ETO ISUNA AWA ARA WA TI IPINLE ONDO F’ODUN 2018
ILE ISE TI N BOJUTO IDAGBASOKE ORO AJE ATI
ETO ISUNA NI IPINLE ONDO
1
ITUMO AWON EDE TI A LO FUN IWE ETO ISUNA YI LEDE GEESI
BUDGET: Eyi je iwoye afojusun iye ti ijoba n petepero lati na ni saa kan tabi laarin
odun kan
Recurrent expenditure: Owo ti ijoba ya soto lati fi sanwo osu fun awon osise ijoba,
yiyanju ele lori gbese, owo ti o wa fun isakoso pelu iseto kalokabo awon ile ise ijoba
elekajeka
Capital expenditure: Eyi je owo ti ijoba n na lori ise idagbasoke, bii eto eko ise ilu bi
atunse awon ile iwe, ile iwosan, atunse popono ati beebee lo.
Roll over fund: owo ti a ko na ni odun to koja, ti a tun fi si eto isuna odun yii.
Personnel costs: Eyi je ara owo ti a ya soto fun gbigbo bukaata owo osu awon osise
ati awon ti o ti fehinti lenu ise ijoba
Budget support: Iye owo ti ijoba apapo fi se iranlowo tabi atileyin ijoba ipinle, fun
sisan owo osu ati owo ifeyinti fun awon osise ijoba ipinle lati ba kere koja ami
Overhead costs: O je owo ti ijoba fi n bojuto idojuko ti o ba de lojiji
Debt stock: Eyi ni apapo gbese ti ijoba je labele tabi seyin odi niwon saa kan
Debt Servicing: Eyi ni owo ti a ya soto ninu isuna fun yiyanju ele ori ojulowo gbese
abele ati tile okeere
Revenue: Apapo owo ti ijoba n pa wole laaarin saa kan
Consolidated revenue fund charge: Ara owo ti ijoba n lo fun sisan owo osu awon
oselu ti o dipo akoso mu, owo ifehinti ati owo osu osise fehinti, owo ajemonu fun
awon gomina ana ati awon igbakeji won.
Cash-backed capital expenditure: Eyi je owo ti o wa lowo fun amuse awon ojulowo
ise
Statutory allocation: Eyi ni ipin owo ti ipinle n gba lati odo ijoba apapo losoosu, eyi ti
ajo FAAC n se akoso pinpin re.
Utilised capital expenditure: Eyi ni apapo owo ise ti ile ise kookan, titi kan elekajeka
ile ise maa san sita fun ise ti awon kongilakito tabi elomiran ba se.
IPSAS: ifojusun alakale isuna ile ise ijoba jakejado agbaye (International Public
Sector Accounting Standards)
IMPPR: Alakale kari ile iseto isuna l’awon ile ise
JMPPR: Ipese ise labe akoso eto ogbin, iseto idokowo ati eka dida ile ise sile
2
M- Mimu idagbasoke l’opo yanturu deba ipese awon ohun ko see mani pelu bi bojuto
won daradara
P- Ipese eko ti o muna doko ati imo gbogbonise fun idagbasoke
P- Ipese eto ilera ti o see yangan pelu wiwa ni arowoto
R- Idagbasoke igberiko
ALAKALE ISUNA 2018
- Alakale eto isuna alabode (MTEF) ati igbese sise n tele.
- Iwe isaju ipe ti o ko jade lojo kejo osu kejo, odun 2017
- Iwe ipe aseoba to jade lojo keta osu kokanla 2017
- Ipe saaju ipade alabesekele waye ni ojo kerindinlogun si ojo ikejidinlogun osu
kokanla, 2017
- Ipade igbimo alabesekele waye lati ojo kerin titi di ojo ikarundinlogun osu
kejila odun 2017
- Tite pepe iwe isuna sile asofin ipinle Ondo, ojo kejilelogun osu kejila, 2017
- Siso iwe isuna d’ofin, waye ni ojo ketadinlogbon osu kinni, 2018
- Ifowosi iwe isuna, waye ni ojo kefa osu keji, 2018
- Abojuto, isoduwon ati isagbeyewo eto isuna
- Sise agbeyewo ibi a ba ise de ni osu merin merin
BI OWO TI SE MAA WOLE: Owo ti ijoba n reti fun odun 2018 yii je bilionu
mokanlelogosan, irinwo le merinlelogun milionu, ojilelegbaametadinlogbon ati orin
lelugba ole meta naira, (N181,424,540,283.00)
A ONA AMUSE ISE:
i. Ipin lati odo ijoba apapo - N25, 352,256,000.00
ii. Owo apawole labele - 20,923,646,783.00
iii. Ipin Faati (VAT) - 12,000,000,000.00
iv. Anaku isuna odun ti o koja - 13,500,000,000.00
v. Owo lori alumoni - 5,536,592,000.00
vi. Ere lori iseto karakata sile okeere - 6,126,000,000.00
vii. Owo ti a gba pada lori ona ijoba apapo ti ijoba ipinle se atunse won
- 10,000,000,000.00
viii. Alekun owo gbese Paris Club - 13,156,000,000.00
ix. Alekun owo epo bentirolu - 3,683,000,000.00
x. Owo iranlowo - 6,279,046,084.00
Aropo gbogbogbo - 126,556,540,867.00
3
B EYAWO:
i. Owo atileyin eto isuna - 10,925,000.000.00
ii. Eyawo alabode/abele - 31,194,564,633.00
iii. Eyawo lati odo awon ajo onidagbasoke ti
ile okeere - 12,748,434,783.00
Akojopo - 54,867,999,416.00
Aropo A + B - 181,424,540,283.00
Bi owo ti se maa wole ni isori isori f’odun 2018
Apapo isuna je : N181, 424,540,283.00
4
Ibi ti owo le gbawole yato si yiya
Apapo iye ti isuan iba je ti a ko ba yawo Kankan ni N126, 556,540,867.00
Apapo owoya: N54, 867,999,416.00
ATILEYIN ISUNA , 10,925,000,000.00
ISETO EYAWO LABALE,
31,194,564,633.00
ATILEYIN LODO AJO MAJEO BAJE,
12,748,434,783.00
Nibo ni awon owo yiya ti a fe lo ti maa jeyo?
5
Independent Revenue: Je aropo iye ti a pa wole labele ni ipinle yii ti awon onigeesi n
pe ni “IGR”
Value Added Tax (VAT): Ni owo ori ti ijoba n gba lori iseto idunadura karakata nile
Naigiria.
19,000,000,000.00
15,398,700,000.00 14,764,363,121.11
20,923,646,783.00
2015 2016 2017 2018
Nai
raOWO APAWOLE LABELE
10,000,000,000.00
8,600,000,000.00
12,000,000,000.00 12,000,000,000.00
2015 2016 2017 2018
IPIN OWO FAATI
6
Exchange Gain: Ere ti a je lori igbokegbode oja pasiparo naira si dollar. Ko si iru
anfani owo bee saaju odun2017
Eya Owo ti ijoba ya soto fun eto ise idagbasoke
Wo oju ewe kinni fun ekun rere alaye lori isori yii.
-
7,305,000,000.00
6,126,000,000.00
2016 2017 2018
Nai
raERE ORI PASIPARO (State)
23,000,000,000.00
39,755,000,000.00
55,697,216,878.89 54,867,999,416.00
2015 2016 2017 2018
Nai
ra
EYAWO
5,000,000,000.00
14,967,000,000.00
6,200,000,000.00
13,500,000,000.00
2015 2016 2017 2018
OWO ISUNA ANAKU
7
Owo ori ajo ile ise, ti n wa epo pentirolu nile Naigiria. Ko si anfani owo yi saaju odun
2017
Owo ti oye ki ijoba apapo da pada lori atunse popona ti ipinle Ondo se.
Wo oju ewe kinnin fun ekunrere alaye.
6,644,000,000.00
3,683,000,000.00
2016 2017 2018
Nai
raOWO ORI ALEKU PENTIROLU
1,000,000,000.00
6,060,000,000.00
10,000,000,000.00
2015 2016 2017 2018
Nai
ra
OWO TI IJOBA IPINLE ONDO NA SORI POPONA IJOBA APAPO
68,000,000,000.00
41,000,000,000.00 44,020,000,000.00
40,888,848,000.00
2015 2016 2017 2018
Nai
ra
IPIN TIWA NINU OWO TI IJOBA APAPO N PIN FUN AWON IPINLE LATI OWO AJO FAAC
8
Sisan alekun gbese ti a n san pada lori paris club bere lati odun 2017.
Owo iranlowo ti a mo si granti kii se owo asanpada. Ebun niru owo bee je fun ijoba lati dawole akanse ise.
13,156,000,000.00 13,156,000,000.00
2015 2016 2017 2018
Nai
raIDAPADA ALEKUN OWO GBESE TI A SAN LORI EYAWO PARIS
CLUB
4,000,000,000.00
5,000,000,000.00
6,279,046,084.00
2015 2016 2017 2018
Nai
ra
OWO IRANLOWO ILE OKEERE ATI LABELE
9
NIBO NI A FE NA OWO TI A N RI YI LE LORI?
10
ISUNA NI ISORI-ISORI
Owo isuna ti a n reti ni 2018 ni a ya soto fun:
i. Sisan ojulowo gbese pada (Principal) - N13, 599,878,084.00
ii. Ipin ni Isori: OSOPADEC - 6,214,636,800.00 10% IGR to JAAC Account - 2,093,364,678.30 Aropo gbogbogbo - 8,308,001,478.30
iii. Owo isakoso eto ise ijoba - 78,587,675,486.07 iv. Owo ti a fe fi sise - 80,928,985,234.00
Eto isuna 2018 ti a fowosi yii je eyi ti owo ti ijoba maa pa wole kere si eyi ti o ma na
lo (Deficit Budget).
OJU OWO LORI SISAN GBESE PADA,
13,599,878,084.63
ISETO INAWO IGBADE GBA,
78,587,675,486.07
IPIN TI A N DA PADA, 8,308,001,478.30
INAWO LORI AKANSE ISE,
80,928,985,234.00
BAWO LATI SE FE NA OWO WONYI?
11
OWO IRANLOWO TI IJOBA N GBA
LATI ITA N 1,768,000,000.00
Kini nina re maa da le lori?
N793M
Ipese omi ero
N725M
Fun Awon Eto Eu Ati Unicef
I.E Abere ajesara HIV/AIDS
N150M
Pipese ebun eko ofe fun awon
omo bibi ipinle Ondo
N100M
Fun itoju awon igbooba ati ibojuto igi
gbingbin
12
N 1.29B
Igbega ati atunse awon ile iwe
alakobere
N2.6B
Ipese ounje fun omo ile iwe
N50M
Ebun eko ofe fun awon akeko ni
pinle Ondo
N600M
Owo atilehin fun awon lajolajo
OWO IRANLOWO LABELE N 4,511,046,084.00
Kini a maa na owo naa le lori?
13
OWO IRANLOWO LATI ODO AWON LAJOLAJO
N12, 748,434,783
NIBO NI OWO BEE NLO
N 1,768,000,000.00
N480M
Iseto ise iranra eniilowo
N3.050B
Ipese omi-ero
N3.0B
Atunse awon ona igberiko
N762.8M
Ironilagbara awon odo wa leka eto
ogbin
N900M
Eto ogbin FADAMA III project
N3.56B
Ipese ojulowo eto ilera jakejado
N1.0B
Abojuto ayika wa ati isele agbara omiyale
14
Ate inawo ijoba lori sisan owo osu awon osise ati owo ajemonu miiran.
Inawo igbadegba lori gbigbo bukata ise ati eto ijoba, kii se pe won n san taara
f’awon osise ijoba. Apere owo bee ni: Owo rira petirolu, diesel, owo ina eletiriki, owo
oko lati ibi kan lo ibo miiran abbl.
37,705,000,000.00 37,000,000,000.00
51,004,000,000.00
37,909,962,000.00
2015 2016 2017 2018
Nai
raIYE- OWOTI IJOBA FI N IBOJUTO AWON OSISE
3,916,100,000.00 3,730,963,000.00 3,975,985,000.00
4,489,289,500.00
2015 2016 2017 2018
Nai
ra
OWO ISAKOSO ETO ISE IJOBA
15
Awon akanse eto kii saba n waye bee losoosu, eekookan lo maa n waye. Apere ni
inawo lori sise olugbowo ere idaraya, ipese atileyin eto fawon obinrin, gbigbaradi sile
fun isuna olodoodun pelu awon eto miiran.
Owo giranti (grant) kii se eyi ti a n san pada. O je owo fun gbigbo bukata ise ati eto
ijoba. Apeere bee ni: owo iranlowo fun awon ile iwe giga ati abbl.
8,071,100,000.00
6,889,000,000.00
7,699,000,000.00
7,227,169,686.07
2015 2016 2017 2018
Nai
ra
ATILEYIN OWO FUN AWON EKA TABI AJO ILE ISE IJOBA
14,387,626,000.00 13,964,362,000.00
16,997,334,300.00 16,311,254,300.00
2015 2016 2017 2018
Nai
raAWON AKANSE ETO
16
Eyi ni owo ti ijoba n pese fun ile ise iwe iroyin Owena Press.
Wo oju ewe kinni fun alaye
Eyi ni owo ti ofin gbe leyin lati maa fun awon ajo to da duro funra won bii: Ajo
OSOPADEC, ajo ti o n bojuto awon ijoba ibile abbl.
200,000,000.00220,000,000.00
180,000,000.00 150,000,000.00
2015 2016 2017 2018
Nai
raOWO GIRANTI ATI EYAWO
12,423,124,000.00
7,390,000,000.00
15,302,880,700.00 12,500,000,000.00
2015 2016 2017 2018
Nai
ra
CONSOLIDATED REVENUE FUND CHARGES
0
8,374,000,000.00 8,308,001,478.30
2017 2018
Nai
ra
Statutory Tranfers
17
Akiyesi: A ti faye sile fun sisan ele ori igbese wonyi lati ara owo ti a fii nsan owo osu
awon oselu ti o dipo akoso ijoba mu, owo ifehinti ati owo ajemonu fun awon gonina
ana ati awon igbakeji won.
Inawo lori awon akanse ise je ara isuna lori ipin olodindi, lori ile ati lori awon dukia
miiran. O je owo ti ijoba n na lori awon ise bii kiko ile iwe, ipese ile iwosan, atunse
popona, ipese ohun elo leto abo abbl.
0
8,126,698,115.26
13,599,878,084.63
2017 2018
Nai
raSisan oju owo gbese (principal)
54,297,050,000.00 54,526,375,000.00
59,186,681,884.74
80,928,985,234.00
2015 2016 2017 2018
Nai
ra
owo ti ijoba n na awon ojulowo ise ati dukia
18
Owo isuna fun ise akanse ise ni 2018 je N80,928,985,234.00
Ipin IPSAS ni owo iyasoto fun awon eto ise idagbasoke
131,000,000,000.00 123,720,700,000.00
170,846,580,000.00181,424,540,283.00
2015 2016 2017 2018
Nai
raAropo eto isuna odun 2015 wo 2018
Iseto ise lawon ofiisi
Abojuto eto oro ajeLAW AND JUSTICE, 1,457,000,000.00
Iseto igbayegbadun
Ipin owo IPSAS si isori isori
19
Awon ise kookan ti a ya soto fun sise ni ipinle yii
N4.427B
Ipese omi ero
N3.2B
Sise atunse awon
ona
N9.583B
Ipin fun ajo UBEC ati
SUBEB
N670M
Eto gbogunti ise
asela
N2.0B
Agbekale ojuko itoju
arun jejere
N14.781B
Lila ati titun awon
ona se
N1.5B
Eto otun titun
N539M
Iseto ibudoko oju
omi
N4.202B
Ipese ounje ti n sara
lore fawon ile iwe
kookan ti a ya soto
N460M
Eto ise idagbasoke
igberiko
N1.635B
Iseto owo ise aje
ati igbeleke eto
idokowo
N662.5M
Gbingbin ojele
million meta koko
(cocoa)
N400M
Ina oni 33 KVA double circuit
power point
N1.2B
Owo ipin tiwa lori eto
akanse ise ti lajolajo
gbe owo kale fun
N900M
eto ogbin FADAMA
III
N4.0B
Kiko ibugbe tuntun
fun gomina ati
igbakeji re
20
Awon ise ti a fe seto eyawo okeere fun labele.
Awon eto ti a fe eyawo abele se.
150,000,000.00
725,000,000.00 793,000,000.00
100,000,000.00
SCHOLARSHIP AWARDS EU & UNICEF PROGRAMMES
PROVISION OF POTABLE WATER
FOREST PRESERVATION & REGENERATION
Nai
ra
Awon ise ti a fe gba eyawo le lori lati ile okeere
21
Pinpin isuna odun yii si isori marun ni ibamu si alakale ajo eleto isuna lagbaye.
Apapo isuna odun 2018: N181,424,540,283.00
Ipese isuna da lori alakale ijoba
Aropo awon eto miiran N12,429,489,000.00
ISETO ISE LAWON OFIISI,
34,820,296,722.10
ISETO ORI AJE, 73,882,940,997.55
OFIN ATI ETO IDAJO, 3,635,475,242.82
ETO IGBAYAGBADUN, 62,871,190,520.53
ISETO ELEKUNJEKUN, 6,214,636,800.00
IPESE ISUNA ODUN 2018 LABE ISORI ISORI
Job Creation through Agriculture,
Entrepreneurship and Industrialization, 9,215,785,000.00
Massive Infrastructural Development and
Maintenance, 26,193,160,000.00 Provision of Functional
Education and Technological …
Provision of Accessible and Qualitative Health Care and Socio Service
Delivery, 13,504,964,866.00
Rural Development and Community Extension
Services, 5,413,000,000.00
BUDGET ALLOCATION BASED ON JMPPR