16
71 Chapter 3 - Orí K÷ta | MARK THE DATE OBJECTIVES: In this chapter you will learn: -How to count from 40 to 100 -How to expess the future -How to ask how much…, how many..., and what is the sum of? -How to identify the days of the week and months of the year.

Chapter 3 - Orí K÷ta | MARK THE DATEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch3.pdf · Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kejì (Lesson 2) COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 76 CC – 2012 The University

  • Upload
    dangnhu

  • View
    229

  • Download
    1

Embed Size (px)

Citation preview

Page 1: Chapter 3 - Orí K÷ta | MARK THE DATEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch3.pdf · Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kejì (Lesson 2) COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 76 CC – 2012 The University

71

Chapter 3 - Orí K÷ta | MARK THE DATE

OBJECTIVES:

In this chapter you will learn: -How to count from 40 to 100 -How to expess the future -How to ask how much…, how many..., and what is the sum of? -How to identify the days of the week and months of the year.

Page 2: Chapter 3 - Orí K÷ta | MARK THE DATEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch3.pdf · Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kejì (Lesson 2) COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 76 CC – 2012 The University

Orí K÷ta (Chapter 3) Àwæn örö (Vocabulary)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 72 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Àwæn örö (Vocabulary)

Nouns bàtà shoe

è«í last year

ìdúnta three years ago

ìbéèrè question

Ìdáhùn answer

Ìpínlë state

ìtàn story

koríko grass

òmìnira independence

orílë-èdè country

o«ù month

ædún year

æjô day

öla tomorrow

ælôpàá police officer

ötúnla day after tomorrow

panápaná fire station

Noun Phrases ìwée gírámàa Yorùbá Yorùbá grammar book

ædún márùnún sêyìn five years ago

æjô mêrin òní three days from now

æjô márùnún òní four days from now

æjô mêfà òní five days from now

æjô wo…? what/which day?

ædún tí ó kæjá last year

Verbs rà to buy

ni is

Adjective yìí this

Page 3: Chapter 3 - Orí K÷ta | MARK THE DATEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch3.pdf · Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kejì (Lesson 2) COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 76 CC – 2012 The University

Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 73 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Lesson 1 - Ëkô Kìíní:

Nôñbà (Numbers) continued

Nôñbà 40-100

0 òdo 10 ÷êwàá

20 ogún

30 ægbön

40 ogójì

41 oókànlélógójì

42 eéjìlélógójì

43 ÷êtàlélógójì

44 ÷êrìnlélógójì

45 aárùnúndínláàádôta

46 ÷êrìndínláàádôta

47 ÷êtàdínláàádôta

48 eéjìdínláàádôta

49 oókàndínláàádôta

50 àádôta

60 ægôta

70 àádôrin

80 ægôrin

90 àádôrùnún

100 ægôrùnún

Eélòó: How much

Eélòó is an interrogative form that means how much? However, in terms of solving problems such as addition, subtraction, multiplication, etc., we ask:

Eélòó ni? What is the sum of?

Bí àp÷÷r÷:

Ìbéèrè: Eélòó ni oókan àti oókan jê? Ìdáhùn: Oókan àti oókan jê eéjì.

Page 4: Chapter 3 - Orí K÷ta | MARK THE DATEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch3.pdf · Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kejì (Lesson 2) COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 76 CC – 2012 The University

Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 74 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 1 Kæ ìbéèrè àti ìdáhùn àwæn àròpö yìí sílë. Write down the questions and answers to the following.

1. 47 + 38 =

2. 39 + 54 =

3. 75 + 15 =

4. 69 + 19 =

5. 44 + 44 =

I«ê »í«e 2 Kæ àwæn ìdáhùn r÷ nìkan sílë. Write down your answers in words only.

Bí àp÷÷r÷:

100 - 39 = oókànlélôgôta.

1. 98 - 43 =

2. 100 - 58 =

3. 75 - 49 =

4. 50 - 25 =

5. 80 - 38 =

Page 5: Chapter 3 - Orí K÷ta | MARK THE DATEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch3.pdf · Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kejì (Lesson 2) COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 76 CC – 2012 The University

Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 75 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 3 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences.

Bí àp÷÷r÷:

Ìbéèrè: Eélòó ni o ra ìwéè r÷?

Ìdáhùn: Náírà mêrin ni mo ra ìwéè mi.

1. Eélòó ni o ra ìwée gírámàa Yorùbáà r÷?

2. Eélòó ni o ra àpò ìwéè r÷?

3. Eélòó ni o ra bàtàà r÷?

4. Eélòó ni o ra pêñsùlù r÷?

5. Eélòó ni o ra pêënìì r÷?

Page 6: Chapter 3 - Orí K÷ta | MARK THE DATEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch3.pdf · Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kejì (Lesson 2) COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 76 CC – 2012 The University

Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 76 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Lesson 2 - Ëkô Kejì:

Future Tense Máa

‘Máa’ is a future tense marker that can be used with both emphatic and regular pronouns. Below, emphatic and regular pronouns can be used interchangeably.

For example:

Èmí máa læ /Mo máa læ I will go

Ìwô máa læ /O máa læ You will go

Òún máa læ /Ó máa læ He/She/It will go

Àwá máa læ /A máa læ We will go

Ëyín máa læ /¿ máa læ You all (or honorific singular) will go

Àwôn máa læ /Wôn máa læ They will go

Emphatic Pronoun + Máa + Negation

Èmí máa læ Èmi kò nì í læ

Ìwô máa læ Ìwæ kò nì í læ

Òún máa læ Òun kò nì í læ

Àwá máa læ Àwa kò nì í læ

Ëyín máa læ Ëyin kò nì í læ

Àwôn máa læ Àwæn kò nì í læ

Regular Pronoun + Máa + Negation

Mo máa læ N kò nì í læ

O máa læ O kò nì í læ

Ó máa læ Kò nì í læ

A máa læ A kò nì í læ

¿ máa læ ¿ kò nì í læ

Wôn máa læ Wæn kò nì í læ

Page 7: Chapter 3 - Orí K÷ta | MARK THE DATEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch3.pdf · Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kejì (Lesson 2) COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 76 CC – 2012 The University

Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 77 CC – 2012 The University of Texas at Austin

The following also indicate future tense

Mà á læ I will go

Wà á læ You will go

Á á læ He/She/It will go

À á læ We will go

Ë ê læ You all will go

Wôn á læ They will go

Máa + Yorùbá Calendar

Ìsöröõgbèsì (Dialogue)

Ösë tí ó ñ bö (Next Week)

Bàbá Adé: Bàbá Ælá, «é wà á bámi læ sí oko ní ösë tí ó ñ bö?

Bàbá Ælá: Rárá o, nítorí pé mo máa læ sí ödö àbúròò mi obìnrin tí ara rë kò yá. Tí mo bá dé ibë, mà á ba læ sí oko láti mú i«u, ilá, tòmátò, ëgúsí, ata rodo, tàtàsé àti ëgê wá sílé. Tí mo bá dé láti oko, mà á ba se oúnj÷. Lêyìn náà, mà á ní láti bá a fæ«æ, læta, kí n sì bá a gé igi. Mà á ba læ gba oogùn lôdöæ apòògùn. Mà á tôjú àbúròò mi dáradára. Mà á dúró tì í títí di alê. Mà á wá padà sí iléè mi.

Bàbá Adé: Ó dára o. Mà á sì læ sí oko láti hú koríko. Tí mo bá «e tán, mà á padà wá sílé.

Bàbá Ælá: Bóyá ti ara àbúròò mi obìnrin bá yá tán a má a jæ læ. Jê kí á læ ìsöæ Màmáa Títí.

Bàbá Adé: Ìy÷n á dára púpö.

Page 8: Chapter 3 - Orí K÷ta | MARK THE DATEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch3.pdf · Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kejì (Lesson 2) COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 76 CC – 2012 The University

Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 78 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 1 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences. 1. Ta ni ó ñ læ sí ödö àbúròo rë? 2. Tí Bàbá Ælá bá dé ibë, kí ni ó máa «e? 3. Kí ni Bàbá Adé àti Bàbá Ælá máa «e nígbà tí ara àbúròo Bàbá Ælá bá yá tán? 4. Kí ni ìdìi rë tí Bàbá Ælá fi máa tôjú àbúròo rë dáradára? 5. Ta ni Bàbá Adé?

I«ê »í«e 2 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences. 1. Kí ni o máa «e ní ösë tí ó mbö? 2. Kí ni o máa «e ní àárö öla? 3. Kí ni o máa «e ní ìparí ëkôö r÷ ní yunifásítì? 4. Kí ni o máa «e ní æjô àbámêta ? 5. Kí ni o máa «e ní æjôæ ìsinmi tí ó ḿbö?

Page 9: Chapter 3 - Orí K÷ta | MARK THE DATEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch3.pdf · Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kejì (Lesson 2) COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 76 CC – 2012 The University

Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 79 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Lesson 3 - Ëkô K÷ta

The Yorùbá Calendar (Days of the Week)

Days of the Week Æjô nínú ösë

Sunday: Æjô Àìkú day of not dying (day of rest)

Monday: Æjô Ajé day of commerce

Tuesday: Æjô Ì«êgun day of victory

Wednesday: Æjôrú day of confusion

Thursday: Æjôbö day of sacrifice

Friday: Æjô ¿tì day of impossibility

Saturday: Æjô Àbámêta day of three resolutions

However, many Yorùbá people substitute the following borrowings below for the traditional days of the week above:

Sunday: Æjôæ Sônñdè / Æjô ö«ë (Æjôösinmi)

Monday: Æjôæ Môñdè

Tuesday: Æjôæ Túsìdeè

Wednesday: Æjôæ Wêsìdeè

Thursday: Æjôæ Tôsìdeè

Friday: Æjôæ Fúráìdeè

Saturday: Æjôæ Sátidé

Yorùbá people also refer to Thursday as Æjô Àlàmísì, and Friday as Æjôæ Jímôö.

Page 10: Chapter 3 - Orí K÷ta | MARK THE DATEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch3.pdf · Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kejì (Lesson 2) COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 76 CC – 2012 The University

Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 80 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Örö àdásæ (Monologue)

Orúkæ mi ni Wálé. Mo jê æmæ bíbí ìlú Ìbàdàn láti ìpínlë Öyô ní orílë-èdè Nàìjíríà. Tí ó bá di æjô k÷sàn-án, o«ù kækànlá ædún tí ó ñ bö ni màá pé æmæ ædún môkàndínlôgbön. Gêgê bí ìtàn tí mo gbô, torí bí ômædé kò bá gbô ìtàn, yóò gbô àrôbá torí pé àrôbá ni bàbá ìtàn. Mo gbô pé æjô ì«êgun ni æjô tí àwæn òbíì mi bí mi. Èyí máa ñ jê kí inúù mi dùn fún æjô-ìbíì mi tí ó bá bô sí æjô ì«êgun. Nípa ti àwö, kí n má purô, mo fêràn àwö «ùgbôn n kò fêràn àwö pupa àti yêlò rárá rárá. Gbogbo ohun tí ÷nu ñ j÷ pátá ni mo fêràn.

I«ê »í«e 1 Sæ 'bêë ni ' tàbí 'bêë kô' fún àwæn gbólóhùn wönyí. State whether the following sentences are true or false.

Òótô ni Òótô kô

1. 1. Wálé fêràn oúnj÷. ☐ ☐

2. 2. Æmæ ìlú Öyô ni Wálé. ☐ ☐

3 3. Æmæ ædún méjìdínlógún ni Wálé báyìí. ☐ ☐

4 4. Æjô àbámêta ni wôn bí Wálé. ☐ ☐

1. 5. Gbogbo àwö ni Wálé fêràn. ☐ ☐

I«ê »í«e 2 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences.

1. Tí Wálé bá «e æjô-ìbíi rë ní æjô-ì«êgun ní ædún yìí, æjô wo ni ó máa «e é ní ædún tí ó ñ bö? 2. »àlàyé irú ènìyàn tí Wálé jê. 3. Irú àwæn oúnj÷ wo ni Wálé fêràn? 4. Õjê ìwæ rò pé Wálé lè «e ìrìn-àjò læ sí ilë òkèèrè? 5. Kí ni ó máa ñ mú inúu Wálé dùn?

Page 11: Chapter 3 - Orí K÷ta | MARK THE DATEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch3.pdf · Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kejì (Lesson 2) COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 76 CC – 2012 The University

Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 81 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 3 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences.

1. Æjô wo ni æjô kìíní o«ù k÷ta ædún yìí? _________________________________________________________ 2. Æjô wo ni æjô kejìdínlógún o«ù k÷rin ædún yìí? _________________________________________________________ 3. Æjô wo ni æjô kækàndínlógún o«ù k÷fà ædún yìí? _________________________________________________________ 4. Æjô wo ni æjô kejìlá o«ù k÷jæ ædún yìí? _________________________________________________________ 5. Æjô wo ni æjô k÷tàlèlógún o«ù kejìlá ædún yìí? _________________________________________________________

Page 12: Chapter 3 - Orí K÷ta | MARK THE DATEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch3.pdf · Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kejì (Lesson 2) COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 76 CC – 2012 The University

Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 82 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Lesson 4 - Ëkô K÷rin:

The Yorùbá Calendar Kàlêñdà Yorùbá (Months of the Year)

O«ù nínú Ædún Months of the Year

O«ù kìíní ædún (»êrê) first month of the year January

O«ù kejì ædún (Èrèlé) second month of the year February

O«ù k÷ta ædún (¿rênà) third month of the year March

O«ù k÷rin ædún (Igbe) fourth month of the year April

O«ù karùnún ædún (Èbìbí) fifth month of the year May

O«ù k÷fà ædún (Òkudù) sixth month of the year June

O«ù keje ædún (Ag÷mæ) seventh month of the year July

O«ù k÷jæ ædún (Ògún) eighth month of the year August

O«ù k÷sànán ædún (Öw÷rë) ninth month of the year September

O«ù k÷wàá ædún (Öwàrà) tenth month of the year October

O«ù kækànlá ædún (Belú) eleventh month of the year November

O«ù kejìlá ædún (Æpê) twelfth month of the year December

Page 13: Chapter 3 - Orí K÷ta | MARK THE DATEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch3.pdf · Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kejì (Lesson 2) COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 76 CC – 2012 The University

Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 83 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 1 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí. Answer the following questions.

Bí àp÷÷r÷:

O«ù wo ni o«ù k÷ta ædún? O«ù ÷rênà (march)

1. O«ù wo ni o«ù kejì ædún?

_________________________________________________________ 2. O«ù wo ni o«ù kejìlá ædún? _________________________________________________________ 3. O«ù wo ni o«ù keje ædún? _________________________________________________________ 4. O«ù wo ni o«ù karùnún ædún? _________________________________________________________ 5. O«ù wo ni o«ù kækànlá ædún?

_________________________________________________________

I«ê »í«e 2 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyìí Answer the following questions. 1. O«ù wo ni à ñ «e ædúnun Kérésìmesì? _________________________________________________________ 2. O«ù wo ni à ñ «e ædúnun ìdúpê (Thanksgiving) ní ædún yìí? _________________________________________________________ 3. O«ù wo ni à ñ «e ædún tuntun? _________________________________________________________ 4. O«ù wo ni æjæ ìbíì r÷? _________________________________________________________ 5. O«ù wo ni æjæ ìbíi bàbáà r÷?

_________________________________________________________

Page 14: Chapter 3 - Orí K÷ta | MARK THE DATEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch3.pdf · Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kejì (Lesson 2) COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 76 CC – 2012 The University

Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 84 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 3 So àwæn tí ó bara mu ni öwô A àti öwô B papö. Match the words in column A with those in column B.

A B

9th month o«ù keje

7th month o«ù k÷fà

6th month o«ù k÷ta

3rd month o«ù k÷sànán

1st month o«ù k÷wàá

8th month o«ù kìíní

10th month o«ù k÷jæ

12th month o«ù kejì

11th month o«ù kækànlá

2nd month o«ù kejìlá

I«ê »í«e 4 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí. Answer the following questions.

Bí àp÷÷r÷:

8/12 = December 8 = Æjô k÷jæ o«ù kejìlá ædún

1. 16/ 2 =

2. 21/11 =

3. 17/ 9 =

4. 21/ 6 =

5. 30/ 4 =

Page 15: Chapter 3 - Orí K÷ta | MARK THE DATEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch3.pdf · Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kejì (Lesson 2) COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 76 CC – 2012 The University

Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 85 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 5 Parí àwæn örö wönyí: Complete the following:

Bí àp÷÷r÷:

o«ù mêta = ösë méjìlá.

1. ösë kan = æjô

2. o«ù kan = ösë

3. ædún kan = o«ù

4. o«ù méjì = ösë

5. ösë mêta = æjô

Page 16: Chapter 3 - Orí K÷ta | MARK THE DATEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch3.pdf · Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô Kejì (Lesson 2) COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 76 CC – 2012 The University

Orí K÷ta (Chapter 3) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 86 CC – 2012 The University of Texas at Austin