10
Wake Keep Thursday 7th September, 2017 Programme

Madam Omotoso Wake keep programme - myeventmyalbum.commyeventmyalbum.com/wp-content/uploads/2017/09/Chief-Elizabeth... · Igba siso okuta nu, igba kiko o jo; Igba fun kikamora, igba

Embed Size (px)

Citation preview

Page 1: Madam Omotoso Wake keep programme - myeventmyalbum.commyeventmyalbum.com/wp-content/uploads/2017/09/Chief-Elizabeth... · Igba siso okuta nu, igba kiko o jo; Igba fun kikamora, igba

Wake Keep

Thursday 7th September, 2017

P r o g r a m m e

Page 2: Madam Omotoso Wake keep programme - myeventmyalbum.commyeventmyalbum.com/wp-content/uploads/2017/09/Chief-Elizabeth... · Igba siso okuta nu, igba kiko o jo; Igba fun kikamora, igba

CHIEF (MRS.) ELIZABETH DADA OMOTOSO JP. | (NEE ALLE)

ETO ISIN

1. Opening Prayer

2. Rosary Prayer

2.1 1st and 2nd Mystery

2.2 Hymn –Hark! Hark! Hark!

2.3 3rd and 4th mystery

2.4 Hymn – Ara e ma je ka gbagbe

2.5 5th Mystery

3. 1st Reading: Eccl. 3:1-11

4. Psalm

5. 2nd Reading: Phil. 4:1-9

6. Gospel – Mtt. 25:1-13

7. Homily

8. Prayer of the faithful

9. Offering – De wa lade

10. Special Rendition

a. NULGE Choir Ekiti State

b. CAN Choir Ekiti State

11. Individual thanksgiving

12. Announcement

13. Closing Prayer

ORDER OF SERVICE

1. Adura Ibere

2. Adura Rosario

2.1 Oro Ijinle kini ati keji

2.2 Orin – Hark! Hark! Hark!

2.3 Oro Ijinle keta ati kerin

2.4 Orin- Ara e ma je ka gbagbe

2.5 Oro ijinle karun

3. Eko Kini – Ekle. 3:1-11

4. Orin Dafidi

5. Eko Keji - Filipi 4:1-9

6. Ihinrere – Mtt. 25:1- 13

7. Iwaasu

8. Adura Onigbagbo

9. Ifitore – De wa lade

10. Orin Adako

a. Akorin NULGE

b. Akorin CAN

11. Idupe

12. Ikede

13. Adura Ipari

3

Page 3: Madam Omotoso Wake keep programme - myeventmyalbum.commyeventmyalbum.com/wp-content/uploads/2017/09/Chief-Elizabeth... · Igba siso okuta nu, igba kiko o jo; Igba fun kikamora, igba

CHIEF (MRS.) ELIZABETH DADA OMOTOSO JP. | (NEE ALLE)

EKO KIKA

1. EKO KINI Oro lati inu iwe Eklesiaste 3:1-11

Gbogbo ohun pelu asiko tire, ati akoko ti a n se ohun gbogbo labe orun; Igba fun bibi, igba fun kikuigba fun gbingbin Igba fun kika esoIgba fun wiwo, igba fun kiko Igba fun ekun, Igba fun erinIgba fun kikedun, Igba fun ijo Igba siso okuta nu, igba kiko o jo;Igba fun kikamora, igba titanuIgba fun wiwa, Igba fun siso nu; Igba fun pipamo Igba fun sisati Igba fun yiyanu, igba fun riranpoIgba fun didake, Igba fun sisoro; Igba fun ife, igba fun ikorira; Igba fun ogun, Igba fun alaafia. Kini ere eniyan lori opo re? Mo wo ise ti olorun gbe ka eniyan laya. Gbogbo ohun ti o n se ni o n bo si asiko re, sugbon bi o tile je ki eniyan mo gbogbo akoko, sibesibe a ko le mo ise olorun lati ibere de opin.Eyi ni oro Oluwa

Ijo: Ope ni fun Olorun

4

Page 4: Madam Omotoso Wake keep programme - myeventmyalbum.commyeventmyalbum.com/wp-content/uploads/2017/09/Chief-Elizabeth... · Igba siso okuta nu, igba kiko o jo; Igba fun kikamora, igba

CHIEF (MRS.) ELIZABETH DADA OMOTOSO JP. | (NEE ALLE)

2. ORIN DAFIDI PELU EGBEEgbe: Bi iwo ba kiyesi aisedede wa Oluwa taani yoo ye

I. Lati inu ibu wa ni emi ti kepe o, oluwa gbo ohun mi je ki eti re tesile si ohun ebe mi

II. Bi iwo, Oluwa ba kiyesi aisedeedee waoluwa ta ni yoo ye?Sugbon lodo re ni a ti n ri idariji Nitori naa ni a se n bola fun o

III. Nitori odo oluwa ni aanu waati idande irapada pipe oun ni yoo ra Israeli pada kuro ninu gbogbo ese re

EKO KEJIOro lati inu iwe Paulu si awon ara Filipi 4:1-9

Nitori naa, eyin ara mi olufe owon, ti mo n saaro, ayo mi ati ade ori mi, e duro sinsin bee ninu Oluwa eyin ayanfe mi. Mo n be Efodia bi mo ti n be Syntyke pe ki won maa gbe po pelu inu kan naa ninu Oluwa. Ati iwo naa, Sysygu, awe mi tooto, jwo ba mi da si oro won, nitori won ran mi lowo ninu ijakadi fun ihin rere, bakan naa ni Klementi ati awon alabase mi yoku, awon ti a ko oruko won sinu iwe iye. E maa yo ninu Oluwa laidekun. Mo tun wi pe e maa yo ki gbogbo eniyan inu rere yin. Oluwa ku si dede. E ma se se aniyan kankan, sugbon se ni ki e maa gbadura pelu ebe fun gbogbo aini yin, ki e si fi idupw mu ibeere yin wa si waju Olorun nigba naa ni alaafia olorun

5

Page 5: Madam Omotoso Wake keep programme - myeventmyalbum.commyeventmyalbum.com/wp-content/uploads/2017/09/Chief-Elizabeth... · Igba siso okuta nu, igba kiko o jo; Igba fun kikamora, igba

CHIEF (MRS.) ELIZABETH DADA OMOTOSO JP. | (NEE ALLE)

to re koja gbogbo imo lo yoo maa so okan ati ironu yin ninu Jesu Kristi.

Ni ikeyin, eyin ara, awon ohun to ye ki e maa gba ro ni yin: Gbogbo ohun ti o jemo otito, owo, ododo mimo, ife, iwa omoluabi, ati gbogbo ohun ti o dara fun iwa rere ati iyin omo eniyan, Ohun wonyii ni ki e maa gbe –yewo. Ohun ti e ti ko ti e ti gba ti e ti gbo lodo mi, ti e si ti ri lowo mi, awon ni ki e maa se. Nigba naa ni Olorun alaafia yoo maa ba yin gbe.Eyi ni oro Oluwa

Ijo: Ope ni fun Olorun

IKEDE IHINRERE Alleluia alleluiaDandan ni ki ara idibaje yii gbe ailebaje wo, ki ara iku yii gbe aiku woAlleluia.

IHIN REREIrohin ayo lati inu iwe mimo lati owo Matiu 25:1- 13

Ijoba orun dabi wundia mewaa ti won gbe atupa won lati lo pade oko iyawo. Marun – un ninu won je omugo, marun – un si je ologbon. Nigba ti awon omugo gbe atupa won, won ko mu epo dani pelu; Sugbon awon ologbon mu igo epo dani pelu atupa won. Bi oko iyawo ti pe gbogbo won toogbe won si sun. sugbon ni ogajan oru ni a gbo igbe kan wi pe: e wo oko iyawo! E wa pade re. Nigba naa ni gbogbo awon wundia dide lati tun atupa won se. Awon omugo so fun awon ologbon pe fun wa ni die ninu epo yin nitori atupa wa n ku lo sugbon awon ologbon; dahun pe ki o ma sai to fun wa ati fun yin ekuku lo ra ti yin lodo awon

6

Page 6: Madam Omotoso Wake keep programme - myeventmyalbum.commyeventmyalbum.com/wp-content/uploads/2017/09/Chief-Elizabeth... · Igba siso okuta nu, igba kiko o jo; Igba fun kikamora, igba

CHIEF (MRS.) ELIZABETH DADA OMOTOSO JP. | (NEE ALLE)

elepo. Nigba ti won si lo ra ni oko iyawo de awon to si ti mura sile ba a wole sibi ase igbeyawo a si ti leku.Leyin naa ni awon wundia yoku de bakan naa, ti won si so wipe Oluwa silekun fun wa. Sugbon o da won lohun pe: looto ni mo so fun yin emi ko mo yin, nitori naa ki e maa sona nitori eyin ko mo ojo naa tabi wakati naa. Eyi ni iyin rere Oluwa.

Ijo: Ope ni fun O Jesu.

HARK HARK MY SOUL

1. Hark, hark my soul angelic songs are swellingO’er earth’s green fieldsAnd ocean’s wave beat shore How sweet the truthThose blessed strains are telling Of what new life when sin shall be no more.

Chorus – Angels of Jesus angels of lightSinging to welcome the pilgrims of the night

2. Onward we go for still we hear them singing Come, weary souls, for Jesus bids you comeAnd through the dark, it’s echoes sweetly ringingThe music of the gospel leads us home

3. Far, far away like bells at evening pealingThe voice of Jesus sounds o’er land and seasAnd laden souls by thousand meekly Stealing kind shepherd turn their weary steps to thee

7

Page 7: Madam Omotoso Wake keep programme - myeventmyalbum.commyeventmyalbum.com/wp-content/uploads/2017/09/Chief-Elizabeth... · Igba siso okuta nu, igba kiko o jo; Igba fun kikamora, igba

CHIEF (MRS.) ELIZABETH DADA OMOTOSO JP. | (NEE ALLE)

4. Rest comes at lengthThough life be long and drearyThe day must downAnd dark some night be pastFaith’s journey’s end in welcome to the wearyAnd heaven the heart’s true homeWill come at last

5. Angel’s sing on your faithful watches keepingSing us sweet fragments of the songs aboveTill morning’s joy shall end the night of weepingAnd life’s long shadows break in cloudless love

ARA E MA JA KA GBAGBE

Egbe: Ara o ma: jeka gbagbe, pe aye loja orun nile wa,Ope ni oya ni, ikuni lati muwa loErin leni, ekun lolaAye loja orun nile wa

1. Nigba ti ab walayeNigba ti awa laye wa Ohun aye jo wa lojuBeni pe a ko ni ku titi

8

Page 8: Madam Omotoso Wake keep programme - myeventmyalbum.commyeventmyalbum.com/wp-content/uploads/2017/09/Chief-Elizabeth... · Igba siso okuta nu, igba kiko o jo; Igba fun kikamora, igba

CHIEF (MRS.) ELIZABETH DADA OMOTOSO JP. | (NEE ALLE)

2. Owo atola asan niIpo atoro ofo niKi a maje ki won fo walojuKi a ba leri ohun ti se t’orun

3. Ojiji firi nile aye je Arinrin ajo ni gbogbo wa oEje ka feyi se irantiKa ma se huwa igberaga

4. Igbose niku ke k’ a ronuIbaji omode tabi agbaIba so; oba tabi ijoyeIku nilati muwon sa

5. Boya lowuro, boya ale,Boya ajin meta tabosan ganganIku ade were boje aleEjeka tele gbaradi

DE WA LADEChorus: De wa lade Olorun igbala wa (2ce)

Ade ogo torun rere mafi dun wa oDe wa lade re o baba de wa lade rereAde e wura torun mafi dun wa o

1. Oba oke to da wa si awa juba reMetalokan Baba Mimo awa yin ooEleti gbaroye o fere fun wa majeA rin lowoOfo nile re loke

9

Page 9: Madam Omotoso Wake keep programme - myeventmyalbum.commyeventmyalbum.com/wp-content/uploads/2017/09/Chief-Elizabeth... · Igba siso okuta nu, igba kiko o jo; Igba fun kikamora, igba

CHIEF (MRS.) ELIZABETH DADA OMOTOSO JP. | (NEE ALLE)

2. Oba oke to da wa si awa wole o Dawalare Baba Mimo anbe ooo nileAlayo lorunFabo fun wa maje Karin lowo ofoNi lere Jesu

3. Olugbala wa ba wag be ka tun je tireSure fun wa Baba Mimo kama pofoAlagbara ti ko lopin pesere oMaje Karin lowo ofo nile re Jesu

4. Ayo igbala ti o ye wa ni koje tawa ileOlogo Baba Mimo ko mu wa debe atobajaye oOjowo lana fun wa ji ka layo, jerire re

5. Oba oke wa pon wa le ka tun ke pe oMu wa dorun baba mimo nile re lokeAlade oniyi lorun fere fun wa Jeki ale dele ogo nile re loke.

10

Page 10: Madam Omotoso Wake keep programme - myeventmyalbum.commyeventmyalbum.com/wp-content/uploads/2017/09/Chief-Elizabeth... · Igba siso okuta nu, igba kiko o jo; Igba fun kikamora, igba

appreciation

© FOS: 08023285808, 09031100932

The family of Hon. (Chief) Michael Adebayo Omotoso JP.

Embassy of Usi-Ekiti, Ekiti State, Nigeria

expresses its profound gratitude to family, church, friends, institutions

and governments who have stood by us since the passing

on to greater glory of our matriarch

Chief (Mrs.) Elizabeth Dada Omotoso JP.

we thank you for your support towards the befitting

funeral rites for our dear departed, and pray God’s continued

protection on all and sundry as you return to your various destinations

may God bless and keep us all in His love

Thank you

Dr. Olubunmi Omotoso