2
“A kò gbọdọ lo ẹsìnláti fa ìyapa, láti fi ìyà jẹni, tàbiláti lo àǹfàní tí kò tọ” 4 th January, 2015 “Orílẹ-èdè Nàìjíríà tí a ni lọkàn jẹ èyí tí gbogbowa á le jọjòkó ƴọayọ ìdùnnú, kí á dì jọdúpẹ lọwọ Olọrunpapọ. Bí ó ti yẹ kí ó rí nìyẹn” 4 th January, 2015 “Ojúṣe ìjọba ni láti pèsè ààbò àti ìfọkàn balẹ fún gbogboọmọ Nàìjíríà láìfi ti ẹsìn, ẹyà àti èdè ṣe. Ohùn tí a gbọdọ pawọpọ ṣe ni, ní pàtàkì jùlọ ní ọjọ òní tí à ń ṣe ìdúpẹ” 4 th January, 2015 “Ìgbàgbọ mi láti ìbèrè ayé mí ni wípé gbogbo ọmọ orílẹ-èdè Nàìjíríà gbọgbọ ní òmìnira ẹsìn láti sin Ọlọrun gẹgẹ bí ìgbàgbọ wọn” 4 th January, 2015 “Ojúṣe ìjọba kìí ṣe ti ẹsìn” 4 th January, 2015. Buhari Nípa Èsìn www.actnow.ng “Inú mi dùn láti ríi wí pé ìsìn ìdúpẹ ọlọdọọdún yìí, bí ó tilẹ jẹ pé ìsìn ẹsìn Kírísítéẹnì ni, síbẹ o kó gbogbo ẹlẹsìn papọ. Kírísítẹnì, Mùsùlùmí àti gbogbo ẹsìn tí ó kù ni wọn ń darapọ níbí lọdọọdún láti dúpẹ lọwọ Ọlọrun. Bí ó ṣe yẹ kí ó rí nìyí” 4th January, 2015. Kín Ni Èrò Bùhárí Nípa Ѐsìn? “Àwòrán fọnrán tí wọn fi sórí ẹrọ agbọrọkáyé fi wọn hàn gẹgẹ bíi elérò kúkúrú. Ó fi irú ènìyàn tí wọn jẹ hàn; irú wọn kò le ṣẹrù bàwá tàbí dúnkokò mọ òmìnira wa . Ọrọ ẹnu wọn ti fi hàn gbangba wí pé wọn kìí ṣe ènìyàn Ọlọrun. Wọn kò ní èrò rere fún ọrílẹ-èdè wa àti àwa ènìyàn ibẹ. Mùsùlùmí ni mi. Mo ní ìmọ ẹsìn kírísítẹnì mo sì mọ wí pé ẹsìn méjéèjì ń wá àgbéjọpọ àlàáfíà fún ọmọ ènìyàn” Vanguard; 8th May, 2014.

BUHARI ON RELIGION -- YORUBA

Embed Size (px)

Citation preview

Page 1: BUHARI ON RELIGION -- YORUBA

“A kò gbọdọ lo ẹsìnláti fa ìyapa, láti fi ìyà jẹni, tàbiláti lo àǹfàní tí kò tọ” 4th January, 2015

“Orílẹ-èdè Nàìjíríà tí a ni lọkàn jẹ èyí tí gbogbowa á le jọjòkó ƴọayọ ìdùnnú, kí á dì jọdúpẹ lọwọ Olọrunpapọ. Bí ó ti yẹ kí ó rí nìyẹn” 4th January, 2015

“Ojúṣe ìjọba ni láti pèsè ààbò àti ìfọkàn balẹ fún gbogboọmọ Nàìjíríà láìfi ti ẹsìn, ẹyà àti èdè ṣe. Ohùn tí a gbọdọ pawọpọ ṣe ni, ní pàtàkì jùlọ ní ọjọ òní tí à ń ṣe ìdúpẹ” 4th January, 2015

“Ìgbàgbọ mi láti ìbèrè ayé mí ni wípégbogbo ọmọ orílẹ-èdè Nàìjíríà gbọgbọ ní òmìnira ẹsìn láti sin Ọlọrun gẹgẹ bí ìgbàgbọ wọn” 4th January, 2015

“Ojúṣe ìjọba kìí ṣe ti ẹsìn”4th January, 2015. Buhari

Nípa Èsìnwww.actnow.ng

“Inú mi dùn láti ríi wí pé ìsìn ìdúpẹ ọlọdọọdún yìí, bí ó tilẹ jẹ pé ìsìn ẹsìn Kírísítéẹnì ni, síbẹ o kó gbogbo ẹlẹsìn papọ. Kírísítẹnì, Mùsùlùmí àti gbogbo ẹsìn tí ó kù ni wọn ń darapọ níbí lọdọọdúnláti dúpẹ lọwọ Ọlọrun. Bí ó ṣe yẹ kí ó rí nìyí” 4th January, 2015.

Kín Ni Èrò Bùhárí Nípa Ѐsìn?

“Àwòrán fọnrán tí wọn fi sórí ẹrọ agbọrọkáyé fi wọn hàn gẹgẹ bíi elérò kúkúrú. Ó fi irú ènìyàn tí wọn jẹ hàn; irú wọn kò le ṣẹrù bàwá tàbí dúnkokò mọ òmìnira wa . Ọrọ ẹnu wọn ti fi hàn gbangba wí pé wọn kìí ṣe ènìyàn Ọlọrun. Wọn kò ní èrò rere fún ọrílẹ-èdè wa àti àwa ènìyàn ibẹ. Mùsùlùmí ni mi. Mo ní ìmọ ẹsìn kírísítẹnì mo sì mọ wí pé ẹsìn méjéèjì ń wá àgbéjọpọ àlàáfíà fún ọmọ ènìyàn” Vanguard; 8th May, 2014.

Page 2: BUHARI ON RELIGION -- YORUBA

Ǹjẹ Alákatakítí Ẹsìn Mùsùlùmí Tí Ó Fẹ SọOrílẹ-èdè Nàìjíríà Di Ẹlẹsìn Mùsùlùmí niBuhari?Ní nǹkan bíi ọdún márùn-ún sẹyìn ni wọn bẹrẹ sí ní fi ẹsùn kan Ọgágun Muhammadu Buhari wí pé alákatakítí ẹsìn Mùsùlùmí ni àti wí pé ó fẹ sọorílẹ-èdè yìí di ti ẹlẹsìnMùsùlùmí. Ẹ jẹ kí á wo àwọn òtítọ tí ó fi ojú hàn:

Òtítọ Ibẹ• Bùhárí kò fi ìgbà kan sọ wí pé òun á mú ìṣèjọba nira fún ìjọba ilẹ Nàìjíríà.• Ọkan nínú àwọn Olóyè Ẹgbẹ PDP Alhaji Lawal Kaita ló sọ wí pé ìsàkóṣo ìjọba ilẹ Nàìjíríà á nira látiṣe lẹyìn ìdìbò ọdún 2011.• Irọ ni Rueben Àbàtì tí ó jẹ amúgbálẹgbẹẹ Ààrẹ lórí ètò Ìròyìn pa wí pé Bùhárí ló sọbẹẹ.

Kín Ni Bùhárí Ṣe Nípa Irọ Àbàtì Yìí?• Bùhárí pe Àbàtì àti ìwé Ìròyìn Guardian (tí ó tẹìròyìnnáà jáde) ní ẹjọ ìbanilórukọjẹ sí ilé ẹjọ gíga (ṅumber ẹjọ yẹn ni ID837/2011).• Bùhárí gbà láti gbé ẹjọ kúrò nílé ẹjọ nítorí pé Jonathan bẹ Bùhárí. • Ní ọjọ Kọkànlá Oṣù Keje ọdún 2013 (11-7-2013) ìwe] ìròyìn Guardian tẹ àtẹjáde níbití Àbàtì tigbà wí pé irọ niòun pa mọ Bùhárí, ó sì tọrọ àforíjì.

Ǹjẹ Bùhárí kórìíra àwọn ẹlẹsìn mìíràn?

• Nígbà tí ó jẹ olórí orílẹ-èdè yìí, mọkànlá (11) nínú àwọn Gómìnà mọkàndínlógún (19) tí ó yàn sí ipò Gómìnà, ẹlẹsìn Kírísítẹẹnì niwọn. Púpọ nínú àwọn tọ ń bá Bùhárí siṣẹ àti àwọn òsìṣẹ inú ilé rẹ, kírísítẹẹnì niwọn.• Bùhárí nígbàgbọ wí pé kò yẹkí orílẹ-èdè Nàìjíríà fi aramọ ẹsìn kan ṣoṣo, dípò bẹẹ, kí á fi ààyè gba olúkálukú láti ṣe ẹsìntí ó bá fẹ. Torí ìdí èyí ló ṣe kọ láti jẹ kí Orílẹ-èdè Nàìjíríà darapọ mọ ẹgbẹ Orílẹ-èdè Ẹsìn Mùsùlùmí Agbaiyé (OIC).

Bùhárí kò kórìíra àwọn tí kìí ṣe ẹlẹsìn Mùsùlùmí!Olórí tí ó fi ọkàn sin ọrílẹ-èdè Nàìjíríà ni. Ó kó ènìyànmọra, ó sì tisiṣẹ pọ pẹlú ọpọlọpọ ọmọ Nàìjíríà láìfi ti ẹsìn tàbí ẹyà ṣe. Àwọn olórí méjì tí ó súnmọ Bùhárí dáadáa ni Ọgágun Yàkúbù Gowon àti TheophilusDanjuma GCON. Ẹlẹsìn Kírísítẹnì ni àwọn méjéèji, wọnsì wà láyé, ẹnití ó bá fẹ mọ òtítọ bóyá alákatakítí ẹsìnMùsùlùmí n iBùhárí tàbí bẹẹ kọ, kí ó lọbí wọn.

Kín Ni Bùhárí Sọ Nípa Boko Haram?“Ìwà ìkà nikí á máa fi àdó olóró pa ènìyàn nígbogbo ìgbà. Ó burú jáì láti huirú ìwà yìí lọjọọdún Kérésì, gbogbo ẹni tó bá nífẹẹ àlàáfíà lóyẹkí ó bu ẹnuàtẹ lu iwà ìkà yìí, kí wọnsì bèèrèfún wíwá àwọn ọdaràn wọnyí kànláti fi wọn jófin” Ìwé Ìròyìn This Day Life; 26th December, 2012.

“N kò mọ ọmọ ẹgbẹ Boko Haram Kankan. N kò gbàgbọ nínú ìpànìyàn, n kò sì mọ ẹsìn Kankan tí á lọ pa ènìyàn, sun ilé-ẹkọníná” Punch 8th November, 2012

Kínṅi Ó Yẹ Kí O jẹ Ojúṣe Àwọn Olórí Ẹsìn?SỌ ÒTÍTỌ!!!

“ahọn gbogbo àwọn wòlíì orílẹ-èdè yìí gbọdọ tú, gbogbo àwọn ẹnu tí a ti padé gbọdọ là, bí wọn bá ti pa ọ lẹnumọ, pọ ohun tí wọn fi dí ọ lẹnu kí o sọrọ nítorí ọjọ iwájú àwọn ọmọ wa - - Bí jíjẹ olórí bàbá mi bá máa mú ìparun bá àwọmọmọ, jẹ kí àjòjì kúkú ṣe olórí kí ìran wasì wà”

“Bí baba bá ń jẹ àjẹyó, tí ebi sì ń pa àwọn ọmọ, ǹjẹ irú ẹni bẹẹ yẹní gégé baba bi?”RevF.R. Ejike Mbaka 31st December, 2014

“Àwọn Olùsọ Àgùtànkan ń jẹ àṣáró Jákọbù, wọn sì ń ta àsọtẹlẹ wòlíì: wọn ń fi ìfàmìòróró yàn se òwò ní Aso Rock --- àwọnkanń gbé owó ilẹ wa, wọn ń sọ ọ di owó Dọlà nínú ọkọ òfurufú aládàáni, wọn ń gbé e jáde lọkùrò lórílẹ-èdè” Rev F.R. EjikeMbaka 31st December, 2014