28
Ebó rirú 1º Se escribe en el centro del tablero el ódu por el cual se va a realizar el ebó, a la derecha se escribe el ódu Ojuani Shobe y a la izquierda el ódu Oshe Tura. 2º Se coloca sobre el tablero los granos de maíz, el opele y el dinero del derecho del ebó. 3º Se mojugba. 4º Se coloca el opele en la parte superior de tablero con el siguiente súyere: Àgònrín ìgbòrò kó yólè é tè Kó má baà deran igún Kó má baà deran Àjé Kó má baà deran Ìyà mi Díá fún Àjàgbé Ti won mú re igbòdù ló tè ní´fá Bàbáláwo kìí wó rùkú ògbèrì Ògbèrì kìí wó igbòdù láì tè ní´fá Ifá ló wá di Òbìrí Mo ló wá di ewéàpadase Oferegége Àjàgbé á dide ò Oferegége Bí ewúre bí´mo lóòjó adìde Oferegége Àjàgbé á dìde ò Oferegége Bí àgùntàn bí’ mo lóòjó a dìde Oferegége Àjàgbé á dìde ò Oferegége Bí ádìe òkòkó bí‘mo lóòjó a dìde Oferegége Àjàgbé à dìde ò Ofèregége Bí ikú n bò Jókòó tèé Bí òfò n´bò Jókòó tèé

EBBO RIRU.docx

Embed Size (px)

Citation preview

Page 1: EBBO RIRU.docx

Ebó rirú

1º Se escribe en el centro del tablero el ódu por el cual se va arealizar el ebó, a laderecha se escribe el ódu Ojuani Shobe y a la izquierda el ódu Oshe Tura.

2º Se coloca sobre el tablero los granos de maíz, el opele y el dinerodel derechodel ebó.

3º Se mojugba.

4º Se coloca el opele en la parte superior de tablero con el siguiente súyere:Àgònrín ìgbòrò kó yólè é tèKó má baà deran igúnKó má baà deran ÀjéKó má baà deran Ìyà miDíá fún ÀjàgbéTi won mú re igbòdù ló tè ní´fáBàbáláwo kìí wó rùkú ògbèrìÒgbèrì kìí wó igbòdù láì tè ní´fáIfá ló wá di ÒbìríMo ló wá di ewéàpadaseOferegégeÀjàgbé á dide òOferegégeBí ewúre bí´mo lóòjó adìdeOferegégeÀjàgbé á dìde òOferegégeBí àgùntàn bí’ mo lóòjó a dìdeOferegégeÀjàgbé á dìde òOferegégeBí ádìe òkòkó bí‘mo lóòjó a dìdeOferegégeÀjàgbé à dìde òOfèregégeBí ikú n bòJókòó tèéBí òfò n´bòJókòó tèéNíjó Ajé ríbò nílé eléboNíjó Aya ríbò nílè eléboNíjó omo ríbó nílé eléboNíjó ire gbogbo n´bò nìlé elèboKi gbé ìdí kí jé kí ó tó owó eléboBí àrùn n´bóJókòó tèé1

5º Se reza un verso del odu Okana Sá para bendecir las manos que haránel ebó. El

Page 2: EBBO RIRU.docx

verso es el siguiente:Òtún pèlé (se coloca la mano derecha sobre el tablero), Awo won ódde ÀbáDíá fún won lode ÀbáEkún Ajé. Ekún aya. Ekún ire gbogbo ni wón n sunWón gbébo, wonrúboKò pé kò jìnnàIre gbogbo wá ya dé tùtúruÒsì pèlè (se coloca la mano izquierda sobre el tablero), Awo won òde ÀboseDíá fún won lóde ÀboseEkún ire gbogbo ni wón n’sunEbo ni wón ní kí wón wá seWón gbébo. Wón rúboKò pé kò jìnnàIre gbogbo wá ya dé tùtúruÀtòtún. Àt‘Òsì kìì sebo àìfìnÀtòtú ni wón dífá fúnOmo okùnrín dèpènùÒ di dèpènù, dèpènùÀ bá dègún, dèpè I‘ Àwo lóriKò lè jà láíláíÀséwélé o dé ò. Omokùnrin dèpènù.

6º Se mueve el dinero y los granos de maíz mientras se reza el versodel odu Okana Sapara que el cliente logre el propósito por le cual hace el ebó:Orí Adé níí se OpónÀwon Òdèlè níí rin ìhòhò sosin, soràÌdànndàn níí fi ara rè se afárá OlúkoyinDíá fún Akówó-raríIfa somo ÀjàníwàrunAkówó-rarí kìí kúEyan tó kówó raríElédàá rè báa tál

7º Terminado de rezar se frota el dinero en la frente y el pecho delcliente y se coloca eldinero debajo del tablero de Ifá.

8º El siguiente verso a recitar sera del odu Ogbe Dí para asegurar queel ebó seráaceptado y protege al cliente de todos los males:Gbàmí igbó lawo gbàmí igbóGbàmí òdàn lawo gbàmí òdànGbàmí hènhen níí sawo gbàmí hénhenIfá ti o bá yò mí ní ibi tó dí gágáágáBí mo bá dé ibi tósunwónMàá san oore è re fún o2Díá fún ÒrúnmìláIfa ó yo omo rè nínú irunbiOwó ò mi wá ba ewè olóbòyòboyo tèmiÒkòsòkòsòNifá ó yo‘mo tè kúròú ibi

Page 3: EBBO RIRU.docx

Òkòsòkòsò

9º Se vuelve a pasar los granos de maíz por la frente y el pecho.10º Este verso que hay a continuación se rezara entre verso y verso decada odu, paraindicar el final de un signo y el comienzo de otro signo, y se usapara llamar a Ifá paraque acepte el ebó. Mientras se reza el verso se tocará la frente y elpecho con el maíz.Ifá mo ní kóo gbèrù kébo finIfá mo ní kóo gbèrù kèbo ò dàIfá mo ní kóo gbèrù kèbo dé àlàde ÒrunWón níònà wo lo gbà tóo fi njé béè

Mo béè náà lòó jé Ifá11º Después de esto se reza un verso del odu Otura Ka:Bíebi bá n´pa inúÀkàsù bànbà làá fìí beéDíá fún TèyìngbìwàTi yóó san‘wó ìpín mo ní ìsinmiTèyìngbìwàMo san‘wó ìpín lórunTèyìngbìwà

12º Otro verso del odu Otura Ka:Òkín ningín-ningín Awo OlókunDíá fún OlókunNíjó omi òkun ò tóóbù bójúÀlùkò dòdòòdò Awo OlósáDíá fún OlósáNíjó omi Òsà ò tóóbù sin‘sèOdíderé abìrìn esè kerewè-kerewèDíá fún Olú-Ìwó ‘Modù ObàOmo atòrun là, gbégbá aje karí wáyéÓ túkà, ò dà káErigí lawo ÀgbasàDíá fún won Isèse- ÀgéréNíjó ti wòn kó ohun ebo sílèTi wón nwá Bàbáláwo ó loroA ró ‘hun ebo lónìí, a ró ‘hun eboErigí lawo ÀgbasàIfá a rórun ebo3Èko tó nbe nílè yìí nkóOhun ebo níí seErigí lawo ÀgbasàIfá a róhun eboEpo tó nbe nílè yìí nkóOhun ebo níí seErìgì lawo ÀgbasàIfá ríhun eboOti tí nbe nílè yìí nkóIfá a ríhun ebo

Page 4: EBBO RIRU.docx

Ohun ebo níí seErìgì lawo ÀgbasòIfá ríhun eboÈyelè ti nbe nílè yìí nkóOhun ebo níí nseÈrìgì lawo ÀgbasàIfá a ríhun eboÈtù ti nbe nílè yìí nkóÈrìgì lawo ÀgbasàIfá a ríhun eboÀkùko ti nbe nílè yìí nkóOhun ebo níí nseÈrìgì lawo ÀgbasàIfá a ríhun eboObi àti Orógbó ti nbe nílè yìí nkóOhun ebo níí nseÈrìgì lawo ÀgbasàIfá a ríhun eboA ríhun eboK‘ebo náà ó finÈrìgì lawo ÀgbasàIfá a ríhun eboEgungun Akódà, egungun èdìdààréÈrìgì lawo ÀgbasàIfá a ríhun eboBólótíbá pon otí tánÈdìdà a dàáÈrìgì lawo ÀgbasàIfá a ríhun eboDàá-dàá níís‘ adie àbaÈrìgì lawo ÀgbasàIfá a ríhun eboDànìdànì lasiwèrè ´n rìnÈrìgì lawo ÀgbasàIfá a ríhun eboEni bá pé kébo má dà4Kàsàì màa b‘èbo lo oÈrìgì lawo ÀgbasàIfá a ríhun ebo

13º Se reza un verso del odu Ojuani Alawana donde Ifá alaba las virtudes deltradicionalismo:Òkun kùn nàre-nàreÒsà kún lèngbe-lèngbeAlazán n‘re asánAlazán n‘re asán Awó Orí OtaÀwon àgbààgbà wo èyìn òròWón ri wípé kò sunwòn móWón fi irun imú dijúWón fi irùngbòn díjà pen-pen-penDíá fún ÌsèseTìì se olórí Orò n‘Ìfe

Page 5: EBBO RIRU.docx

Njé kínni Ìsèse eniÒlódùmarè ni Ìsèse eniÌsèse là bà boKàí tèní b‘ÒrìsàÌyà eni ni Ìsèse eniÌsèse là bà boKàí tèní b‘ÒrìsàBàbá eni ni Ìsèse eniÌsèse là bà boKàí tèní b‘ÒrìsàOkò eni ni Ìsèse eniÌsèse là bà boKàí tèní b‘ÒrìsàÒbò eni ni Ìsèse eniÌsèse là bà boKàí tèní b‘ÒrìsàE jè ká bo Ìsèse ò, OlówóÌsèse là bà boKàí tèní b‘ÒrìsàÌsèse ni bàbà ètùtùÌsèse là bà boKàí tèní b‘ÒrìsàÌsèse ilé ÌyáÌsèse ilé bàbáGbogbo won yóó wá láse sí ebo yìíÌsèse là bà boKàí tèní b‘Òrìsà5

14º Se reza un verso del odu Okana Sa donde se llama a los ancestros ya los Orisaspara que den su aprobación al ebó que se está haciendo:Àtorí bóso Awo EgúngúnDíá fún EgúngúnEgúngún n‘shawo ò loóde ÒjéKí Egúngún ilé yìí lówó sí ebo yìíÒkan nànààpòn Awo OròDíá fún OròOrò n‘sawo lò sòde ÌgbèhínKí Orò ilé yìí ó láse sí ebo yìíÀkànmólè e pèrèkùn Awo Òòsànlá ÒsèèrèmàgbòDíá fún Òòsàlá ÒsèèrèmàgbòTí nrayé ìlaìnííkúTí nrayé ogbó o tíen-réreÒòsàlá ìwo lò dá ojúÌwo lòó dá imúKí o jé kí èmí elébo yìí ó gùn gbéreBí a bá wí ti Olórò tánE jé ká wí tara eniDíá fún Elénpe Àgarawú

15º Se reza un verso del odu Ogunda Masa para que le cliente tengaéxito en la vida y

Page 6: EBBO RIRU.docx

las cosas que haga sean exitosas:Òpè ìháhá nìì sowó alàkedun tirimómó-tirimómóDíá fún ÒnbèTí yoo maa be Ipin onípìn-ìn káàkiriOrí Awo ó bèÀbégbó mà ni oIpín Awo ó béAbeto mà ni o

16º A continuación se reza un verso del odu Okana Sa para que todoslos awo que estenpresentes en el ebó pongan su ayuda, esto es poniendo la mano izquierda sobre eltablero cuando se termina de rezar el odu:Àsá ò lápáÒfenu s‘oróÀwòdì ò lápáÓfesè jalèDíá fún ohun Awo fowo bàTíí di eboEbo kóó fín oÀsànì àjà6

17º Hecho esto se reza un verso del odu Okana Sa donde ya se da porseguro que el ebóha sido aceptado:Jòó nìdí ìbonAjòlèlè majò lòfàAkíyangbà ni wón sefá fúnTíí somo elérùnpéÈyì tó to nseboBèé ni ò finÈyí tó to nse ètùtùBèé ni ò gbàÈyí tó to nse OròBèé ni ò w‘òrunÌgbàyí lebo wa ó maa dà dórunAkínyagbá ìwo mà lomo ElèrùúpéEbo wa yóó maa dà dórunKófin-kofin lorí eku n kéEbo wa yóó maa dà dórunKófin-kofin lorí eja n‘ kéEbo wa yóó maa dà dórunAkínyagbá ìwo mà lomo ElèrùúpéEbo wa yóó maa dà dórunKófin-kofin lorí eye nkéEbo wa yóó maa dà dórunAkínyagbá ìwo mà lomo ElèrùúpéEbo wa yóó maa dà dórunKófin-kofin lorí eran nkéEbo wa yóó maa dà dórunAkínyagbá ìwo mà lomo ElèrùúpéEbo wa yóó maa dà dórun

Page 7: EBBO RIRU.docx

Òrò àìfìn ò sunwònEbo wa yóó maa dà dórunAkínyagbá ìwo mà lomo ElèrùúpéEbo wa yóó maa dà dórun18º Ahora es que se rezan los versos del odu por el cual se estahaciendo el ebó, entreverso y verso del odu se rezara el verso para que Ifá acepte el ebó (Nº10).19º Después de rezar los versos del odú del ebó, se rezará los versosdel odu llamadoomó-iyá, es decir el hermano contrario al del ebó (Ejemplo: odu delebó Ogbe Roso,omó iyá Iroso Umbo). Nótese que no es el contrabure como se dicecomúnmente, en esecaso sería. Ejemplo: Ogbe Roso – Oyekun Juani. Este no es el caso.7

20º Una vez rezado esto es cuando se reza el odu Ojuani Shobe, odu quese puso a laderecha del odu del ebó, este verso es para poner el asé de Esu Odaraal ebó para quesea aceptado en el cielo:Òwónrín-Sogbè Awo AyéÒwónrín-Sogbè Awo Òdé ÒrunDíá fún Àgàn ÌgbàlèTì omo aráayé nwá idi rèé ríEbo ni wón ni kó wáá seÓ gbébo ó rúboÒdómodé kìkí rídìí ÀganIgi ìgbàlè le rí

21º Otro verso de Ojuani Shobe:Olú KinndínrinÀsà KinndínrinDíá fún ÒwónrínTi ń sawo lo àpá ÒkunTòun Ìlàméjì ÒsàÓ ń lòó gbágún ÒkùnÓ ń lòó gbágún ideÓ ń lòó gbágún Olgìnnìgìnnì aso òde Ìràdà wáléEbo ni wón ní kó wáá seÓ gbégo ó rúboOlú KinndínrinÈsù Òwónrín-Sogbè p‘Ajé wáOlú KinndínrinÈsù Òwónrín-Sogbè p‘Aya wáOlú KinndínrinÈsù Òwónrín-Sogbè p‘ Omo wáOlú KinndínrinÈsù Òwònrín-Sogbè p‘Ogbó wáOlú KinndínrinÈsù Òwónrín-Sogbè p‘ re gbogbo wá22º Otro verso de Ojuani Shobe:Èsù kú Orí

Page 8: EBBO RIRU.docx

Egbà kú OriDíá fún won ni Ìjèsà orùn ekuÈsù kú OríEgbà kú OriDíá fún won ni Ìjèsà orùn ejaÈsù kú OríEgbà kú OriDíá fún won ni Ìjèsà orùn eye8Èsù kú OríEgbà kú OriDíá fún won ni Ìjèsà orùn eranÒwónrín-Asogbè, k‘Èsù gbàÈsù gbà tireKóo yáa lo oÒwónrín-Asogbè, k‘Èsù gbà

23º Otro verso de Ojuani Shobe:Bonranhún Awo Òde ÌdóÒpè gorongobì Awo Òde ÌjèsàÈrìgì-dúdú Awo ÌmósàkunDíá fún Olófin ÒbèlènjèTi nbá ibi í sùnTi nbá ibi í jíEbo mo wónní kó wáá seWón gbégbó ó rùbóÒní ki ibi ìdíIbia a mó yáa ló oIgba lewé Olówònrànnsánsán okoKa siì kó‘bi rèlùjùA kóre sojú AwoAlubi a sì maa pèyìn dàÈdú gbá‘lé oÈdú gb‘ónàÈdú gbá gbogbo irumbi dà s‘ósà

24º Después se rezara el odu Obara Bogbe:Ikú yòóÀrùn yòóIrumbi níí gbébàá òrun fìofìoDíá fún lóde ÌdóNíjó ajogun ká won mole pitpitiEbo ni wón ní kí wón wáá se oWón gbébo ó rùboIkú ilé yìí kó derùKó máa lo oÒwìrìwìrìA ó finá Ifá wi wón làra oÒwìrìwìrìÀrùn ilé yìí kó derùKó máa lo oÒwìrìwìrìEjó ilé yìí kó derù

Page 9: EBBO RIRU.docx

Kó máa lo o9ÒwìrìwìrìA ó finá Ifá wi wón làra oÒwìrìwìrìÒfò ilé yìí kó derùKó máa lo oÒwìrìwìrìA ó finá Ifá wi wón làra oÒwìrìwìrì25º Otro verso de Obara Bogbe:Apòpó ibìkan ò so ní poro okoDíá fún Òòsànlá ÒsèèèmàgbòTi yóó pa Ikú lópàá ÒjéEbo ni wón ní kó wáa seÓ gbébo ó rúbóNjé Òòsànlá ÒsèeèmàgbóÒun ló pa Ikú lópàá ÒjéOba Ijiwó ló pa Ikú Awo ní gbangba

26º Otro verso del odu Obara Bogbe:Ikú yòóÀrùn yòóDíá fún won lóde IdóOmo atannà beere leku lo oTikú-Tikú làá ràgbáÀwon àgbà níí pète àìkúDíá fún won lágbòó ÒdoIbi tilkú n gbé won lómo loWorowórtè gbántetéDíá fún won ní Ìjàyè ApèróIbi wón gbè nfojoojúmó kominú ajogunEbo ni wón ní kí wón wáá seWón gbébo ó rùboWorowórtè gbántetéKó ro igbá iléGbántetéKó ro àwo iléGbántetéKó ro okoKó ro ayaGbántetéKó ro ebiKó ro omoGbántetéWórò dé o Gbánteté10

27º Otro verso del odu Obara Bogbe:Akìí mòó sunKómòó wìK‘ètí eku ó má baá jóná IfáDíá fún Látosé

Page 10: EBBO RIRU.docx

Omo Èwí nílé AládóA kìí mòó sunKó mòó wíK‘ètí eku ó má baá jóná IfáDíá fún SónrówòTíí somo Ìyá miA kìí mòó sunKó mòó wìK‘ètí eku ó má baá jóná IfáDíá fún Káru-KódàáTíí somo Elégbárá oÀwon mérèèrin ni wón múlé ayéEni wón pé yóó lòówó níí lówóEni wón pé yóó bímo níí bímoEni wón pé yóó níre níí níreÀwon mérèèrin wá dopón sílè wéEbo ni wón ní kíwón wáá se oWón gbébo ó rùboEmi sebo títíMo pe LátoséIfá ò bá je‘bo ó dà félébo oSìnrìngunsìnEmi sebo títíMo pe SìnrìngunsìnTíí somo ÒsùSìnrìngunsìnIfá ò bá jé‘bo ó´dà félébo oSìnrìngunsìnEmi sebo títíMo pe SónrówòTíí somo Ìyá mi oSìnrìngunsìnIfá ò bá jé‘bo ó´dà félébo oSìnrìngunsìnEmi sebo títíMo pe Káru-KódàáTíí somo Elégbára oSìnrìngunsìnIfá ò bá jé‘bo ó´dà félébo oSìnrìngunsìnBí e bá njà n´lé11Bí e bá njà lodoIlé eni tó bá nseboNikí e máa dá sí

28º Después se reza el odu Ogunda Bede:Agídí páálí pèlú ìniraÀkùretè pèlú ìyáKàkà kí ń jé àkùretèMa kúkú jé agídí-páálíDíá fún Ògúndá

Page 11: EBBO RIRU.docx

Ti yóó ya‘lé Ogbè kó jòkòóMo ya‘lé Ogbè mo ńíìsinmi oÒgúndá ló ya‘lé Ogbè ló jókòóMo ya‘lé Ogbè mo ńíìsinmi o

29º Otro verso del odu Ogunda Bede:Kùkùté ò mire jìgìDíá fún LánkosìnOmo ajagun gbádé boríÓní ibi e bá forò sí oE má mà jé kó yèAwo ni kùkùté ò mire jìbìAwo ni LánkosìnKùkùté ò mire jìbì

30º Otro verso del odu Ogunda Bede:ÒtóóttootóÒróórooróÒtóóto làá jèpàÒtóóto làá je ìmumuLótòlótò làá so olú esunsun sènuOun torí ni toríOun toòrì ni toòrìOun torí-toòrì làs fìì fún Obamakin lóde ÌrànjéKó baà lè foun torí toòrì tani lóreDíá fún Atíòro bàgèbàgèTi nsawo relé OníkòyíIbi Orí ì mi rán mi rè ni mo lo oÀtìóro gàbébàgè tì ńsawo relé OníkòyíIbi Orí ì mi rán mi rè ni mo lo o12

31º Otro verso del odu Ogunda Bede:Tòtò ni òmu igi lókèDíá fún ObàTi ńlo sóko alero lódúnEbo ni wón níkó wáá seÓgbébo ó rúboMo rokoMo je gburu ajé locoObà tó làlààlàTíwón ńpè ní ObàtáláOba tóta ilá tó là láálàNi wón ńpè ní ObàtáláObà o mà ti là lálàjù

32º Después se reza el odu Okana Yeku, este odu se conoce como “Onibodè Olórun”,que significa el portero del cielo. Es mediante este odu que el ebópasa antes de entrar alcielo:Òkànràn-Òyèkú, Onibodè OlórunDíá fún AdàgólójóTi nlòó fara sofá lodo Etu

Page 12: EBBO RIRU.docx

Ebo ni wón níkó wáá seÓ gbébo ó rúboFìrí la r‘ÉrinÉrin nigbàwo lo mà dòkè

33º Otro verso del odu Okana Yeku:B‘àlé bá léWon a ló dowóo finná-finnáBóòrùn ò ràn móWon a ló dowó OlodùmarèDíá fún AlárìnnàkáWòn ní aáyán ó yánWon ní èèrà ràáÒrúnmìlà ní tó bá se bii ti Alárìnnàká omo toùn bá niÀáyán kìí yánmó IkinÈèrà kìí ra omo ÒrùnmìlàNg ó lòNg ó bò sìlée bàbá à mi oTóòrùn bá yo lòwuròBóbá daléA pada sílé e bàbá ré13

34º Otro verso del odu Okana Yeku:Ìkóríta méta ò senu gongo sókoDíá fún ÒrúnmìlàBàbá ńlo rèé fé TéníòlàTíí somo AláráÓ ńlo rèé fé Tèn´‘olàTíí somo AjeròÓ nlo rèé fé OlólòlòòmokùnTíí somo Owánràngun-AgaEbo ni wón ní kó wáá seÓgbébo ó rúboÌgbà tí Téníòlà máa bíÓ bí Eboo-finÌgbà tí Olólòlòòmokùn máa bíÓ bí Àdàkan-Àdàkan-ni-t‘ÒpápaÒrúnmìlà kó won ní dídá owóWón mòó dáÓ kó won ní òntè-alèWón mòó tèÓ kó won ní òkarara eboWón mòó ha kooroko jakóWón wá lo sefá fún Olófin-sebo-kórùn-ó-móNíjó tó nbe laarin ìnira sángílítíOlófin-sebo-kórùn-ó-móOùn ló sefá fún Òkan-yìí-ò-níí-kúTíí somo Olódùmarè AgòtúnÌkan yìí ò níí kú ó ráa mi oÀwa á ti sebo sètùtù

35º Otro verso del odu Okana Yeku:

Page 13: EBBO RIRU.docx

Awo ilè Àjànkoro dùgbéDíá fún won ní ìlú Àjànkoro dùgbéWón láwon ò sebo, s‘Òòsa móÀjàngun lóká won mólé pitipitiWón ní kí wón sákáalè ebo ní síseWón gbèbo wón rùboNjé jànkoro dùgbè-dùgbèA ti rùboEbo ó dá ná oÀjànkoro dùgbè-dùgbèIlé mi mà jìnBí Ikú ńloKó rè wá mo sebo oÀjànkoro dùgbè-dùgbèAti rùbo14Ebo dà ná oÀjànkoro dùgbè-dùgbèIlé mi mà jìnB´Árùn ńloKó rè wá mo sebo oÀjànkoro dùgbè-dùgbèAti rùboEbo dà ná oÀjànkoro dùgbè-dùgbèIlé mi mà jìnB´ ejó ń loKó rè wá mo sebo oÀjànkoro dùgbè-dùgbèAti rùboEbo dà ná oÀjànkoro dùgbè-dùgbèIlé mi mà jìnB´ ófò ń loKó rè wá mo sebo oÀjànkoro dùgbè-dùgbèAti rùboEbo dà ná oÀjànkoro dùgbè-dùgbèIlé mi mà jìnB´ájé ń loKó rè wá mo sebo oÀjànkoro dùgbè-dùgbèAti rúboEbo dà ná oÀjànkorodùgbè-dùgbèIlé mi mà jìnB‘Áya ńloKó yà wá mo sebo oÀjànkoro dùgbè-dùgbèAti rúboEbo dà ná oÀjànkoro dùgbè-dùgbè

Page 14: EBBO RIRU.docx

Ilé mi mà jìnB‘ómo ńloKó yà wá mo sebo oÀjànkoro dùgbè-dùgbèAti rúboEbo dà ná oÀjànkoro dùgbè-dùgbèIlé mi mà jìnBi ire gbogbo nlo15Kó yà wá mo sebo oÀjànkoro dùgbè-dùgbèAti rúboEbo dà ná oÀjànkoro dùgbè-dùgbè

36º El siguiente odu en rezar es Oshe Bile, a continuación el verso del odu:Eni tó jìn kòtòLó kó ará yòókù lógbónDíá fún ÒsèTi yóó bi Ìretè sílé AjéEbo ni wón ń kó wáá seÓ gbébo, ó rúboIbi ówù yìn e tì mí síIbi ire ń Ifá ńgbé mií lò oIfá ngbé mi rèlú IlájéL‘Erigí-Àlò n gbé mi í rèIbi ireIfá ngbé mi í ìlámoIbi ireL‘Èrìgì-Àlò ngbè mi í rèIbi ireIfá ń gbé mi rélú íníre gbogboIbi ireL‘Erigí-Àlò ń gbé mi í réIbi ire.

37º Otro verso del odu Oshe Bile:LáafiàÀlááfiàÈúùfù tó fé rekojaKó má gbojùde bàbá á tèmi rékòjá ló oDíá fún SéoróTíí somo kùnrin abataÈyí tó soore láyéTó lóun ò tún soore móÓ ní ìkà ló kù tóun ó maa seoOgún, Awo ilé AlàràWón ò mèbè e re oOgbón Awo Okè ÌrejìWón bèé-bèéWon ò mèbè e re oÈtàlélégbégbèje Awo Èpa Tòòròmòfé

Page 15: EBBO RIRU.docx

Wón bèé-bèéWon ò mèbè e re o16Àwòn Àró-gàáÀwòn Àró-gòóDíá fún ÒrúnmìlàIfá ńrayé OlùjégèÒun Èra-jééje oEbo ni wón níkò wáá se oÓ gbébo ó rúboB‘Ósó ń bínúÒsè-bìí-lè, ‘wo loó bèéBajèé ńbínúÒsè-bìí-lè, ‘wo loó bèéÈbùré o dé o Awo OlùjébèBí a bá r‘Awo ireA sì jébè

38º Otro verso del odu Oshe Bile:Pepe lawo IléÌgbàlèrò lawo ÒdeÒgúnná ni ò wò rùrùùrùKó gòkè odòAlàpàndèdè ló kòlé tánLó yojú u rè s‘ódòòdoDíá fún OyèpólúOmo Ìsòrò n‘IfèBaba rèé fi sílè kúKí kékeré lénje-lènjeÌyáa rèé fí sílé kúKí kékeré lénje-lènjeKó máa wáá sorò ilé e Baba reÓ wá tu púrú sékúnÓ lóun Oyèpólú ò mòkan oÒun ò mo dídá owóÓun ò mo òntè alèÒun ò tilè won dé Òtu-Ife sodúnWón ní kó máa tèé básuWón ní kó máa tèé básuWón ní kó máa tèé básu-bàsuWón ní Akódá yóó máa gbà fúnAsèdá yóó máa gbà fúnOyèpotu ò mòkanÌsòrò OlórunEjírò awo ilé OlófinOlórun-tìkùn awo Ìjèbú-mùreÒgbònkàn nídàNíjó ti wón ko igbá ebowon lóde órunWón ní àwon taani17Wón ní àwon ade-pápá owó òtúnÀwon ‘gbèdeò pa bata mésè tosíÀwon gbénà-gbénà órun Ìgbábogo ide

Page 16: EBBO RIRU.docx

Njé Akódá e sikùn fébo oAsèdá e síkún fébo oÀse iná ni iná fi nmókoÀse òòrùn lorun fi n kàngbònNkjó eyin die bà dari solèOjo nàá níí fóNíjó iná bá fojú kan omiOjó nàá níí kéé rómÈsìsì ò níí jé kébo tàwa ó sùnnà

39º Otro verso del odu Oshe Bile:Ejírò Awo ilé OlófinOlórun-tìkùn awo Ìjèbú-‘MùreÒgbònkàn nídàNíjó ti wón ko igbá ebo won lóde órunWón ní àwon taaniWón ní àwon ade-pápá owó òtúnÀwon àgbède ò pa bátá mésé tosíÀwon àgbènà-gbénà órun Ìgbábogo ideNjé Akódá e sikùn fébo oAsèdá e síkún fébo oÀse iná ni iná fi nmókoÀse òòrùn lorun fi n kàngbònNkjó eyin die bà dari solèOjo nàá níí fóNíjó iná bá fojú kan omiOjó nàá níí kéé rórnÈsìsì ò níí jé kébo tàwa ó sùnnà

40º Otro verso del odu Oshe Bile:Ká gbáa níbùúKá gbáa loroDíá fún ÀàsèTí ńlo ogun ÌlurinEbo ni wón níkó wáá se oÒgbèbo ó rúboTáàsè bá lu‘rin tánAra a rè a sì le kokooko18

41º Otro verso del odu Oshe Bile:Ejò ni ò kómo léyìn yooyóòyoKó máa je ká‘koDíá fún kérénnàsíTí yòò gbògbóògbóTí yòò gbé egbèédógún odún láyéKì mà í kú‘kú oeówòSasaraKìí kú‘kú orówòSasaraAkárákárá ojúu Kangara ni O seé gbá múÒkánjúwà ló wòkè ràdàràdàNí ń wò rosoroso

Page 17: EBBO RIRU.docx

42º Otro verso del odu Oshe Bile:Kèngbè ni ò gburu w‘amuDíá fún OdiA bù fún YàràÌwà Odi ń séÌwà Odi ń bàjéÀtèwe, àtàgbàE wá lo rèé tún‘wà Odi se o

43º Otro verso del odu Oshe Bile:Aagba fàá níhìn-ínÌjòkù fàá lóhìn-únDíá fún WalamiTí nlo rèé bá won tún ìwà Okò seBókò bá ròkun ròsàElébùúté níí fori í fúnNí´le Oba won nílé Èyò-maroMá mà jókò ó dàWalamiMá mà jókò ó dà19

44º A continuación se reza el odu Irete Meji. El dicho “ti Ìká káríebo Ìretè níí tèé” quesignifica, si Ìká completa el ebó, Ìretè le da su aprobación. Verso del odu:Èèrùn-ún yán ni ìfofò keeteDíá fún AtókaTíí se ìkàrí OlòdùmarèMo di Ìlàrí IkinÈmi ò ròkoAtóka di Ìlàrí OlòdùmarèMo di Ìlàrí IkinÈmi ò ròkoAtóka di Ìlàrí Olòdùmarè

45º Otro verso del odu Irete Meji:Oko réAya réDíá fún Òkéké jègbèTí yóó fé bìnrin Ikú tánTí yóó fobì méfà tanÈrò Ìpò èrò ÒfàE wá bá ni lárùúsé ogunÀgbàgbé ninfa ó gbà láya

46º Otro verso del odu Irete Meji:Pagúnnugún bofá Awo wón nílé AláráPàkàlàmàgbò bosè Awo Òkè ÌjèròPàtíòro b‘Ògún aláyà bi òde èèbóFàá nànàànà kó sì tú pèéOde Gabón mi níí wólé ejaApàjùbà níí wólé àparò

Page 18: EBBO RIRU.docx

Òlùgbóngbó tìnlà ni wón fi nségun ÒgúnlùntuAkò esin níí sáré bonranyìn-bònrànyínBésin bá jíEsin a kó gbindin-gbindin há inúDíá fún Láígbo ÒgègéTí wón ń mo ilé e rè láyéWón é pilè e tòrun pé kó wáE bá wa wólé Òrin nùE wá tún tayé mo oÌjògun Òrun abewú orí sànkòIlé awo mà ń wó lorunÓgègéIlé awo mà ń wó lorunÓgègé20

47º Otro verso del odu Irete Meji:Pètèpéètè níí mójú òná gbábùúDíá fún Elédè abomo yòòOmo pò níwájúOmo pò léyinOmo yòyòòyò ni tòdo

48º A continuación es que se reza el odu Oshe Tura que se coloco a laizquierda del odudel ebó. Este odu se reza para que las cosas solicitadas se realicen:Pénpé elesèè tùbúÈlà agemo ni ò tó gèlèÌbá tó gèlèNbá mú relé lòó wéDíá fún AwúrelàTí n sawo ròde IjèbúÀpèjín làá pe OnírúÀpèjín làá pe OníyòÀpèlà, àpèlà làá pe AwúrelàNí ÌjebúÒsé Awúrelà, Awo ire ni o

49º Otro verso del odu Oshe Tura:Akéke nì bagi saDíá fún ÒrúnmìlàTí Awo bá ní a ó làájéTí nlòó gba Ìbà òun Àse nílé OlódùmarèÀ máa lájéÀkéké nì bagi saEnu àwoN‘Ìbà òun Àse wáEnu àwoTí awo báni a ó láyaÀ máa láyaÀkéké ni bagi saEnu awoN‘Ìbà òun Àse wá

Page 19: EBBO RIRU.docx

Enu awoT‘ awo bá nì a ó bìmoA máa bìmoÀkéké ni bagi saEnu awoN‘Ìbà òun Àse wáEnu awoT‘ awo bá nì a níre gbogbo21A máa níre gbogboÀkéké ni bagi saEnu awoN‘Ìbà òun Àse wáEnu awo

50º Otro verso del odu Oshe Tura:Pàákàrà wóó wóó wóó Awo Ìdí ÈsùDíá fún Òsé TééréTì n gbébo ilèé ròde ÒrunEni í fówó ó níE wáá rán fá nséÒsé ngbébo rò de ÒrunBi e nísé e ránEni í fáya á niE wá rán fá nséÒsé ngbébo rò de ÒrunBí e nísé é ránEni í f`ómo ó níE wáá rán fá nséÒsé ngbébo rò de ÒrunBí e nísé é ránEni í fére é níE wáá rán fá nséÒsé ngbébo rò de ÒrunBí e nísé é rán

51º Otro verso del odu Oshe Tura:Apá nii gbóko níí te kósóÌrókò èlùjè níí gbé`lè níí sònmèmèÒpè àgùnlá n ló yo kangà MérìndínlógúnIjió ni míMa dáwó okó kan un lágboDíá fún won ní Ibadan ÒjígínOmo ajèggín yóFi ìkarahun fór fómo won muTalétalé àwo ilé OnísakìDíá fún OnísakìOmo Ògún ò rokeÀgbède won ò mè`ro ìlèkèDíá fún won ní ÌlorinWon ó mò rírú eboWon ó mò èrù àtètètùWon n kú ikú agó sílé beerebe

Page 20: EBBO RIRU.docx

Òró wònyí ti tó apero gègè gègè22Díá fún won làbe OlúmoPàákàrà yéé yèè yéé kò seé tù lágbèrùDíá fún TètéTíí yóó se ìyá Òsé-TùúráIre ayé ń làwa nwáLowó àwa ò tó IfáÒsé Elérùwà iwo lomo ìjòyè Òkè-ÀpàIfá o gbó óÈdú o gbó lórun oÒsé Awùrelà Ifá o gbó oIre aya nlàwa nwáLowó àwa ò tó IfáÒsé Elérùwà ìwo lomo ìjòyè Òkè-ÀpàIfá o gbó óÈdú o gbó lórun oÒsé Awùrelà Ifá o gbó oIre omo nlàwa nwáLowó àwa ò tó IfáÒsé Elérùwà ìwo lomo ìjòyè Òkè-ÀpàIfá o gbó óÈdú o gbó lórun oÒsé Awùrelà Ifá o gbó oIre ogbó nlàwa nwáLowó àwa ò tó IfáÒsé Elérùwà ìwo lomo ìjòyè Òkè-ÀpàIfá o gbó óÈdú o gbó lórun oÒsé Awùrelà Ifá o gbó oIre gbogbo nlàwa nwáLowó àwa ò tó IfáÒsé Elérùwà ìwo lomo ìjòyè Òkè-ÀpàIfá o gbó óÈdú o gbó lórun oÒsé Awùrelà Ifá o gbó oÀsélé o dé, Ilé gbóhùnAwo o wá dé `bí ilé gbé ń gbìre oTóó! Esìn!

52º A continuación se cogen todos los granos de maíz y se colocan en el suelo odentro de una jícara con agua fresca. Después se le debe pedir al cliente que23recoja uno por uno y que los ponga en el eko usado para ofrecer el ebó. Mientrasse hace esto, el cliente dice que el ha pagado por la muerte, la aflicción, lapérdida, la litigación, las brujas, los magos, todas las cosas malasde la vida paraque nada pueda afectarlo. Después ellos pagaran por riqueza, esposa, hijos,longevidad, éxito, felicidad, victoria, buena salud y las buenas cosasde la vidapara que asi sean de ellos. Después de esto el practicante de Ifápondrá parte delos materiales del ebó con el eko. Se pondran las plumas de algunas aves y se

Page 21: EBBO RIRU.docx

pondrán en el eko. Se le añadirá agua. Mientras se añade el agua, el practicantede Ifá usará un verso de Ifá para poner Àse en el ebó. Por ejemplo, un verso enÈjì-Ogbè puede ser utilizado:Alóló omiAlòló omiÀti-wáyè e GunugunÀti-ròrun ÀkàlàmàgbòÓ n roni lójú tòkíDíá fún ÒrúnmìlàIfá nlo rèé gbé Olómi-tútù niyawoIfá ló di èèwò IfeÈrìgì-Àlò ó níí fi Olómitútù fún Ikú paT`òun Ikú ti di ìmùlè(Este verso es usado para tenga una vida larga y feliz)

53º Después de esto se le pregunta a Ifá si se le echa epó al ebó, sidice que si se lerezara el verso mientras se le añade, bajo ningún concepto se echará epó si elebó es a una mujer embarazada. Verso del odu:Gùrugùru gùègùèDíá fún EpoTííí se omo ìyá EboEpo gorí i rè ó d`EboGùrugùru gùègùèEpo gorí i rè ó d`EboGùrugù gùègùè

54º Si dice que no al epó, se pregunta a Ifá si se le añade licor, sidice si se le rezael verso del odu Otura Rete mientras se le añade el licor al ebó:Òtúrá lalèmuÌretè lalèràDíá fún ÀrànìsànTí yóó muti kan àmulòwòOti olà lawo ń mu

55º Después se pregunta a Ifá que se hace con los ingredientes del ebó quesobraron y que camino cogen. Terminado esto se escribe de nuevo en el tablero24sobre el iye-irosun sobrante el odu Okana Sa, se coloca el ebó encimadel tablero,entonces se coge el iruke de Ifá (cola de vaca), y se tapa el ebó. Se reza elsiguiente verso del odu Okana Sa:Ká mú gégé lu gégéAwo ilé AlákòókóÌgbin òtara iná yíyáÀwòdì ni ò pa sàà gbèádìe ràOlúwo méta irùkèrè méfáOgun ti a fi èsín síTi a ò leè síOgun ti a fi òkó jàTi a ò leè jàKíni Èdú fi tú mó o rè

Page 22: EBBO RIRU.docx

Ìrùkèrè l`Èdú fi túmò o rèTú mò IkúTú mò ÀrùnTú mò EjóTú mò Òfò

56º Otro verso del odu Okana Sa:Òkànràn Sálè SákùútàAwo Okó ló díá fún fOkóTíí somo Onírèé SànbéÒkànràn Sálè SákùútàAwo Aso ló díá fún f`Aso

57º Otro verso del odu Okana Sa:Òkànràn Sálè SákùútàAwo Okó ló díá fún f`OkòTíí somo Onírèé SabeÒkànràn Sálè SákùútàAwo Okó ló díá fún f`AsoÒkànràn Sálè SákùútàAwo ilé ló díá fún IléA kìí gbó`kú OkóA kìí gbó`kú AsoA kìí gbó`kú IléÀyàfi bó sá

58º Otro verso del odu Okana Sa:25Òkànràn Gan-anran Awo AwóDíá fún AwóWón nó kó rúboKí òrò o rèé lè lóríÓ gbé`bo ó rúboKò pé kò jìnnàE wá bá ni bá wòwó ire o

59º Otro verso del odu Okana Sa:Ó tù sooro Awo OpaDíá fún OpaKá ti iwájú bùúKá ti èyìn bùú, Awo ÀjèDíá fún ÀjèÈmì yìn-ìn Awo OkóDíá fún OkóAgbè-bìkan jìfà, Awo ElébùútèDíá fún ElébùútèBókò bá ròkun ròsàDandan ni kó forí fún Elébúùtè

60º Ahora es que se pregunta si le falta algo al ebó y el camino quecoge el ebó.

61º Ahora se procede a comer un poco del iye-irosun que quedo del ebó con el

Page 23: EBBO RIRU.docx

siguiente verso del odu Osa Di:Adimula AdimuyeErindimu ErinyasoEfondimu EfonyajanaManjagbani ManjagbrareAdifa fún AkikaTinloreedi opo ope mu ni tori abiye omoOpe emi odi omu ki oma yinminuIyere ara igi ki iwonnuIjo ti Ikú bambú koobooIjo ti gbogbo ajogun banbo koobooIjo ti aje banbo koosiisiléIjo ti Ire gbogbo banbo koosiisilé