lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe

 • View
  0

 • Download
  0

Embed Size (px)

Text of lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI. lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo de ori awon ebe

 • • NAER\..S lLANA Tl 0 PEYE FUN

  OGBIN IRESI.

  Nl ORILE EDE NIGERIA

  RECOMMENDED PRACTICES NO. 5 (Yoruba Version)

 • lLANA Tl 0 PEYE

  FUN

  OGBIN IRE:SI

  Nl ORILE EDE N '~GERIJ'~

  EXTENSION RECOMMENDED PRACTICES NO.5 (Yorubet Version)

 • lLANA Tl 0 PEYE FUN OGBIN IRESI

  lresi gbigbin je ise ti o se pataki ni ile Nigeria nitori

  wiwulo iresi fun jije ati fun tita. Kosi ibikan ni ile Nigeria

  ti a ko ti le gbin iresi. Nitorina awon agbe ni lati mo

  ilana ti o peye fun iresi gbigbin.

  A won onimo ijinle ninu ise oko ti fi ilana ti o dara ti a le

  gba gbin iresi fun ikore yanture ati fun iresi ti o peye

  koda ti a le fi yang an Iarin iresi ti nti ilu okere wo ile wa

  lele. Nitori idi eyi, yio dara pupo bi awon agbe olugbin

  iresi ba ntele ilana inu iwe yi dada fun gbigbin iresi ati

  titoju lehin ti a ba ti kore re tan.

  ILE Tl 0 DARA FUN OGBIN IRESI

  Orisi ile ti o dara lati gbin iresi si :

  • lie akuro: lresi se gbin si eteti akuro tabi adagun

  omi. !ru ile bee gbodo le gba ami duro tabi ki omi

  wa nibe fun osu merin si marun. Ni awon agbegbe

  miran, ami le wa nibe ju osu marun lo.

  • lie akuro inu omi: lie akuro ti omi le dagun si fun

  osu mefa fun ogbin iresi.

  • A take ile ti o ni ora ati ami ojo fun bi osu meta si osu

  meje.

  2

 • IRUFE HORO IRESJ Tl 0 DARA LATI MA GBIN

  lie akuro:

  FARO 12: lresi Faro 12 se gbin si ile akuro ti ole gba

  omi duro fun osu merin si marun. lru iresi Faro 12 yi ni

  ale kore lehin osu merin abo.

  FARO 10: lresi Faro 10 dara lati gbin si ile akuro,

  nitoripe iresi yi lese dada ninu ile akuro ti omi re tutu.

  Eyi ni kan ko, iresi yi tun se gbin ni agbegbe ti o tutu bi

  Jos. lresi yi se kore lehin osu merin si osu marun.

  FARO 13: Faro 13 ni awon onimo ijinle fi owo si lati

  gbin si ile akuro gege bi Faro 12. Eyi si se gbin si ile ti

  a fa omi si lati je ki ile tutu tabi re gege bi oko iresi

  abomirin ti o wo po ni apa oke oya fun ogbin iresi lemeji

  ni odun kan. 0 se kore leyin osu merin abo si marun.

  Awon iresi ti a re tete kore ni Faro 27 ati 44. t i awon

  iresi ti yio pe ki a to le kore won je Faro 8, 12 ati 15.

  A won iresi ti o rna npe die ki a to kore won ni iresi Faro

  29,35,37,50,51 ati 52.

  Faro 15 ni awon onimo ijinle fowo si pe o se gbin si

  oko akuro ati oko ti a le fi omi won. lrufe iresi yi nilo ajile oniyo lati se dada. A si le kore re ni osu merin abo . si marun abo.

  ..,

  .)

 • Faro 16 ni awon animo ijinle fi owo si pe o se gbin si

  ibi ti ale gbin Faro 15 si. 0 rna nse kore lehin osu

  merin abo si osu marun abo.

  Faro 19 ni awon animo ijinle fi owo si pe o se gbin si

  oko akuro ati ile akuro atowoda ni apa Oke Oya. 0 rna

  nse kore lehin osu merin abo si osu marun.

  Faro 21 ni awon onimo ijinle fi owo si pe o se gbin si

  akuro ati ile ti a ti bomin rin (akuro atowoda} ti ale fi

  omi won irugbin won gegebi eyi ti o wa ni Niger,

  Kaduna,Zamfara ati Sokoto states ati awon ile ise to

  nri si idagbasoko ibomirin ise ogbin (River Basins)

  lagbegbe re. lrufe horo iresi yi nilo iwonba ajile oniyo o

  si rna ngbomo dada. Eyi ni kan ko, o tete rna ndagba,

  kii si se tabi da lule. 0 rna nse kore lehin osu meta si

  merin.

  Faro 24 dara lati gbin si akuro ati oko ti a ti bomirin

  tabi bomi won ni awon agbegbe gege bi Wurno ni ipinle

  Sokoto ati Yau lagbegbe Ngala ni ipinle Barno. 0 rna

  nse kore lehin osu merin abo si marun.

  Faro 26 dara lati gbin si ile ti a ti bomi rin ati ile akuro.

  Ale kore re lehin osu merin abo.

  4

 • Faro 27 dara lati gbin si ile akuro ati ile ti a ti fa omi si.

  Faro 27 ma ntete dagba, o si se kore lehin osu meta

  abo si merin.

  Faro 28 se gbin si ori ile ti o dara fun Faro 27. 0 si se

  kore lehin osu merin abo .

  Gbogbo awon irufe horo iresi ti a ti menu ba ni o je

  dandan lati gbin si oko akuro. Nigbati a ba ngbiyanju

  lati wa irugbin ti o dara fun ile akuro oni erofo. a gbodo

  gbe ojo ikore yewo lati ni idaniloju pe omi wa ni arowoto

  lakoko ogbin iresi yi.

  Faro 13, 15, 16, 17, 26, 28, 44, 47, 48, 49, 50, 51 ati

  52 je iresi igbalode ti o peye ju awon ta ti mo tele lo.

  Awon eya irufe Faro wonyi yato si awon eya iresi

  abafaiye ti o ti wa tipe ,ti o je wipe won ma nga, ti won

  si ma nda lule.

  lrugbin iresi ti o dara fun akuro oni erofo:

  Faro 4 dara lati gbin si oko akuro inu erofo pelu ojo ti

  nro fun osu marun si meje. lresi Faro 41e farada om.i to

  jin to ese bata meta si mefa. 0 se kore lehin osu mefa

  si meje abo.

  5

 • Awon eya iresi ti o tun dara fun akuro inu erofo gegebi

  Faro 4 ni Faro 7, 14 ati 15.

  lrugbin iresi ti o dara fun agbegbe ekun omi:

  Faro 6: lrugbin yi ni ale dape gegebi iresi ti o nlefo

  loju omi. Faro 6 ni awon onimo ijinle fowo si pe o se

  gbin si agbegbe ti ekun omi saba ma nwa. lru ekun

  omi bee le jin to ese bata meta abo .. Faro 6 manse

  dada ninu iru ekun omi bayi, papa julo ni agbegbe bi

  atonutoji Rima (River valley) ati ni Birni Kebbi ni ipinle

  Sokoto ati Kebbi. 0 se kore ni osu meta si meta abo.

  Faro 7: I rug bin yi nse dada ni ibikibi ti Faro 6 ba ti se gbin. Sugbon o ma ngbomo ju Faro 61o. A won animo

  ijinle ti fowosi gbigbin re. 0 se kore lehin Osu marun si

  meje.

  Faro 4: Gegebi Faro 7, Faro 4 se gbin bakanna. 0 si

  tun se kore lehin osu marun abo si osu meje.

  lrugbin iresi to dara fun ori ile papa (atake):

  Faro 1: Faro 1 manse dada pelu ojo ti o nro dede ni

  agbegbe Oke Oya ni ile Nigeria. Osi tun ma ntete

  dagba. Awon irugbin ti o dabi Faro 1 ni Faro 40, 45,

  54 ati 55. 6

 • Faro 48, 49 ati S3 ma npe die bi o tile je pe awon na ma nse dada lagbegbe Oke Oya ti ojo ti ma nro dede.

  Awon onirno ijinle fowo si pe awon irufe iresi t i a ti

  menuba wonyi se fi ropo Faro 3. Osu merin si marun

  ni a lese ikore iresi yi.

  Faro 25: Gege bi Faro 11, irufe iresi yi le farada arun

  ewe alawo ile (brown spot disease) ti o ma nda iresi

  afojo dagba (upland rice) lamu. 0 si ma nse bo dada

  pelu ero. lrufe iresi bi eleyi ma ndagba fun ikore lehin

  osu meta abo si merino le die.

  Awon ibi ti a ti le ri irugbin iresllgbalode

  E kan si a won ile ise wonyi fun irugbin iresi ti o dara:

  a) Akowe agbe ni agbegbe re (Extension Agent)

  b) lie ise idagbasoke ise ogbin (ADP) ti o wa

  lagbegbe re.

  c) lie ise ogbin ti o nri si idagbasoke ati ibomirin

  (River Basins Authority) lag beg be re.

  d) Eka ile ise National Seeds Service ti o wa

  lagbegbe re

  e) lie ise ti ijoba fowo si lati rna ta irugbin iresi

  (Seed companies)

  7

 • ITOJU ILE FUN OGBIN IRES!

  Fun iresi akuro: Pese ojuba pelu ebe ti o te rere

  kekere (nursery beds)ninu osu karun si ikefa. Eleyi wa

  lowo bi ojo ba se nro dada si. Ti o ba nlo akuro

  alabomirin (irrigation) nibi ti omi wa fun iresi ninu osu

  karun, pese ebe re (nursery beds) ninu osu kerin odun.

  A won ebe ti o te rere kekere ti a ti pese gbodo ga ju ori

  ile lo. Awon poro (alafo) ti o wa ni aarin awon ebe wonyi

  gbodo kun fun omi. Ori awon ebe wonyi gbodo se

  lubulubu. Ekun omi to wa ni poro awon ebe ko gbodo

  de ori awon ebe yi. Fi iwon agolo miliki (113.5g) aj ile

  oniyo (CAN) ati iwon tomati agolo kan (42.6g) ajile

  onihoro (super phosphate) ti a ti popo si iwon mita meta

  Iori ebe ti a ti pese sile. Rii wipe o po ajile yi mo ile ni

  kete ti o ti fi sii, ki o to dipe o gbin iresi si ori ebe fun

  biba.

  Osuwon iresi ti a gbodo gbin

  Fun Akuro: Lo iwon horo iresi kongo mewa si metala

  (Swamp Ricce) (40-50kg) fun saare oko meji abo (1

  hectare)

  Fun akuro inu omi: (Floating rice) Lo iwon kongo

  medogbon (1 OOkg) horo iresi fun saare oko meji abo

  (1 hectare). Sora lati gbin opo omo iresi re soju kanna. 8

 • Eieyi yo dena a run Kokoro ti a n pe ni pyncuieria rna nfa.

  Fun ogbin ori ile Atake/papa (Upland): Lo iwon

  kongo metala si medogun horo iresi lati gbin saare

  meji abo (1 hectare. Ti o ba je pe o fe fon horo iresi

  sari oko, lo iwon ogun kongo si kongo medogbon horo

  iresi lati gbin oko saare meji abo (1 hectare).

  Asiko ogbin iresi (Time of Planting)

  Fun Akuro: - Gbin horo iresi re ni osu karun odun, o

  pe ju ni ibere osu kefa. Eleyi wa lowo bi omi ba se wa

  larowoto sii. Tu awon odo iresi re lo ni ipari osu kefa

  lehin igbati odo iresi re bati to ose meji si ose merin.

  Rii wipe awon omo iresi toga daada lo tu fun lilo.

  Fun akuro inu omi- Nibiti o ba ti seese, gbin iresi si

  oju iba ti a ti pese sile. Tu odo iresi re lo ni kete ti omi

  bati wa Iori oko. Ti ojuba (nursery) ko base pese, fon

  horo iresi re sori oko ni iwon kongo merinla fun saare

  oko meji abo. Se itoju ile re nigbati ojo akoko ba ti ro.

  Eeleyi yio fun o ni anfani lati den