22
COERLL - Yorúbà Yémi CC – 2011 The University of Texas at Austin 259 Chapter 11 - Orí Kækànlá | NICE STYLE! OBJECTIVES: In this chapter you will learn: - About different types of clothing - About seasonal clothings - The use of the verbs fi_ lé / fi_ kô, wö, dé/gë, wé, ró - Further use of interrogatives - Current trends in fashion

Chapter 11 - Orí Kækànlá | NICE STYLE! - COERLLcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch11.pdfChapter 11 - Orí Kækànlá | NICE STYLE! OBJECTIVES: In this chapter you will learn: - About

  • Upload
    lemien

  • View
    221

  • Download
    1

Embed Size (px)

Citation preview

COERLL - Yorúbà Yémi CC – 2011 The University of Texas at Austin 259

Chapter 11 - Orí Kækànlá | NICE STYLE!

OBJECTIVES:

In this chapter you will learn: - About different types of clothing - About seasonal clothings - The use of the verbs fi_ lé / fi_ kô, wö, dé/gë, wé, ró - Further use of interrogatives - Current trends in fashion

Orí Kækànlá (Chapter 11) Àwæn örö (Vocabulary)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 260 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Àwæn örö (Vocabulary)

Nouns àpônlé respect

à«à culture

a«æ clothe

bùbá a shirt or a blouse (Yorùbá style)

búláòsì blouse (western style)

èjìká shoulder

fìlà hat

gèlè a scarflike headgear

gínnì guinea

ìborùn shawl

ìbæsë sock(s)

ìböwô glove(s)

ìgbéyàwó wedding

ìmúra an outfit

ìró a wrap-around cloth/ wrapper

ìsìnkú funeral

ìsæmælórúkæ naming ceremony

iyì honor

jákêëtì jacket

jíìnsì jeans

kæjúsôkæ ‘to face one’s husband’

kóòtù coat

obìnrin female

oko farm

æjà market

ækùnrin male

æyê harmattan

pàtàkì important

«òkòtò a pair of pants

súwêtà sweater

tí«÷ëtì t-shirt

síkêëtì skirt

y÷tí earring(s)

Orí Kækànlá (Chapter 11) Àwæn örö (Vocabulary)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 261 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Noun Phrases àsìkòo fôölù fall season

àkókò köökan each season

àsìkò mêrin ötöötö four different seasons

a«æ ëërùn clothes for the dry season

a«æ òde formal wear

a«æ ojoojúmô informal clothing

a«æ òjò clothes for the rainy season

a«æ òkè woven material

a«æ léèsì lace material

a«æ têêrê strip of cloth

àwæn ælôlá rich people

ëwùu kòlápá sleeveless clothing

ibi i«ê/ ibi«ê workplace

ìgbà ooru hot weather

ilë òkèèrè foreign countries

orílë-èdèe Àmêríkà USA

látàrí ooru as a result of heat

«òkòtò péñpé short pants/shorts

Verbs dé/gë to wear, e.g. a hat

gbayì popular

gbôdö must

jê to be

nípæn thick

ró to wrap around

wé to tie, e. g. a headgear

wæ to wear ( clothes, shoes, or other apparel)

wôn to be expensive

Verb Phrases di ìgbàdí wrap-around waist

fún … láàyè allow

irú… wo? what type?

Orí Kækànlá (Chapter 11) Àwæn örö (Vocabulary)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 262 CC – 2012 The University of Texas at Austin

kò pé not complete

pa òwe say proverbially

yàtö sí different from

Adjectives orí«irí«i different types

Conjunction tàbí or

Preposit ional phrase ní önà mìíràn in another way

Orí Kækànlá (Chapter 11) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 263 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Lesson 1 - Ëkô Kìíní:

A«æ wíwö ní i lë÷ Yorùbá (Types of Clothing)

Orí«ì a«æ méjì pàtàkì ni àwæn Yorùbá máa ñ wö: a«æ ojoojúmô àti a«æ ìmúròde. A«æ ojoojúmô tí wæn máa ñ wö ni a«æ àõkàrá àti a«æ àdìr÷. A«æ òde tí wôn máa ñ wö ni a«æ léèsì àti a«æ òkè. Fún a«æ ojoojúmô, àwæn obìnrin máa ñ ró ìró, wôn máa ñ wæ bùbá, wôn sì tún máa ñ wé gèlè. Fún a«æ òde àwæn obìnrin máa ñ ró ìróo léèsì, wôn sì máa ñ wæ bùbáa rë. Bákan náà ni fún a«æ òkè. Wôn lè fi ìborùn lé tàbí kí wôn fi kô èjìká. Öpölæpö àwæn ödômæbìnrin ni wôn máa ñ so ìborùnun wæn mô ìdí lode-òní. Fún a«æ ìmúròde àwæn ækùnrin máa ñ wæ «òkòtòo léèsi tàbí a«æ òkè. Wæn máa ñ wæ bùbáa léèsì tàbí a«æ òkè. Wôn sì máa ñ dé fìlà. Gèlè wíwé jê ara àwæn à«à ìmúra tí ó gbayì láàárín àwæn obìnrin. Orí«irí«i gèlè ni ó wà. Wæn máa ñ pe gèlè kan ní “kæjúsôkæ.” Awæn Yorùbá máa ñ «e àpônlé tí ó pö fún obìnrin tí ó bá mæ gèlèe wé dáradára. Nítorí ìdí èyí ni àwæn Yorùbá fi máa ñ pá a ní òwe pé : “Gèlè òdùn bí i ká mö ô wé, ká mö ô wé kò tó kó y÷ni.” Gèlè máa ñ gbé ÷wà obìnrin yæ jáde gan-an ni. Àwæn ènìyàn ti sæ ìborùn tó jê a«æ têêrê tí wôn máa ñ fi lé èjìkà di ìgbàdí tí wôn máa ñ ró mô ara ìró. Orí«irí«i ìró ni ó wà. Ìró a«æ òkè jê èyí tí ó wôn jù. Nínú àwæn a«æ òkè, “sányán” àti “àlàárì” jê méjì nínúu èyí tí àwæn ælôlá àti ènìyàn pàtàkì máa ñ wö jù. Àwæn obìnrin tún máa ñ wæ “àrán.” A«æ àrán jê ökàn lára a«æ tí wôn máa ñ kó wá láti ilë òkèèrè ní ayé àtijô. Ní ilë÷ Yorùbá, bí àwæn obìnrin «e máa ñ wæ a«ô yàtö sí bí àwæn ækùnrin «e máa ñ wö tiwæn. Fún a«æ ìmúròde, lêhìn tí àwæn ækùnrin bá wæ «òkòtò àti bùbá, wôn á wæ agbádá léwæn. Ní ilë÷ Yorùbá, fìlà dídé «e pàtàkì fún àwæn ækùnrin. Ní öpölæpö ìgbá, apá òsì ni àwæn ækùnrin máa ñ sáábà g÷ fìlà sí. Ìmúra ækùnrin kò pé tí kòbá dé fìlà, àti wí pé, iyì tí ó wà nínú ìmúra ni wí pé kí ækùnrin dé fìlà. Orí«irí«i fìlá méjì ni ó gbayì púpö láàárin àwæn ækùnrin: fìlá "ìkòrí" àti fìlà “a-betí-ajá”. Orí«irí«i ni a«æ ti wôn fi ñ «e àwæn fìlà yìí: a«æ àõkàrá, a«æ àdìr÷, asæ dàmáàsìkì àti a«æ òkè. Fìlà gígë jê önà tí àwæn ækùnrin máa ñ gbà dé fìlà. À«à ìbílë÷ Yorùbá fún ækùnrin àti obìnrin ní àyè bí wôn «e lè múra. Obìnrin kò gbædö wæ «òkòtò, bêë ni ækùnrin kò gbædö ró ìró. Bákan náà, obìnrin nìkan ni ó ní ëtô láti wæ y÷tí. Fún ìdí èyí, à«à kí obìnrin máa wæ «òkòtò tàbí kí ækùnrin máa wæ y÷tí ní òde-òní jê à«à tí ó wá láti ilë òkèèrè.

Orí Kækànlá (Chapter 11) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 264 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 1 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê.

Answer the following questions in complete sentences.

1. Orí«i ì«örí a«æ mélòó ni àwæn Yorùbá ní? Dárúkæ wæn. 2. Irú àwæn a«æ wo ni àwæn Yorùbá máa ñ wö læ sí àwæn òde pàtàkì? 3. Báwo ni àwæn obìnrin Yorùbá «e máa ñ múra gêgê bí à«à ìbílë÷ Yorùbá? 4. Báwo ni àwæn ödômæbìnrin «e ñ lo ìborùn ní ayé òde-òní? 5. Irú orí«i ìró mélòó ni àwæn obìnrin máa ñ ró ni ilê÷ Yorùbá? Èwo ni ó wôn jù nínúu wæn? 6. Kí ni ìyàtö tí ó wà láàárín a«æ obìnrin àti ti ækùnrin ní ilë÷ Yorùbá? 7. Báwo ni àwæn ækùnrin Yorùbá «e gbôdö múra ni ilë÷ Yorùbá? 8. Apá ibo ni wôn sáábà máa ñ g÷ fìlà sí ní ilë÷ Yorùbá? 9. Kí ni àwæn ohun tí à«à a«æ wíwö ní ilë÷ Yorùbá kò fàyè gbà fún ækùnrin àti obìnrin láti

wö? 10. Kí ni èròo r÷ nípa à«à a«æ wíwö ní ilë÷ Yorùbá?

I«ê »í«e 2 Sæ bêë ni tàbí bêë kô fún àwæn gbólóhùn wönyìí State whether the following sentences are true or false

BÊË NI BÊË KÔ

1. Ì«örí a«æ mêta pàtàkì ni àwæn Yorùbá máa ñ wö ☐ ☐

2. A«æ ìmúròde tí awôn Yorùbá máa ñ wö ni a«æ àõkàrá àti a«æ àdìr÷

☐ ☐

3. Àwæn ækùnrin Yorùbá máa ñ wö bùbá àti «òkòtò ☐ ☐

4. Ní ilë÷ Yorùbá bákan náà ní a«æ ti àwæn ækùnrin àti æbìnrin.

☐ ☐

5. Obìnrin le wö «òkòtò ní ilë÷ Yorùbá ☐ ☐

Orí Kækànlá (Chapter 11) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 265 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 3 Parí àwæn gbólóhùn wönyí. Complete the following sentences.

1. Àwæn Yorùbá máa ñ wæ irú orí«i a«æ a. mêta b. m÷rin c. mêfà d. méjì

2. Nínúu à«àa Yorùbá ni kí æbìnrin lo______________. a. fìlà b. y÷tí c. «òkòtò d. agbádá

3. Àwæn ækùnrin Yorùbá máa ñ wæ ______________. a. fìlà b. kaba c. ìró d. agbádá

4. ______________«e pàtàkì nínú ìmúra àwæn ækùnrin Yorùbá. a. fìlà b. «òkòtò c. bùbá d. agbádá

5. ______________jê ökan lára a«æ ilë òkèèrè. a. a«æ òkè b. àdìr÷ c. a«æ àrán d. a«æ léèsì

Orí Kækànlá (Chapter 11) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 266 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 4 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí. Answer the following questions.

Irú a«æ wo ni àwæn Yorùbá máa ñ wö læ sí...?

1. æjà 2. ibi ìgbéyàwó 3. ibi ìsæmælórúkæ 4. ibi«ê 5. «ôö«ì / ilé-ìsinmi

I«ê »í«e 5 Nibo ni àwæn Yorùbá máa ñ wæ àwæn a«æ wönyí læ? Where do Yorùbá people wear these clothes to? 1. a«æ àdìr÷ 2. a«æ àõkàrá 3. a«æ léèsì 4. a«æ òkè 5. a«æ dàmáásìkì

Orí Kækànlá (Chapter 11) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 267 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Lesson 2 - Ëkô Kejì:

More Interrogatives

The following models illustrate the use of interrogatives such as: ‘kí ni’, ‘ta ni’, ‘nígbà wo’, ‘níbo’, ‘kí ló’, ‘báwo’ and ‘èwo’.

Who?

Q. Ta ni ó wà nínúu yàrá nàá? Who is inside the room?

R. Ìdáhùn: Kò sí ÷nì kankan nínúu yàrá nàá. Nobody is inside the room.

Q. Ìwée ta ni yìí? Whose book is this?

R. Ìwée Títí ni. It’s Títí’s book.

Q. Ta ni o fêràn ni ilé-ìwéè r÷? Who do you like in your school?

R. Mo fêrànan olùkôö mi. I like my teacher.

What?

Q. Kí ni ò ñ «e nísìnyí? What are you doing now?

R. Mò ñ ka ìwéè mi. I’m reading my book.

Q. Kí nì yìí? What is this?

R. Aáyán ñlá ni. Yéèpà! It’s a big cockroach. Wow!

Q. Kí ní ò ñ kà? What are you reading?

R. Mò ñ ka ìwèé »óyínká ni. I’m reading a book by »óyínká .

When?

Q. Nígbà wo ni æjô-ìbíì r÷? When is your birthday?

R. Öla ni. It’s tomorrow.

Where?

Q. Níbo ni ò ñ gbé? Where do you live?

R. Ní ëgbê æjà ni mò ñ gbé I live near the market.

Orí Kækànlá (Chapter 11) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 268 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Why?

Q. Kí ló dé tí ò ñ sunkún? Why are you crying?

R. N kò rí àpò owóò mi. I cannot find my wallet.

How?

Q. Báwo ni? How are you?

R. Dáadáa ni? I’m fine.

Q. Báwo ni o «e máa dé æjà? How will you get to the market?

R. Mà á gun këkêë mi ni. I will ride my bicycle.

Which one?

Q. Èwo nínú àwæn ödômædékùnrin y÷n ni o fêràn?

Which of those boys do you like?

R. Túndé ni mo fêràn. I like Túndé.

Q. Títì wo ló læ sí «ôö«ì? Which street leads to the church?

R. Títi æwô òsì ni. The street on the left.

I«ê »í«e 1 Fi à«ebéèrè tó bá y÷ dí àwæn àlàfo wönyí Fill in the spaces below with the appropriate interrogative.

____________ nínú ëyin akêköô ni æjô ìbíi rë jê öla? ____________ ni o ti máa «e ædún

ìbíi yìí? ____________ ni o «e máa má «e é? ____________ o fê «e æjô ìbíi yìí pëlú?

____________ ni ædún ìbíi yìí máa parí?

I«ê »í«e 2 Lo àwæn à«ebéèrè wönyí látì «ëdáa gbólóhùn. Use the following interrogatives to form sentences. 1. Kí ni? 2. Ta ni? 3. Níbo ni? 4. Kí lódé? 5. Báwo ni?

Orí Kækànlá (Chapter 11) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 269 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Lesson 3 - Ëkô K÷ta:

Verbs f i_lé/f i_ kô, wö, dé, wé, ró, gë

The following verbs are used with clothing: fi_lé/ fi_ kô, wö, dé, wé, ró, gë. For instance: Àwæn ækùnrin máa n wæ bùbá àti agbádá. Wôn máa n dé fìlà. Àwæn obìnrin máa n wæ bùbá, ró ìró, wé gèlè. Wôn sì máa n fi ìborùn kô / lé èjìká The verb “gë” can be used for both “gèlè” and “fìlà”.

Bí àp÷÷r÷:

Ækùnrin ñ g÷ fìlà.

Obìnrin ñ g÷ gèlè.

However, dé and wé are general terms while gë denotes a particular style of headgear or hat. Below are the different types of clothes for men and women and the manner in which they are worn in Yorùbáland.

A«æ okùnrin (Male clothes) A«æ obìnrin (Female clothes)

bùbáa léèsì, «òkòtòo léèsì, agbádáa léèsì, fìlà a«æ òkè tàbí fìlàa dàmáásìkì

bùbáa léèsì, ìróo léèsì, gèlèe léèsì tàbí gèlèe dàmáásìkì

bùbá àõkàrá, «òkòtò àõkàrá, agbádá àõkàrá

bùbá àõkàrá, ìró àõkàrá, gèlè àõkàrá

bùbá a«æ òkè, «òkòtò a«æ òkè, agbádá a«æ òkè, fìlà a«æ òkè

bùbá àõkàrá, ìró àõkàrá, gèlè gidi

dàñ«íkí, «òkòtò, fìlà bùbá a«æ òkè, ìró a«æ òkè, gèlè a«æ òkè

tàbí

bùbáa léèsì, ìró a«æ òkè, gèlè a«æ òkè

tàbí

bùbáa léèsì, ìróo léèsì, gèlè a«æ òkè

Orí Kækànlá (Chapter 11) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 270 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Ayé ñ læ à ñ tö ô (Fashion Trends)

Bí ó tilë jê pé à«àa Yorùbá ni pé kí obìnrin wæ bùbá, ró ìró, kí wôn sì tún wé gèlè, àti pé kí okùnrin wæ bùbá, wæ «òkòtò, kí wôn tún dé fìlà, orí«i a«æ mìírán tún wà tí wôn le wö. Ní òde-òní, orí«irí«i àrà ni àwæn ènìyàn ñ fi a«æ àõkàrá, léèsì, àdìr÷ àtí gínnì dá. Bí ìgbà «e ñ yí ni à«à a«æ wíwö náà ñ yí láàrín àwæn Yorùbá. Kódà ölàjú ti mú kí à«à a«æ wíwö àwæn Yorùbá di ohun tí àwæn ènìyàn láti ìlú òkèèrè ñ wárí fún. Nítorí pé öpölæpö àwæn Yorùbá ni wôn jê oní«ê æba, ó «òró láti máa wæ bùbá àti «òkòtò, tàbí kì wôn máa ró ìró tàbí wé gèlè læ sí ibi i«ê òòjôæ wæn. Ìdí nìyí tó fi jê pé orí«irí«i àrà ni wôn ñ fi àõkàrá rán: bí i síkêëtì, bùláòsì, súùtù àti kaba. À«à fífi àwæn a«æ bíi àõkàrá, léèsì, gínnì ati àdìr÷ dá àrà lórí«irí«i ti gbilë ní ilë÷ Yorùbá tó fi jê pé púpö nínú àwæn télö (arán«æ) ni ó ti di olówó àti gbajúmö nípa bê ë.

Nítorí pé wôn ti ñ fi àwæn a«æ yìí dá orí«irí«i àrà, àwæn ènìyàn bíi olùkô, öjögbôn, oníròyìn àti aköwé lè wæ àõkàráa súùtù, tàbí àdìr÷ búláòsì àtí síkêëtì læ sí ibí i«ê. »ùgbôn àwæn i«ê kan wà tí a kò lè wæ àwæn irú a«æ báyìí læ bí ó ti wù kí ó mæ. Àwæn irú i«ê báyìí ni i«ê÷ agb÷jôrò, i«ê àkàtáõtì àti bêë bêë læ. Dandan ni fún àwæn agb÷jôrò àti ò«ì«ê ilé ìfowópamô láti wæ súùtù òyìnbó àti táì læ sí ibi i«ê÷ wæn. Fún ìdí èyí, à«à a«æ wíwö láàárín àwæn Yorùbá ti yí wænú araa wæn.

Bó ti lë jê pé ìró, bùbá, gèlè àti ìborùn j÷ a«æ ìbílë tí obìnrin Yorùbá máa ñ wö, tí bùbá, «òkòtò àtí fìlà sì jê a«æ ìbílë fún àwæn ækùnrin Yorùbá, wôn tún máa ñ wæ àwæn a«æ òyìnbó gêgê bí i«ê tí wôn bá ñ «e bá «e rí. Nítorí ìdí èyí ni àwæn Yorùbá «e máa ñ pa òwe pé, “bí ÷y÷ bá «e fò ní a «e ñ sôkòo rë”. Èyí túmö sí pé bí ìgbà bá «e rí ni a «e ñ lò ó. Bí àwæn ækùnrin Yorùbá bá wæ súùtù òyìnbó læ síbi i«ê wæn, wæn á de táì, de bêlíìtì sí «òkòtòo wæn. Wæn a wæ ìbösë àti bàtà. Wæn á dì bíi aköwé. Àwæn obìnrin Yorùbá pàápàá tó ñ «i«ê ìjæba náà á wæ súùtù tàbí kí wôn wæ síkêëti àti búláòsì. Wôn á sì tún wæ bàtà òyìnbó. Gbogbo wæn á máa t÷lë “ko-ko-kà”. Lóòótô ayé ti dayé ölàjú. Gbogbo nõkan ló sì ti yí padà.

Orí Kækànlá (Chapter 11) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 271 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 1 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí. Answer the following questions.

1. Báwo ni àwæn ækùnrin àtí obìnrin Yorùbá «e máa ñ wæ«æ tàbí múra gêgê bí à«àa Yorùbá?

2. Kí ló dé tí àwæn ará ìlú òkèèrè fi ñ wárí fún à«à asæ wíwö láàrín àwæn Yorùbá lóde-òní? 3. Kí ni ìdí rê tí wôn fi ñ fi àwæn a«æ ìbílë bíi àõkàrá dá orí«irí«i àrà ní òde-òní? 4. Yàtö si bùbá, ìró àtí «òkòtò, kí ni a tún le fi àõkárá, léèsì tàbí àdìr÷ rán ? 5. Kí ni nõkan pàtàkì tí fifi àwæn a«æ ìbílë dá orí«irí«i àrà ti «e fún à«àa Yorùbá? 6. Kí ni ìdí rë ti àwæn ènìyàn bíi agb÷jôrò àti òsì«ê ilé ìfowópamô kò «e lè wæ àwæn a«æ

ìbílë læ síbi i«ê? 7. Kí ni èrò r÷ nípa bí ó ti jê dandan fún àwæn agb÷jôrò láti wæ súùtù òyìnbó læ síbi i«ê? 8. Kí ló dé tí àwæn Yorùbá fi máa ñ pa òwe pé “bí ÷y÷ «e fò ni a «e ñ sökòo rë?” 9. Sæ ìyàtö tó wà láàárín a«æ i«ê obìnrin àtí ækùnrin tí ó ñ «isê ìjæba. 10. Õjê àõfààní kankan wà nínú ölàjú tí àwæn Yorùbá gbà láàyè nínú à«à a«æ wíwöæ wæn?

I«ê »í«e 2 So àwæn tí ó bara mu ni öwô A àti öwô B papö. Match the words in column A with those in column B.

A B

gèlè wæ

fìlà wé

ìró fi_ lé /fi_kô èjìkàá

«òkòtò dé

ìborùn ró

Orí Kækànlá (Chapter 11) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 272 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 3 Wá àwæn örö wönyí

Look for these words in the puzzle below. Pay attention to the tones! a«æ‚ bùbá‚ fì là‚ gèlè‚ ìborùn‚ ìró‚ ìsæmælórúkæ‚ iyì ‚ æjà‚ «òkòtò

i r o u « ò k ò t ò i b o r a

u a t m è f æ o g b á d e b s

a s a b o ì g j s e a d è i o

b ù b á i l è r à d l o d b p

i l è k u à ì r ó f a e j o o

b í b í l a r í l è p a g r l

i j a ì s æ m æ l ó r ú k u o

l o g è b a l u m a f b ú n n

a d è p a o i y i n i u i j i

b u l á g u r è p è t b á y á

u g è í b a d ù f i l a g b ì

g b á j u m á p n í g b a d u

ú ì s æ m æ l ó r ú k æ è b è

i k e j p o p o l á a j a g b

a « æ a j s o k o t o g b e j

Orí Kækànlá (Chapter 11) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 273 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 4 Parí àwæn gbólóhùn wönyí ní ëkúnrêrê.

Complete the following sentences.

1. ______________kì í «e ökan lára àwæn a«æ obìnrin láwùjæ Yorùbá. a. Bùbá b. Ìró c. Gèlè d. Fìlà

2. Àwæn ækùnrin Yorùbá kí ì wæ ________________ a. bùbá b. agbádá c. búláòsì d. súùtù

3. Àwæn ækùnrin Yorùbá máa ñ wæ ______________. a. gèlè b. ìró c. ìborùn d. bùbá

4. ________________ kì í «e a«æ ìbílê÷ Yorùbá. a. A«æ àõkárá b. A«æ léèsì c. A«æ àdìr÷ d. A«æ súùtù

5. ________________ kì í «e a«æ tí àwæn ènìyàn ñ wö læ sí ibi i«ê ní òde-òní. a. Súùtù òyìnbó b. Síkêëti c. Búláòsì d. Bùbá

I«ê »í«e 5 State the equivalence of this proverb in English and explain its relevance in today’s activities. “bí ÷y÷ bá «e fò ní a «e ñ sôkòo rë”

Orí Kækànlá (Chapter 11) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 274 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Ì lëkë títò ní i lë÷ Yorùbá

Àwæn Yorùbá jê akíkanjú nínú isê æwô «í«e. Wæn kì í «e öl÷ tàbí ìmêlê. Wôn jê ènìyàn tí ó têpá mô«ê. Nínú àwæn i«ê æwô tí wôn máa ñ «e ni a«æ òkè híhun, ÷ní apërë híhun, a«æ pípa láró, apëërë híhun, ÷yìn fífö, ìlëkë sínsín àti bêë bêë læ. Àwæn ènìyàn pàtàkì bíi ìdílé Æba, ìdílé oyè àti ìdílé ælà ní wôn máa ñ wæ ìlëkë ní ayé àtijô. Ìlëkë tí ó sí wôpö nígbà náà ni iyùn. Iyùn jê ìlëkë olówó iyebíye. »ùgbôn ní òde-òní, nõkan tí yàtö. Gbogbo ènìyàn tí o bá wù ni ó lè lo ìlëkë. Kò sì pæn dandan pé kí ó jê iyùn. Idí ni pé orí«irí«i ìlëkë ní ó ti wà ní òde-òní nítorí ìmö-ëræ tí ó ñ gbilë jê kí a lè rí ìlëkë oníke dípò ìlëkë gidi. Àp÷÷r÷ àwæn ìl÷kë gidi ni ojú ológbò, ìlëkë fífô, kírísítààlì. Orí«irí«i nõkan ní a lè to ìlëkë fún. A lè to ìlëkë láti fi «e ëgbà ærùn, ëgbà æwô, ëgbà ÷së, bàtà ÷së, àpò ìmúròde àti bêë bêë læ. Onírúurú ni àwö àwæn ìlëkë tí ó wà ní òde-òní – pupa, funfun, dúdú, àti búlúù.

I«ê »í«e 6 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê.

Answer the following questions in complete sentences.

1. Irú ènìyàn wo ni àwæn Yorùbá? 2. Dárúkæ i«ê æwô tí àwæn Yorùbá máa ñ «e. 3. Irú àwæn ènìyàn wo ni wôn ñ lo ìlëkë ní ilë÷ Yorùbá? 4. Kí ni ó fà á tí ìlëkë oníke fi wà ní ayé òde-òní? 5. Dárúkæ irú àwæn àwö ìlëkë tí wôn wà ní ayé òde-òní.

I«ê »í«e 7 Kæ ìtumö àwæn örö wönyí sílë ní èdèe Yorùbá. Write the meanings of these words in Yorùbá.

1. Akínkanjú 2. Iyùn 3. Ìdílé oyè 4. Ölàjú 5. À«à

Orí Kækànlá (Chapter 11) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 275 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 8 Parí àwæn gbólóhùn wönyí. Complete the following sentences.

Àwæn Yorùbá jê ènìyàn ____________ . Wæn kì í «e ____________. Lára àwæn i«ê tí wôn

máa ñ «e ni ____________ . Ní ayé àtijô‚ àwæn ìdílé ____________ ni wôn máa ñ wæ ìlëkë

têlë «ùgbôn ní òde-òní‚ gbogbo ènìyàn ló lè lo ìlëkë nítorí ____________ tí ó ti gba ayé

kan. ____________ jê ìlëkë tí ó pàtàkì láwùjæ Yorùbá.

Orí Kækànlá (Chapter 11) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 276 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Lesson 4 - Ëkô K÷rin:

Seasonal Clothings

Ærí«irí«i a«æ ni àwæn ènìyàn máa ñ wæ ní àsìkòo fôölù, wíñtà, sípíríõgì, sômà àti àkókò æyê.

Bí àp÷÷r÷:

Ní fôölù Ní wíñtà

- súwêtà tí kò nípæn - kóòtù wíñtà

- jákêëtì - súwêtà

- jíìnsì - ìböwô

- tí«÷ëtì - ìbæsë

Ní sípíríngì Ní sômà

-súwêtà tí ó nípæn -«ôöti

- jákêëti -tí«÷ëtì

- jíìnsì - síñgílêëtì

- búláòsì

A«æ òjò ní ëërùn

Àwæn Yorùbá ní ìgbàgbô pé kò y÷ kí ènìyàn máa wæ a«æ òjò ní ëërùn nítorí pé ìgbà ara ni à á búra‚ ÷nìkan kì í bú »àngó ní ëërùn. Orí«irí«i a«æ ni àwæn ènìyàn máa ñ wö ní àkókò köökan. A«æ òjò yàtö sí ti ërùn, bêë ti æyê kò fi ara jæ ti ìgbà ooru. Bí ó «e wà ní ilë÷ Yorùbá náà ni ó wà ní gbogbo ibi tí ó fi dé orílë-èdèe Àmêríkà. Àsìkò mêrin ötöötö ni a lè rí ní orílë-èdè Àmêríkà. Àsìkòo wíñtà‚ sípíríõgì‚ sômà àti fôölù. Ní gbogbo àwæn àsìkò yìí‚ orí«irí«i a«æ ni àwæn ènìyàn máa ñ wö. Ní àsìkòo wíñtà‚ àwæn ènìyàn máa ñ wæ àwæn a«æ bíi kóòtù‚ súwêtà‚ ìböwô àti ìbæsë. Àsìkò sípíríõgì‚ ni àwæn ènìyàn máa ñ wæ súwêtà tí ò nípæn‚ jákêëtì àti jíìnsì. Ní àsìkòo sômà, àwæn a«æ tí kò nípæn rárá bí i ëwùu kòlápá‚ «òkòtò péñpé‚ síkêëtì àti búláòsì ni àwæn ènìyàn máa ñ wö látàrí ooru tí ó máa ñ mú ni àsìkò yìí. Tí ó bá wá di àsìkòo fôölù‚ nítorí pé òtútù ti máa ñ fê bërë láti mú. Àwæn ènìyàn máa ñ wæ àwæn a«æ bí i súwêtà tí kò nípæn, jákêëtì‚ jíìnsì àti tís÷ëtì.

Orí Kækànlá (Chapter 11) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 277 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 1 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê.

Answer the following questions in complete sentences.

1. Kí ni ó dé tí ènìyàn kò fi lè wæ a«æ òjò ní ëërùn? 2. »àlàyé ohun tí ó máa ñ «÷lë ní àsìkòo wíñtà. 3. Irú a«æ wo ni àwæn ènìyàn máa ñ wö ní àsìkòo sípíríõgì? 4. »é lóòótô ni pé a«æ ti kò nípæn ni àwæn ènìyàn máa ñ wö ní àsìkòo fôölù? »e àlàyé. 5. Tí ó bá di àsìkòo sômà‚ irú a«æ wo ni ìwô fêràn láti máa wö?

Orí Kækànlá (Chapter 11) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 278 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 2 Parí àwæn gbólóhùn wönyí. Complete the following sentences.

1. Àwæn Yorùbá máa ñ bú »àngó ní_______________? a. àsìkòo fôölù b. àsìkòo wíñtà c. àsìkò ëërùn d. àsìkò òjò

2. Irú àsìkò mélòó ni a le rí ní orílë-èdè Àmêríkà? a. mêta b. méjì c. mêfà d. mêrin

3. Àsìkò mélòó ni a le rí ní orílë-èdè Nàìjíríà? a. mêta b. méjì c. mêfà d. mêrin

4. Ní àsìkò sômà‚ àwæn ènìyàn máa ñ wæ____________? a. kóòtù b. súwêtà c. ìböwô d. «òkòtò péñpé

5. _________________ jê a«æ tí àwæn ènìyàn máa ñ wö jù ní àsìkòo wíñtà? a. Jákêëtì b. Jíìnsì c. Tí«÷ëtì. d. Kóòtù

Orí Kækànlá (Chapter 11) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 279 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 3 Sæ bêë ni tàbí bêë kô fún àwæn gbólóhùn wönyìí State whether the following sentences are true or false

BÊË NI BÊË KÔ

1. Àwæn Yorùbá fêràn a«æ òjò ní ëërùn. ☐ ☐

2. Kò sí ìyàtö láàrin àsìkò òjò àti àsìkò ërùn ní orílë-èdè Nàìjíríà.

☐ ☐

3. Òtútù máa ñ pö ní àsìkòo fôölù ju àsìkòo wíñtà læ. ☐ ☐

4. Tí«÷ëtì ni àwæn ará orílë-èdè Àmêríkà máa ñ wö ní àsìkòo wíñtà.

☐ ☐

5. Àsìkò méjì péré ni a lè rí ní orílë-èdè Àmêríkà. ☐ ☐

The Interrogative ‘Nígbà wo?’, and ‘Nígbà tí ’

Nígbà wo is an interrogative marker that denotes when. Nígbà tí can be used as a response to nígbà wo.

For instance: Nígbà wo ni wà á læ sí ilé? When are you going home? Mà á læ sí ilé nígbà tí mo bá parí ìwé tí mò ñ kà. I will go home when I finish with the book I'm reading. Nígbà wo ni ilé-ëkô gíga Yunifásítì tiTexas When does the school year begin at ní Austin ñ bërë lôdún? the University of Texas at Austin? Ní o«ù k÷jæ ædún ni. It’s in the eighth month of the year.

Orí Kækànlá (Chapter 11) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 280 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 4 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí. Answer the following questions.

1. Nígbà wo ni àsìkò òjò ni ìlúù r÷? 2. Nígbà wo ni o máa ñ j÷un àárö? 3. Nígbà wo ni bàbáa r÷ máa ñ ti ibi i«ê dé? 4. Nígbà wo ni wà á læ sí æjà? 5. Nígbà wo ni o máa ñ sùn? 6. Nígbà wo ni o máa ñ wæ a«æ òtútù? 7. Nígbà wo ni àsìkò ërùn ni ìlúù r÷? 8. Irú a«æ wo lo fêràn láti wö nígbàa sômà? 9. Irú a«æ wo lo fêràn láti wö nígbà òjò? 10. Nígbà wo ni àsìkò òtútù ni ìlúù r÷?

I«ê »í«e 5 O yà‚ ó kàn ë. Lo ‘nígbà wo’ láti bèèrè lôwô örêë r÷ ohun tí ó máa ñ «e ní ösë. Má «e jê kí ó ju ìbéèrè márùn-ún læ. It’s now your turn. Use ‘nígbà wo’ to ask your friend some questions. Do not ask more than five questions.

I«ê »í«e 6 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí. Answer the following questions.

1. Nígbà wo ni àwæn Yorùbá máa ñ wæ súwêtà? 2. Nígbà wo ni àwæn æmæ ìlú Àmêríkà máa ñ wæ kóòtù àti ìböwô? 3. »é ènìyàn lè wæ «ôöti ní àkókòo wíñtà? 4. Nígbà wo ni àwæn æmæ ìlú Àmêríkà máa ñ wæ a«æ péñpé? 5. Nígbà wo ni ìwæ máa ñ fêràn láti wæ jákêëtì?