28
111 Chapter 5 - Orí Karùnún | MY FAMILY TREE OBJECTIVES: In this chapter you will learn: - How to describe people by using the verbs ‘jê’, ‘ni’ - How to use the negation ‘kô’ - How to use the interrogative ‘ta ni’ - How to describe one’s family

Chapter 5 - Orí Karùnún | MY FAMILY TREE › yemi › pdfs › yy_ch5.pdf · Chapter 5 - Orí Karùnún | MY FAMILY TREE OBJECTIVES: In this chapter you will learn: - How to describe

  • Upload
    others

  • View
    13

  • Download
    0

Embed Size (px)

Citation preview

111

Chapter 5 - Orí Karùnún | MY FAMILY TREE

OBJECTIVES:

In this chapter you will learn: - How to describe people by using the verbs ‘jê’, ‘ni’ - How to use the negation ‘kô’ - How to use the interrogative ‘ta ni’ - How to describe one’s family

Orí Karùnún (Chapter 5) Àwæn örö (Vocabulary)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 112 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Àwæn örö (Vocabulary)

Nouns aáwö differences

àbúrò younger sibling

àgbà older person

agbolé compound

àdúgbò neighborhood

àgbàlagbà older person

agb÷jôrò lawyer

àkójæpö collection

akêköô student

àlàáfíà peace

apòògùn pharmacist

àpônlé respect

ara body

à«à culture

baálé male head (of family)

burêwà ugly

dókítà doctor

ëgbôn older sibling

ëkô studies

ëwà beans

gbogbo all

ìdàgbàsókè progress, development

ìdöbálë prostration

ìdílé family (immediate)

ìlú town, city, country

ìgbàgbô belief

igun branch (of family)

ìpàdé meeting

ì«ègùn medicine

ìtumö the meaning

kódà in fact

Orí Karùnún (Chapter 5) Àwæn örö (Vocabulary)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 113 CC – 2012 The University of Texas at Austin

mölêbí family (extended)

ojoojúmô every month

ækæ husband

olórí head

o«oo«ù every month

ösöösë every week

oúnj÷ food

æjà market

æmædé youth

pàjáwìrì emergency

píparí settling of; completion of

wúrà gold

Noun Phrases bùrödáa lágbájá brother (of somebody)

ètò ÷bí organization of family

Verbs dàrú confused, disorganized

fún for

gbé to live in/at

gbædö must

j÷ to eat

jê to be

kúnlë kneel down

parí to complete

sörö to talk

tí if

túmö sí translates to/means/implies

wí pé said that

Verb Phrases bí tëlé to be born following

kóra jæ to get together

lè dàrú can lead to chaos; can be disorganized

Orí Karùnún (Chapter 5) Àwæn örö (Vocabulary)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 114 CC – 2012 The University of Texas at Austin

kò ì tí ì has/have not yet

máa ñ wáyé always takes place lágbára to be strong

«e kókó is important; is crucial

«e pàtàkì is important

Adjectives ga tall

kéré small

kúrú short

köökan each sanra fat

tóbi big

tínínrín skinny (thin)

Adverbs péré only

Conjunction àti and

nítorí èyí because of this

nítorí pé because

nípa about

Preposit ional phrases láàárín among, in the middle of nígbà mìíràn at other times

Interrogative mélòó ni how many?

Other Expressions ÷ni tí ó bá juni læ anyone that is older than oneself

ìdí èyí ni wí pé this/that is why

kí ayé ó gún for the world to be in good shape

ægbôn àti òye wisdom and understanding ökan lára one of

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 115 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Lesson 1 - Ëkô Kìíní:

The verbs ‘ jê’ ‘ to be’ and ‘ni ’ ‘ to be’

The Verb ‘Jê’

The verb ‘ jê’ implies to be. It is frequently used with professions. For example: Ladi jê dókítà. Ladi is a doctor. Fadérera jê agb÷jôrò. Fadérera is an attorney/a lawyer. Mo jê akêköô. I am a student.

The verb jê can be used to link phrases. For example: Ëwà jê oúnj÷ tí ó dára láti j÷ Beans are good to eat.

Jê can also be used to express one’s age. For example: Kêmi jê æmæ ædún mêwàá Kêmi is 10 years old Màmáà mi jê æmæ ogójì ædún My mother is 40 years old

Jê + negation

Jê kì í «e Ladi jê dókítà Ladi kì í «e dókítà Ladi is a doctor Ladi is not a doctor Mo jê akêköô N kì í «e akêköô I am a student I am not a student Kêmi jê æmæ ædún mêwàá Kêmi kì í «e æmæ ædún mêwàá Kêmi is 10 years old Kêmi is not 10 years old

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 116 CC – 2012 The University of Texas at Austin

The verb ‘Ni’

In Yorùbá, ‘ni ’ is another form of the verb ‘to be’ as used in the sentences below: Èmi ni màmáa Túndé. I am Túndé’s mother. Dókítà ni Ládi. Ladi is a doctor. Öla ni æjà Tomorrow is market day. Ìyá ni wúrà Mother is gold. However, one cannot say: * Dókítá jê Ládi * Öla jê æjà one would rather say Ládi jê dókítá Öla jê æjô æjà

Negation ‘kô’

When ni is negated, it becomes ‘kô ni’, as found in the examples below: Èmi ni bàbáa Kóyè. I am Kóyè’s father. Èmi kô ni bàbáa Kóyè. I am not Kóyè’s father. Àwæn ni màmáà mi. She is my mother. Àwæn kô ni màmáà mi. She is not my mother. Olú ni àbúrò Adé Olú is Adé’s younger sibling. Olú kô ni àbúrò Adé Olú is not Adé’s younger sibling. »é àwæn ni olùkôö r÷? Is s/he your teacher? Rárá, àwæn kô ni olùkôö mi. No, he is not my teacher. Regular pronouns cannot be used with ‘ni ’ as in the following examples: *Mo ni dókítà *Ó ni olùkö Similarly, ‘kô’ cannot be used with regular pronouns as in the following examples: *Mo kô ni dókítà *Ó kô ni olùkö

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 117 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 1 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní òdì. Respond to the following questions negatively. 1. »é bàbáà r÷ ni olórí ìlú?

2. »é àwæn ni ëgbônæn Kíkê?

3. »é ìwæ ni dókítà?

4. »é ÷êjæ àti eéjì ni ÷êsànán?

5. »é èmi àti ìwæ ni ëyin?

I«ê »í«e 2 Yí àwæn gbólóhùn yí sí òdì. Turn the following into negative. 1. Bàbáà mi jê olórí ìlú.

2. Àwæn ni ëgbônön mi.

3. Ó jê ælôpàá.

4. Èmi àti iwæ ni örê.

5. Mo jê agb÷jôrò.

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 118 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 3 Lo ‘jê’ tàbí ‘ni’ láti fi dí àwæn àlàfo wönyí. Use ‘jê’ or ‘ni’ to fill out the blank spaces below.

1. Màmáà mi nôösì.

2. Èmi mò ñ «i«ê ní ilé-ìwé.

3. Wôn öjögbôn ní ilé-ìwèé mi.

4. »é àwæn màmáà r÷?

5. Èmi æmæ bàbáaTádè.

6. Ó mà«e o. Ó æmædé nií.

I«ê »í«e 4 Yí àwæn gbólóhùn wönyí sí òdì. Turn the following sentences into negation.

1. Mo jê nôösì

2. A jê akêköô

3. O jê dókítà

4. ¿ jê öjögbôn

5. Ó jê olùkô

6. Wôn jê olórí ìlú

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 119 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Lesson 2 - Ëkô Kejì:

The interrogative ‘Ta ni’

The interrogative ‘ta ni’ implies ‘who’ Ta ni örêë r÷? Ta ni bàbáà r÷?

Ìsöröngbèsì (Dialogue)

Ælá: Bàbáà mi, mo ní örê kan. Dad, I have a friend.

Bàbá Ælá: Ìy÷n dára o. Ta ni örêë r÷? That’s nice. Who is your friend?

Ælá: Orúkæ rë ni Láñre. His name is Láñre.

Bàbá Ælá: Ta ni bàbáa Láñre ? Who is Láñre’s father?

Ælá: Öjögbôn Ö«úndáre ni bàbáa Láñre

Professor Ö«úndáre is Láñre’s father.

Cultural Vignette: ÀPÔNLÉ

Àpônlé jê ökan lára à«à àti i«é àwọn Yorùbá. Yorùbá máa õ pa á lówe pé: ÷ni tí ó bá ju ’ni læ lè juni nù . Ìtumö èyí ni pé, ÷ni tí ó bá ju ènìyàn læ ní ægbôn àti òye ju ènìyàn læ. Àwôn Yorùbá á tún máa wípé: Àìböwö fún àgbà ni kò jê kí ayé ó gún. Eléyìí túmö sí pé: ilé ayé ñ dàrú nítorí wí pé àwæn ènìyàn kò «e àpônlé tí ó y÷ fún àwọn tí ó jù wôn læ. Bàbá àti ìyá ènìyàn nìkan kô ló y÷ kí ènìyàn «e àpônlé fún. Ó «e pàtàkì fún gbogbo ènìyàn láti «e àpônlé fún ëgbôn, ÷bí, ará àti ojúlùmö tó bá junì læ. Ènìyàn kò gbædö pe àgbàlagbà lórúkæ. Bùrödáa lágbájá tàbí àõtíi/sìsìtáa lágbájá ni ènìyàn gbædö pe ÷ni tí ó bá junì læ. Ìdöbálë ni ækùnrin máa ñ kí ÷ni tí ó bá ju ènìyàn læ. Àwæn obìnrin máa ñ kúnlë láti fi àpônlée wæn hàn. Ní önà mìíràn, ènìyàn kò gbædö lo ‘ó’ fún ÷ni tí ó bá dàgbà ju ènìyàn læ, kódà kó jê wí pé ödún kàn péré ni ÷ni náà gbà lôwô ènìyàn. ¿ni tí kò bá ní ëkô ilé ní ó máa ñ pe àgbàlagbà lórúkæ. Ara ÷kô ilé ni bí a ti «e ñ kí àwæõ tí ó bá ju ènìyàn læ.

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 120 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 1 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê.

Answer the following questions in complete sentences. 1. Ta ni ó y÷ kí ènìyàn «e àpônlé fún?

2. Kí ni àpônlé ní ilë÷ Yorùbá?

3. Ta ni ó máa ñ pe àgbàlagbà lórúkæ?

4. Kí ni ìtumö òwe yìí: ‘÷ni tí ó bá ju ’ni læ lè juni nù’?

5. Kí ni àpônlé ní ìlúù r÷?

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 121 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Lesson 3 - Ëkô K÷ta:

¿bí ní ìdílé Mêta (Three Generations of a Family)

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 122 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 1 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences.

1. Kí ni orúkæ ìdílée bàbá Àdùk÷?

2. Kí ni orúkæ bàbáa bàbá Àdùk÷?

3. Ta ni màmá Àdùkê?

4. Ta ni æmæ æmæ Æláníkëê?

5. Ta ni àwæn æmæ æmæ Æláníkëê?

6. Æmæ mélòó ni Æláníkëê ní?

7. Æmæ æmæ mélòó ni Æláníkëê ní?

8. Ta ni Babalælá?

9. Ta ni àbúròo Gbádébö?

10. Ta ni ëgbôn Àdùkê?

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 123 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 2 Parí àwæn örö wönyí. Complete the following sentences.

Bí àp÷÷r÷:

Babalælá ni ækæ Títílælá. Òun ni bàbáa Atinúkê àti Gbádébö. Òun sì ni ækæ æmæ Æláníkëê àti Adéníyì

1. Adéníyì ni

2. Gbádébö ni

3. Olútóókê ni

4. Bádé ni

5. Atinúkê ni

I«ê »í«e 3 Sæ lóòótô ni tàbí lóòótô kô fún àwæn gbólóhùn wönyí. State whether the following sentences are true or false.

Òótô ni Òótô kô

1. Àdùkê ni ækæ Ælá«ùpö. ☐ ☐

2. Ælá«ùpö ni ìyàwó Àdùkê. ☐ ☐

3. Atinúkê ni æmæ æmæ Æláníkëê. ☐ ☐

4. Bádé ni bàbá Atinúkê. ☐ ☐

5. Adéníyì ni bàbáa bàbáa Gbádébö. ☐ ☐

6. Babalælá ni bàbáa Gbádébö. ☐ ☐

7. Olútóókê ni ëgbônæn Títílælá. ☐ ☐

8. Æláníkëê ni ìyàwó Adéníyì. ☐ ☐

9. Ælá«ùpö ni æmææ Bádé. ☐ ☐

10. Bádé àti Títí ni àwæn æmæ Adéníyì àti Æláníkëê. ☐ ☐

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 124 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 4 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí. Answer the following questions.

Bí àp÷÷r÷:

Ækæ Títílælá ni? Babalælá

1. Bàbáa bàbá Àdùkê ni?

2. Òbí Àdùkê àti Ælá«ùpö ni?

3. Bàbáa Bádé ni?

4. Æmææ Bádé ni?

5. Æmææ Babalælá àti Títílælá ni?

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 125 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Wá àwæn örö wönyí. Look for these words in the puzzle below. Pay attention to the tones!

àpônlé‚ à«à‚ àgbàlagbà‚ bùrödá‚ ægbôn‚ ìdöbálë‚ wúrà‚ ìdílé‚ olórí‚ ìdàgbàsókè

à g b a l a d à b á d í l é à

d ì l e l o b í « æ l a ó g l

w í d á g b á s d à l e l a a

d ú k í ó b à ó k ö í k o l æ

w u r á l e a g í b æ a l a g

ó t b à í é d á b ö á g á m b

ì g i d ö b à d g à í j b n o

á d d ö o d í p o k l b a ô l

k í ö g l b ó d ô l b à b k n

o g a b i t ù s a n í n g á b

ó l o r á í n r á b l d ó b a

a d ó s á l ö b ö r d é k i à

ö k o r ó b ë l á d í l a r i

a d á b í o d ó b i á g d í b

b Ì d à g b à s ó k è í k e à

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 126 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Cultural Vignette: ¿bí ní i lë÷ Yorùbá

Ní ilë÷ Yorùbá, mölêbí jê àkójæpö àpapö igun. Baálé ilé ni olórí igun köökan. Ètò ÷bí jê nõkan tí ó «e pàtàkì fún àlàáfíà láàárín àwæn æmæ ÷bí àti ìlú lápapö. Ìdí èyí ni wí pé, àlàáfíà láàárín mælêbí «e kókó fún ìdàgbàsókè ìlú. Yorùbá ní ìgbàgbô wí pé ìlé lè dàrú tí àlàáfíà kò bá sí láàárínin mælêbí. Gbogbo ènìyàn ni ó gbôdö jê mælêbí kan tàbí òmíràn. Nítorí èyí ni Yorùbá fi máa ñ sæ wí pé: “A kìí wáyé ká má lêbí.” Ìpàdée mælêbí máa ñ wáyé ní ösöösë tàbí ní o«oo«ù. Nígbà mìíràn, àwæn mælêbí máà ñ ní ìpàdé pàjáwìrì. Gbogbo mælêbí tún máa ñ kóra jæ láti «e ìgbéyàwó, ìsæmælórúkæ àti ìjádeòkù.

Gbogbo ÷bí ni ó ní olórí ÷bí. Olórí ÷bí jê ækùnrin tí ó dàgbà jùlæ nínúu mælêbí. »ùgbôn nígbà mìíràn olórí ÷bí lè jê obìnrin tí ó dàgbà jùlæ nínúu mælêbí. Ara àwæn ojú«e olórí ÷bí ni píparí aáwö láàárín àwæn mælêbí. Olórí ÷bí tún máa ñ «ojú àwæn mælêbíi rë ní ìpàdé àdúgbò, ìpàdé agbolé, tàbí ìpàdé ìlú. Ó «e pàtàkì kí olórí ÷bí rí i wí pé ÷bí kò tú mô òun lórí. Ìdàgbàsókè ÷bí ní í «e pëlú irú olórí ÷bí tí wôn bá á ní.

I«ê »í«e 6 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences. 1. Kí ni pàtàkì mölêbí ní ilë÷ Yorùbá?

2. Ta ni olórí ÷bí ní ilë÷ Yorùbá?

3. Kí ni i«ê olórí ÷bí nínú ÷bí àti ní ìlú?

4. Kí ni mælêbí jê fún ìdàgbàsókè ìlú?

5. Kí ni ìtumöæ mælêbí?

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 127 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 7 Túmö àwæn örö wönyí ni èdèe Yorùbá. Provide the meanings of the following words in Yorùbá Language.

1. olórí

2. Ìpàdé

3. gbôdö

4. ojú«e

5. baálé ilé

Örö àdásæ (Monologue) Àbíkê ñ sörö nìpa ÷bíi rë fún Arábìnrin Fáladé, olùkôæ rë. Àbíkê is talking about her family to Mrs. Fáladé, her teacher. ¿bíì mi (My Family)

¿bíì mi ni ÷bí Adédìran À ñ gbé ní ìlú Ìbàdàn ní àdúgbò Ìyágànkú. Bàbá àti ìyáà mi bí æmæ mêrin. Àkôbí wæn ñ jê Adéolú. Æmæ ædún méjìlélôgbön ni wôn. Apòògùn sì ni wôn pëlú. Wôn ní ìyàwó. Orùkæ ìyàwóo wæn ni Gbémi. Wôn bí æmæ méjì, Doyin àti Yétúndé. Ækùnrin ni Doyin. Doyín jê æmæ ædún mêrin. Yétúndé sì jê æmæ ædún méjì. Æmæ kejì tí bàbáà àti màmáà mi bí ni Bímpé. Bímpé jê æmæ ægbön ædún. Dókítà ni wôn, «ùgbôn wôn kò ì tí ì fê ækæ. ¿ni tí ó tëlé Bímpé ni Jídé. Æmæ ædún mêrìndínlôgbön ni wôn. Agb÷jôrò ni wôn. Wôn «ësë bí æmæ kan tí orúkæ rë ñ jê Rónkê. Rónkê jê æmæ o«ù mêta. Èmi ni àbígbëyìn nínú ÷bíì mi. Orùkæö mi ni Àbíkê. Mo jê æmæ ædún méjìlélógún. Mo wà ní Yunifásítì ti ìlú Ìbàdàn. Mo ñ kô nípa ëkô ì«ègùn.

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 128 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 8 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí. Respond to the following questions.

1. Kí ni orúkæ ÷ni tí ó ñ sörö? 2. Kí ni i«ê tí Bímpé ñ «e? 3. Ipò wo ni Adéolú wà nínú ÷bí yìí? 4. Kí ni orúkæ àdúgbò àwæn Àbíkê? 5. Kí ni orúkæ ìyàwó Adéolú? 6. Ta ni wôn bí tëlé Bímpé? 7. Æmæ ædún mélòó ni Jídé? 8. Kí ni orúkæ àwæn æmæ Adéolú? 9. Kí ni orúkæ ilé-ìwé gíga Àbíkê? 10. Kí ni orúkæ ÷bí yìí?

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 129 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 9 Parí àwæn örö wönyí. Complete the following based on the monologue.

Bí àp÷÷r÷:

Æmæ ædún méjìlélógún ni = Àbíkê

1. Apòògùn ni =

2. Ìyàwó Adéolú ni =

3. Doyin àti Yétúndé ni =

4. Æmæ kejìi bàbáà àti màmáà mi ni =

5. Æmæ ædún mêrin ni =

6. Æmæ ædún méjì ni =

7. Æmæ ægbön ædún ni =

8. Dókítà ni =

9. Ó ñ kô nípa ëkô ì«ègùn =

10. Æmæ æ«ù mêta ni =

11. Àbígbëyìn ni =

12. Agb÷jêrò ni =

13. Æmæ ædún mêrìndínlôgbön ni =

14. Æmæ Yunifásítì ni =

15. Ó ñ sörö nìpa ÷bíi rë =

Örö àdásæ (Monologue) ¿bí Akínwálé

Orúkæ mi ni Lælá. Orúkæ bàbáà mi ni Fêmi. Orúkæ màmáà mi ni Æláníkëê. Mo ní abúrò mêta. Orúkæ wæn ni Jídé, Báyö àti Bùnmi. Jídé àti Báyö ni àwæn abúrò mi ækùnrin, Bùnmi sì ni àbúrò mi obìnrín. Jídé ni æmæ kejì. Báyö ni æmæ k÷ta. Bunmi ni àbúrò mi àbígbëyìn. À ñ gbé ní ìlú Èkó. Mo fêrànan gbogbo àwæn ÷bíì mi gan-an ni.

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 130 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 10 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences. 1. Kí ni orúkæ ÷bíi Lælá?

2. Kí ni orúkææ bàbáa Jídé?

3. Ta ni Báyö?

4. Kí ni orúkæ àwæn àbúròo Lælá?

5. Ta ni Æláníkëê ?

6. Kí ni orúkæ ëgbônæn Lælá?

7. Ta ni Bùnmi?

8. Æmæ mélòó ni ó wà nínú ÷bí Akínwálé?

BunmiBayoJideLola

OlanikeeFemi

Baba ati Mama¿bí Akínwálé

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 131 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 11 Mú èyí tí ó bá tönà nínú àwæn ìdáhùn wönyí. Circle the correct answer. 1. Orúkæ bàbáa Lælá ni? a. Gbénga b. Fêmi c. Báyö d. »eun

2. Kí ni orúkæ àbúròo Bàyô? a. Lælá b. Bùnmi c. Kêmi d. Jídé

3. Æmæ mélòó ni Æláníkëê bí? a. Æmæ mêta b. Æmæ márùnún c. Æmæ kan d. Æmæ mêrin

4. Ëgbôn mélòó ni Bùnmi ní? a. Méjì b. Mêta c. Mêfà d. Mêrin

5. Ìlú wo ni ÷bí Akínwálé ñ gbé? a. Ìbàdàn b. Abêòkúta c. Èkó d. Ilé-Ifë

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 132 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 12 Túmö àwæn örö wönyí ni èdèe Yorùbá. Provide the meanings of the following words in Yorùbá language. 1. My brother-in-law 2. Her mother-in-law 3. His niece 4. Your nephew 5. My first cousin 6. Our uncle 7. Your aunt 8. My grandfather 9. Their great grandfather 10. Her grandmother

I«ê »í«e 13 So àwæn tí ó bara mu ni öwô A àti öwô B papö. Match the words in column A with those in column B.

A B

¿bí Younger sibling

Bàbá Older sibling

Màmá Grandmother

Bàbáa bàbá Grandfather

Màmáa màmá Mother

Ëgbôn Father

Àbúrò Family

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 133 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 14 So àwæn tí ó bara mu ni öwô A àti öwô B papö. Match the words in column A with those in column B.

A B

Ìkúnlë Respect

Ìdöbálë Culture

Àpônlé Compound

À«à Kneeling down

Agbolé Prostration

I«ê »í«e 15 Ya àwòrán ÷bíì r÷. Tí o bá «e é «e, ya àwòrán yìí títí dé ìran k÷ta. Draw a picture of your family, if possible a three- generation family tree.

1. Generation

2. Generation

3. Generation

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 134 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 16 Mú fôtò ÷bíì r÷ wá sí kíláàsì. Fi fôtò ÷bíì r÷ han örêë r÷, jê kí örêë r÷ gbìyànjú bóyá ó lè sæ nípa àwæn ÷bíì r÷ fún ÷. Bring a picture of your family to class. Show it to your partner in class, and let your partner guess who the members of your family are.

I«ê »í«e 17 Ní méjì méjì. ( In pairs) Nínúu kíláàsì, láláìsí fôtò, «e àpèjúwe ÷bíì r÷ fún örêë r÷, kí örêë r÷ náà sì «e àpèjúwe ÷bíi rë fún ìwæ náà. ¿ kæ ohun tí ÷ sæ fún ara yín sílë. In pairs, without pictures, let each student describe his or her family to his or her partner. Each of you should write down what the other person said.

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 135 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Lesson 4 - Ëkô K÷rin:

Describing people

Àbúròò mi ækùnrin lágbára My younger brother is strong

Örêë mi sanra My friend is fat

Mo kúrú I am short

Tádé ga Tádé is tall

Ëgbônön mi tínínrín My older sibling is skinny

Bàbáà mi kúrú My father is short

Örêë mi tóbi My friend is big

Kò kúrú kò ga S/he is neither tall nor short

Ènìyàn dúdú a black person

Ènìyàn pupa a light-skinned person

Ènìyàn funfun a white person

Abíælá nìyí. Ó sanra. Kò ga. Ò«ì«ê ni.

Sëìndè nìyí. Ó tínínrín. Ó ga. Ó yöl÷.

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 136 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Kúnlé nìyí. Ó tóbi. Ó lágbára.

Akínkanjú ènìyàn ni.

Títí nìyí. Kò kúrú. Kò ga.

Gerunds are formed from adjectival verbs. Some examples of adjectival verbs include ga (tall), sanra (fat) and tóbi (big). ga gíga sanra sísanra tóbi títóbi However, some adjectival verbs do not follow the above structure. Some examples include: kéré kékeré small kúrú kúkúrú short burú búburú wicked, mean

Gerunds can be used to describe people. They follow their nouns. For example: màmáà mi jê ènìyàn gíga my mother is a tall person OR ènìyàn sísanra ni bàbáà mi my father is a fat person

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 137 CC – 2012 The University of Texas at Austin

The prefixes oní-, al-, æl-, ÷l- (one who is ) can be added to the noun to describe people. For example: ægbôn ælôgbôn àánú aláàánú ìwàpëlê oníwàpëlê Example: màmáà mi jê ælôgbôn OR màmáà mi jê ælôgbôn ènìyàn OR ælôgbôn ènìyàn ni màmáà mi

Örö àdásæ (Monologue) Olú ñ «e àpèjúwe ÷bíi rë nínúu kíláàsì. Olú is describing his family in the classroom.

Bàbáà mi tínínrín, wôn sì dúdú. Màmáà mi sanra, wôn sì pupa. Wôn lêwà. Kì í «e pé bàbáà mi búrêwà o! Wôn jê ælôgbôn, aláàánú àti onírëlë. Wôn sì tún jê ènìyàn gíga. Màmáà mi jê oníwàpëlê. Wæn kì í «e onígbéraga. Wæn kò ga bíi bàbáà mi. Wæn kò sì kúrú púpö. Wôn jê ènìyàn rere. Wôn sì jê æmælúwàbí ènìyàn.

I«ê »í«e 1 Sæ lóòótô ni tàbí lóòótô kô fún àwæn gbólóhùn wönyí. State whether the following sentences are true or false.

Òótô ni Òótô kô

1. Bàbá Olú sanra. ☐ ☐

2. Màmá Olú ga. ☐ ☐

3. Bàbá Olú jê oníwàpëlê. ☐ ☐

4. Bàbá Olú kò búrêwà. ☐ ☐

5. Màmá Olú kò gbéraga. ☐ ☐

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 138 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 2 »e àpèjúwe àwæn ènìyàn wönyí. Describe the following people.

Bí àp÷÷r÷:

Britney Spears = Ó kúrú, ó kéré, kò gbéraga.

1. George H. W. Bush =

2. Miley Cyrus =

3. 50 Cent =

4. Barack Obama =

5. Michael Jackson =

6. Michael Phelps =

7. Bill Clinton =

8. Hillary Clinton =

9. Carrie Underwood =

10. Michelle Obama =

11. Kanye West =

12. Oprah Winfrey =

13. Will Smith =

14. Paula Abdul =

15. Simon Cowell =

16. Christina Aguilera =

17. Angelina Jolie =

18. Brad Pitt =

19. Jennifer Aniston =

20. Nelson Mandela =

21. Dolly Parton =

22. Percy Sledge =

23. Beyoncé Knowles =

24. King Sunny Ade =

25. Fela Anikulapo Kuti =

26. Jennifer Aniston =

27. Denzel Washington =

28. Dalai Lama =

29. Muhammed Ali =

30. Martin Luther King Jr. =