuwe awon Olugbagbo ododo ni ibi inife ara awon ati mi ma ke ara won,pelu aanu,won da gegebi ara kan ti orike kan ninu ara naa bati se aisan,gbogbo orike yoku naa yo si ma ba se aare ati aisun). O tun so wipe - salalahu alaehi wasalam - .

  ). ( (Mumini si Mumini da gegebi ile ti amo,ti apakan re diro mo apakan). Mo njeran ki iwo omo iyami Alhaji teti si awon leta omo iyare ti o ni ife re,ti o si ni aanu re loju, ki Olohun jeki o se o ni anfaani.

 • Umrah ati awon oni AlhajiAwon leta ti o wa fun awon

  4

  LETA KINNI Omo iyami Alhaji,mase gbagbe wipe tori oun ti o fi fi ilure sile ni ise Haji,ki o si lo mo amodaju wipe ise Haji yii ati gbogbo ise rere,kole je atewogba ti yoo fi ni awon mojemu meji yii ninu: Sise nitori Olohun nikan

  5/) ( (A ko pa won lase ju pe ki won njosin fun Olohun lo, ki won fo esin mo fun U) Albayyinah /5, ki o ba suna Ojise Olohun mu - salalahu alaehi wasalam - ,oun naa ni o sowipe :

  ) ( (Enikeni ti o base ise kan ti kosi ba ilana wa mu iru ise naa koni je atewogba). Kio ya riwipe gbogbo ero re nipe nje ise re je atewogba abi ko je atewogba?. Anobi - salalahu alaehi wasalam - ti so nipa ise Haji wipe :

  ) (

 • Umrah ati awon oni AlhajiAwon leta ti o wa fun awon

  5

  (E mu ise Haji yin lati odo mi).itumo re niwipe :e ko nipa bi mo sese Haji mi,ki eyin naa si se bee,kie mase se adadasile kankan nibe,ko wa si ona ti eniyan le gba se ise Haji yii ju ki o se gegebi o se wa lati odo Ojise Olohun lo,ki eniyan le baari ife Olohun ati aforijin re,Olohun ti o ga sope:

  ( .31: ...)

  (Wipe :Bi enyin ba je eniti o feran Olohun e tele mi, Olohun yio feran nyin, yio si fi ori awon ese nyin jin nyin).Aal-imran/31 O di owo ire omo iyami Alhaji alaponle lati ko nipa ise Haji,ki o si bi awon onimimo leere re,ki o to bere ise naa,nibayi,maa so die fun o nipa ise Haji ati Umrah,kiba dara ki o lo ka lekunrere nipare ninu tira miran.

 • Umrah ati awon oni AlhajiAwon leta ti o wa fun awon

  6

  BI ATI NSE UMRAH (1) - Ti o ba de (Miiqoot)- ibugbe arami- we iwe bi o ti ma nwe iwe janaba,fi lofinda si ara re, wo aso arami re;(iro ati idabora funfun),Obinrin yo wo oun ti o ba wu ninu aso,sugbon ki o mase je aso oso tabi aso bi aso Okunrin,da aniyan ki o si sowipe :(Labbaika Umrah)ti o ba jewipe ise umrah lo fe se,lehin naa ki o maa se (Labbaeka), (Labbaika Allaummo labbaika,labbaika laa sheriika laka labbaika, innal amda wanni'imotalaka wal mulka ,laa sherika laka). (Mo nje ipe re Olohun,mo nje ipe re,mo nje ipe re kosi si orogun fun o,mo nje ipe re,ope ati idera ati ola ti Ire ni,kosi orogun fun O.) Dida aniyan ni miiqoot je oranyan, ko leto ki eniti o fe se ise Haji tabi Umrah koja re laida aniyan. ( 2)- Ti o ba ti da aniyan, awon nkan wonyi ti di eewo fun o lati se :

 • Umrah ati awon oni AlhajiAwon leta ti o wa fun awon

  7

  * Mimu irun kuro ni ara, tabi rire ekana owo ati ese,Olohun ti o ga sowipe :

  ) ( /196.

  (Ki e ma si se fa(irun) ori yin titi ti ore na yio fi de aye re).Albaqorah/196 *Fifi lofinda si ara ati aso ati onje,bakanaa ko leto fun pe ki o wo nkankan ti lofinda yi,Ojise Olohun - Salalahu alaehi wasalam - sope :

  ). ( (E mase lo lofinda fun,e si mase bo ori re). *Ibalopo,eleyi ni o lagbara ju ninu awon nkan wonyi,toriwipe ti eniyan ba danwo ki o to se tawaaf Haji,Haji re ti baje patapata,o si je dandan fun ki o maa ba ise Haji naa lo,bakanaa oranyan ni fun ki o tun Haji naa se ni eemi (odun ti o tele e),atiwipe yo pa eran Rakumi kan fun itanran. Bakanaa o di eewo ki Okunrin fi ara po Obinrin niti igbadun,tabi pipan enu ara eni la.

 • Umrah ati awon oni AlhajiAwon leta ti o wa fun awon

  8

  Bakanaa ko gbodo fe iyawo,kosi gbodo fe fun eniyan,Ojise Olohun sowipe :

  ). ( (Oni ise Haji ati Umrah ko gbodo fe iyawo, won kosi gbodo fe fun,koda ko gbodo ba Obinrin soro fife). *Okunrin ko gbodo wo aso tiwon ran gegebi ewu,sokoto,awotele,bakanaa ko gbodo de fila,lawani,ate tabi akete,ati beebe lo. *Eewo ni fun okunrin ati Obinrin pe ki o pa eran ori igbe,koda ko gbodo ran eniti o fe pa lowo,tabi ki o lee si. *Obinrin ko gbodo bo oju re,beesini ko gbodo lo ibowo tori wipe Ojise Olohun - salalahu alaehi wasalam - sope :

  ) ( (Obinrin ti o bati gbe arami ko gbodo bo oju re [nigbati o ba dawa tabi o wa pelu oni eewo re] bee sini kogbodo lo ibowo). sugbon yo maa bo ojure nigbati o ba wa laarin awon Okunrin ti kiise eni eewo re.Aisha-ki Olohun yonu si i-sowipe :

 • Umrah ati awon oni AlhajiAwon leta ti o wa fun awon

  9

  (

  ). (Awon arin irin ajo ma ngba odo wa koja nigbati a ba wa pelu Ojise Olohun - Salalahu alaehi wasalam - ti won ba se deede wa, onikaluku wa yo si da iboju re ti o wa ni ori re- bo oju re, tiwon ba koja lo tan,ao si tun si pada). (3)- Ri wipe o nse labaika daada titi o fi de moka ti iwo yo si fi bere tawaaf kahba. Poyi ile Olohun ni eemeje ,ki o si maa bere ni ibi okuta dudu,(Ajarul aswad)ki o si maa pari re sibe bakana,lehin eleyi ki o kirun opa meji lehin maqaamo Ibrahim,ni tosi re ni tabi ibiti ojina si,sa tise eyiti o ba rorun fun o. (4)- Lehin irun opameji yi: Mura lati lo sa safa ati morwah ni eemeje,yo bere lati safa yo si pari re si moriwah,safa si moriwah ni alakoko,moriwah si safa ni elekeji,bayi ni ao maa ka titi yo fi pe meje ni moriwah.

 • Umrah ati awon oni AlhajiAwon leta ti o wa fun awon

  10

  (5)- Lehin eleyi fa irun ori re tabi ki o ge gbogbo re,sugbon fifa ni oni olaju,pelu eleyi ni ise umrah fi pari,osi ti di eto fun o lati bo aso arami,ki o si wo ewu ati sokoto re (6)- Ti o ba je wipe Haji nikan ni o fe se, (Ifraad) nigbati o ba de miiqoot sowipe: (LABBAIKA HAJAN),ki osi mase labaika lopolopo titi ofi ju oko ni (JAMARATUL AQOBAH) NI ojo odun,ti o ba de kabah,se tawaaf (qudum) lemeje,ti oba le sa safa ati morwah, ni igbayi oti dipo sisa Safa ati morwa Haji niyen sugbon o ko gbodo ge nkankan nibi irun ori re,ki iwo yo si wa ninu aso arami re titi di ojo odun. (7)- sugbon ti oba je wipe o fe se Haji pelu umrah ni (Qiraan) : nigbati o ba de meeqot iwo yo sowipe (Labbaika umrah wa hajjan), ki osi maase labbaeka daada titi ofi ju oko ni ojo odun,iwo naa yo si mase gegebi eniti o nse Haji nikan se nse.

  AWON ISE HAJI

 • Umrah ati awon oni AlhajiAwon leta ti o wa fun awon

  11

  (1)- Ni iyaleta ojo - kejo (Dhul-ijjah) osu kejila odun Hijrah,we iwe igbe arami,ki o si gbe arami re, sowipe (Labbaika Hajjan) ,ki o si maase gbolohun(Labbaika Allahumo.) daadaa titi iwo yio fi ju oko ni ojo odun,ao maase gbogbo nti aso yi ti o baje wipe eniti nse Haji pelu umrah (TAMATU'U)ni. (2)- Sugbon ti oba je Haji pelu umrah (QIRAAN) tabi Haji nikan soso(IFROOD) ni o nse,iwo koni bo aso arami re sile. (3)- Ni ojo yii losi mina,ki irun aila ati alasari ni opa mejimeji,ki irun mogribi ni opa meta ati ishai ni opa meji,bakanaa ki irun Asuba ni opa meji re,iwo yo maa ki awon irun yi ni asiko won ni. (4)- Ti orun bayo ni ojo Arafa ti se ojo kesan osu Dhul ijjah,lo si Arafa ki o si maase labbaika daada,ti obade Arafa tan,ki irun Aila ati Alasari papo ni asiko irun Aila,ni opa mejimeji,ao sipe irun lekan soso,sugbon iqoomo kookan ni owa fun iru

 • Umrah ati awon oni AlhajiAwon leta ti o wa fun awon

  12

  kookan,kio wa ni Arafa yi titi orun yo fi wo,kio si se adua ati iranti Olohun daadaa, pelu pe kio koju si Qiblah. Ri daju pe inu arafa ni owa,ki osi sora gidigidi lati kuro ni Arafa ki orun to wo. (5)- Ti orun ba wo tan daadaa,gbera kuro ni Arafa losi Muzdalifa ni pelepele,ati suru,ti o ba de ibe, ki irun Mogribi ati Ishai papo pelu irun pipe kan,ati iqoomot meji,ki Mogribi ni opa meta re,Ishai ni opa meji,ti o ba tun di asunba,ki