3
ESENTAIYE (Dicho en la Ceremonia) OMI Omi li a mbu we. Omi li a mbu mu. Eda to wu ti o mba. Omi s ‘ota a ku iku ait’ojo. Omi kiiba’le ko ma n’ipa. Ki...n’ipa rere s’owo. K’o ni’pa rere s’omo. K’o ni’pa rere ninu ohun rere gbogbo. Awayemate oruko ti aipe omi... Motuntemise oruko ti aipe omi... Abudi oruko ti aipe omi... EPO Ero Li epo riro ni i ro igba elop... Amororo li oruko ti aipe epo... Didun-mimu li a i ran’hin iye. Yiyo ni araye i ye fun oniyo. Ki aye... ki o ni adun ati ayo. OYIN Iwaye oyin ki i koro. Ki aye---dun ju oyin lo. ATARE Atare kiiko ile re ki o ma kun un. Ki iru-omo...po bi omo atare. Ata ti a fi newure ni a npe ni atare. Nitorina atare iyo maa wi chun rere gbogbo wa fun... Atare kanna ni omo-araye npe ni Oluya. Oluya ki o ya... ni Olola Oniyi Olorulo rere ninu-aye. Olowo Olomo ati ohun rere gbogbo. Ki ara re ki o da. Ki ara re ki o ya. OBI Obi li araye fi nbi Iku. Oun li araye fi nbi arun. Oun li araye fi nbi ejo. Oun li araye fi nbi ofo. Ati ohun ibi gbogbo danu. Ki obi maa ba wa bi Iku arun ejo. Ofo ibanujhe ati ohun ibi gbogbo danu fun... Ki won gbo bi obi. Ginnugun kiiku l’ewe afuwape ni ti pepereku. Agba l’obi nda ki... gbo ki won to. OROGBO Ori ogbo ori ato aiteteku airun. Ire gbogbo ni i to orogbo lowo. Ire gbogbo ni iyo ma to... lowo ninu aye. Ki ... ni isokan pelu ara won bi orogbo. Ase. Oriki ORUNMILA 1

esentaye español

Embed Size (px)

Citation preview

Page 1: esentaye español

ESENTAIYE

(Dicho en la Ceremonia)

OMIOmi li a mbu we. Omi li a mbu mu. Eda to wu ti o mba. Omi s ‘ota a ku iku ait’ojo. Omi kiiba’le ko ma n’ipa. Ki...n’ipa rere s’owo. K’o ni’pa rere s’omo. K’o ni’pa rere ninu ohun rere gbogbo. Awayemate oruko ti aipe omi... Motuntemise oruko ti aipe omi... Abudi oruko ti aipe omi...

EPO Ero Li epo riro ni i ro igba elop... Amororo li oruko ti aipe epo... Didun-mimu li a i ran’hin iye. Yiyo ni araye i ye fun oniyo. Ki aye... ki o ni adun ati ayo.

OYIN Iwaye oyin ki i koro. Ki aye---dun ju oyin lo.

ATAREAtare kiiko ile re ki o ma kun un. Ki iru-omo...po bi omo atare. Ata ti a fi newure ni a npe ni atare. Nitorina atare iyo maa wi chun rere gbogbo wa fun... Atare kanna ni omo-araye npe ni Oluya. Oluya ki o ya... ni Olola Oniyi Olorulo rere ninu-aye. Olowo Olomo ati ohun rere gbogbo. Ki ara re ki o da. Ki ara re ki o ya.

OBIObi li araye fi nbi Iku. Oun li araye fi nbi arun. Oun li araye fi nbi ejo. Oun li araye fi nbi ofo. Ati ohun ibi gbogbo danu. Ki obi maa ba wa bi Iku arun ejo. Ofo ibanujhe ati ohun ibi gbogbo danu fun... Ki won gbo bi obi. Ginnugun kiiku l’ewe afuwape ni ti pepereku. Agba l’obi nda ki... gbo ki won to.

OROGBO Ori ogbo ori ato aiteteku airun. Ire gbogbo ni i to orogbo lowo. Ire gbogbo ni iyo ma to... lowo ninu aye. Ki ... ni isokan pelu ara won bi orogbo. Ase.

Oriki ORUNMILA(Saludando al Espíritu del Destino de la mañana)

Olodumare, mo ji loni. Mo wo'gun merin aye. Igun'kini, igun'keji, igun'keta, igun'kerin oni Olojo.

Creador, saludo al nuevo día. Saludo a los cuatro puntos cardinales que crean el mundo. La primera curva, la segunda esquina, la esquina en tercer lugar, las esquinas del cuarto son dueños de todo el día.

Comentario: esta es una referencia a los primeros cuatro Odu de Ifa la adivinación, Ogbe Eji, Meji Oyeku, Iwori Meji y Meji Odi.

Gbogbo ira gbaa tioba wa nilo aye. Wa divertido millas ni Temi.

1

Page 2: esentaye español

T'aya - t'omo t'egbe - t - Ogba,

Nos trajeron la suerte de que nos sostiene en la tierra. Me traen todas las cosas que sustentan mi espíritu,

Comentario: esta es una referencia a la idea de que los cuatro primeros Odu convertirse en la primera dieciséis Odu que evolucionan en el Odu doscientos cincuenta y

seis que conforman el Universo.

. wa wa fi Yiye Ki f'ona Han wa. eni Wa fi - Eleni sí Temi.

Con usted no hay ningún fracaso, alabamos el camino que ha creado, no puede bloquear el poder del Espíritu.

Comentario: Ifá enseña que la vida es buena y que la Creación está diseñado para funcionar, lo que sugiere que thse que desarrollar un buen carácter será bendecido.

Alaye o alaye o. Afuyegegege meseegbe. Alujonu eniyan ti nf'owo ko-le-.

Damos gracias a la luz de la Tierra, sino que sostiene la abundancia de la creación.

Comentario: Esta es una referencia al Espíritu de Ela, que en algunos rituales de Ifá aparece como un rayo de luz que emerge de la tierra. Este haz de luz es la conciencia

primordial que puede ser desplazado a través del uso de invocación en un espíritu necesario en el momento de llevar abundancia a la comunidad. Este es el fundamento

de la oración de Ifá.

A ni kosi igi meji ninu igbo bi obi. Eyiti o ba ya'ko un abidun ya - Dun - dun-dun. Alaye o, alaye o.

Nos trae la comida de la selva. Nos trae las cosas buenas de la vida. Damos gracias a la luz de la Tierra, alabamos la luz de la Tierra.

Comentario: La Luz de Ela se utiliza para comprender las fuerzas en la naturaleza y sobre la base de que la comprensión de la Luz de Ela nos muestra cómo vivir en

armonía con las citadas Fuerzas.

2