10
EKO AKETE. K l W E IR O H IN O SO SE . j VOL I. NO. 16. SATURDAY, OCTOBER 28, 1922. T hreepence. kdilor:—ADEOYF,. DENIGA, ASAN-SILg NI OWO GBIGBA Rig Office.: 24, Williams Street, Eko Hu miran iiuokere fcKO- ni Nigeria. " u UKere- P.O. Box 286 Qdnn kau 12/- 13/- 14/- 0^.11 myfa 6/- 6/6d. 7/- [ Lagos, Nigeria. ...............' .... GBBHUK-BBOHUn. J^WQN LO NRO SAFO (A-WA OKp MOTOR KAN,). A kily gidigidi fun enia-lasan kan ti o nva Motor 1.104, pe iruf? i\va t’ o hu ni ggy to kyja ti 0 -iiiy-my iyry ti Motor, na re a won Ogbeni D. O. THOMAS t' o nsiye ni I bode { ( us'onis Agent) ati ADELANi GboOBOADE Onise-Qba ,ni I bode ( A 1 ierk in His Majesty s Customs) s’ cml lori afara DEATON nigbati nwyn nby \va ile lali ibi okii, pgbeni RHODES 1 ’ Ebute-Mota. le gte e ju s’ IjJwon ti ko ba riagbype yn bykinni yi jaja by ninu evu’ yi, HOMAS si pe e lohun-rara pe ki o duro won) yon ni al|ky. 1 na busi gbiVgba. A ki awon A fe ki awon Qlypa kiyesi a-wa Motor yi L104 kiye-; lati on ti wo janib; daradara. i'AGfDAKI ! • Ann fe ni lati gbn pe Ogbeni S. A. F a rot u. A k ,« Uymbo I I.O. ni Ijobu-Ode ti a ba r» ’jo pe o .la ba mpa ;;btgbe ema kan t.-mp-le ni ,-uiabvwo-ara.re ni ijttbu-Ode, jfb| ?1 V m ™ Koru U » fe ni Ibadan ni pan lo In: Adajn S ir F. A. VAHDKR M y. EN I <> da jo na a si sppe ki Ogbfni na san pgbpn ppun bibekp ko o » «wpn o»u nwfa . Oobeni yi san a w na, fugbon o tun gbe eg) dide si GanrAN I' Fko nibi ’ Qgbeni MoNTACUTK T hompson r 0 ba ae eg yi ra m m A 'M

EKO AKETE. - ir.library.ui.edu.ng

  • Upload
    others

  • View
    1

  • Download
    0

Embed Size (px)

Citation preview

Page 1: EKO AKETE. - ir.library.ui.edu.ng

EKO AKETE.K l W E I R O H I N O S O S E .

j VOL I. NO. 16. SA TU RD A Y, OCTOBER 28, 1922. T h r eep en c e .

kdilor:—ADEOYF,. DENIGA, ASAN-SILg NI OWO GBIGBA Rig

Office.: 24, Williams Street, Eko Hu miran iiu okere fcKO- ni Nigeria. " u UKere-

P.O. Box 286Qdnn kau 12/- 13/- 14/- 0 .11 myfa 6/- 6/6d. 7/- [

Lagos, Nigeria................' ....

G B B H U K - B B O H U n .

J^WQN LO NRO SAFO (A-W A OKp MOTOR KAN,).

A kily gidigidi fun enia-lasan kan ti o nva Motor 1.104, pe iruf? i\va t’ o hu ni ggy to kyja ti 0 -iiiy-my iyry ti Motor, na re a won Ogbeni D. O. THOMAS t' o nsiye ni I bode { ( us'onis Agent) ati ADELANi G boOBOADE Onise-Qba ,ni I bode ( A 1 ierk in His Majesty s Customs) s ’ cml lori afara DEATON nigbati nwyn nby \va ile lali ibi okii, pgbeni RHODES 1’ Ebute-Mota. le gte e ju s’ IjJwon ti ko ba

r ia g b y p e yn bykinni yi jaja by ninu evu’ yi, HO MAS si pe e lohun-rara pe ki o duro

won) yon ni al|ky. 1 na busi gbiVgba. A ki awon A fe ki awon Qlypa kiyesi a-wa Motor yi L104

kiye-; lati on ti wo janib;

daradara.

i'AGfDAKI !

• Ann fe ni lati gbn pe Ogbeni S. A. F a rot u. A k ,« Uymbo I I.O. ni Ijobu-Ode ti a ba r» ’jo pe o .la ba mpa ;;btgbe ema kan t.-mp-le ni ,-uiabvwo-ara.re ni ijttbu-Ode, jfb| ?1V m ™ K oru U » feni Ibadan ni pan lo In: Adajn S ir F. A. VAHDKR M y. EN I <> da jo na a si sppe ki Ogbfni na san pgbpn ppun bibekp ko o » «wpn o»u nwfa . Oobeni yi san a w na, fugbon o tun gbe eg) dide si Ga n rAN I' Fko nibi ’ Qgbeni MoNTACUTK T hompson r 0 ba ae eg yi ra

mmA'M

Page 2: EKO AKETE. - ir.library.ui.edu.ng

4 V i > ■

2

:\ \ EKO A K E T E

KABQ, BALO GUN M E YA K I.A ki Qgagun H. C. M oo rh o u se

Oloye C.M.G. “ K ab o ” lati ilu re, lyhin isimi oyu rnefa ti o ti gba ly si ’ie. Qgagun na ba Oky-Elefi “ K k a ri” de ni Saturday to kyja. Alafia ki Me wa bi ?

A K A ILU, $ KU EWU, EWU 1NA K I I P ’ AWODI, AWODI, E KU EWU.

Ni ary Frida y ysy to kyja, ewu nlanla kan wu a won enia t' o nly t* o mby lati yna Ebute-Myta: bi Motor Alaru gbangba ti a won Oyinbo Gr a c e B r o s , ti fy ya fun* ’t o l a r Je - ly -n k y ti A r a o t i ■ (Mr's . G J o h n s o n ) byni M o t o r gbar.gi 'a yi si fori sy awyn opo irin tery-tyry to wa leti afara na ( Ca r t e r BRIDGE) ygafa, o-di-wy ninu omi! a gby pe obinrin Hausa kan t’ o nfi ysy rin ly niti ara re ft ara pa die.

A dupe pe ko si ymi ti o yofo Iona bayi.

" E§U $E E, KO DURO D E M I.”

Irufyayiwere kan yse ti o kyja ni yjy 19 oyu yi, nigbati asiwere na yo tike ti o si sa si oke-aja Ue-pytysi awyn Oyinbo M a c i v e r ni Apapa, li 0 nda gbogbo enia t’ 0 ba fy sun my o lamu; o sa ojinbo kan lapa, ati S a ji .(Sergeant) olopa kan ni iwaju, o

ki on ba le sykale, nwyn fun u, sugbyn sibesibe ko sokale; awyn Panapana 1’ a ransy si, ti nwyn wa ki i lyrun my Me nikyhin. A gby pe okunrinyi jy okan ninu a w y n “ L e b i r a " a w o n O y in b o A r m str o n g Oniye ni Apapa, ati pe ko si ohun to se e saju yjy yi, lojiji ni were na “ (y’di si i.”

ILE-EJO ERU-JhjJ ki

Ue-k/iy awon Ju ry yio.si ni Monday ijy kefa oyu November ti o nby. Adele Adajy A g b a ( A b k r i n - S e p u j a , Q ly la A. R . P en n in g t o n , K .C .) pylu awyn

“ Abeyo” ry, yio kyky ly ye Is in' ,1 Alagogo ( Christ church ) gygy bi iye lakoko yi 1’ ydydun,, ki o to wa byry | A ti nfi iwe pe awyn S a r a k i wa sin 'ba die’ ninu iyy Jury .

A R 1 IY A W O KQ ’Y A L E ?

A sakiyesi, pe nnu awyn enia ti 0Ariya Alake, A d em o la K e j 1, nigbati i; nye Ajoyy Adota ydun ti a ti bi i, a ko ti awyn enia wynyi larin wyn.B<j)kinni A d e b e sin F o l a r in , L fJ Dr A ku v a n d e S a v a g e , a ‘Ogbeni J . K . Co k e r , laisi ani-i enia , meteta wonyi ye gudugudu.L ao apo A dem o la Qmo-A ladk ki to di yniti* gbogbo 1/Igba fe ki o gun !Ity ni ydun Ekeji ohun. K a si nkan

P A S T O R I§QLA §E ’HUN ARA. ;A ba O j iy e - Q l o r u n , PASTOR

A . A d e d e j i I s o l a Alabojuto, Brotherhood yy fun Iwe-Oye (Cetlifi o f Proficiency) ti o ri gba lati Ilu-Oyinboi “ ti Ijafafa ti o ni ninu Eky ohun ti . ( Psychological Studies ) Iwe na ba yk<j\ “ Rlcari ’ ’ de ni ysy ti o koj^. '

AJQDUN K E JQ TI IJQ “ EBENEZER A FR IC A N CH U RC H ," OGUNPA,

IB A D A N , N IG E R IA , 24th S E P T E M B E R , 1922.

E st a b l ish ko A u g u st 1 9 14 *

1KO.HIN K U K U R U ., Kni-ywi. No. us,

Bibeli,

Ni ago myta ysan yjy na, n E. A . Obigbysan bery nipa kikorii lehin eyi ni Jjlni-ywy ka die nil Kni-ywy S. A. Allen wa gbadura. ^

Akowe ijy yi, Qgbeni J . Ade. Qtegbolaj lyhin eyi owa pe Ugbeni pataki ykan ntj onisowo nla ni syro kukuru Ibadan J. Ally Johnson ko wa ye alakoso yjy na, nipa gbigba Aga awyn isyngbe ry ni wynyi ......................................... ‘ ‘ " in . E. aA. Pearse, $r Allen.

Page 3: EKO AKETE. - ir.library.ui.edu.ng

October 28 ]

[■ Otudeko, M. D- Ogunbayyde, E. Victor W a ts o n , N. S O ke. C. J. Meflle, ;T. H. Scott, Charles C. L. ydybiyi, H. O. !,Williams, O. J. E. Okuyiga, Suberu. T. H. Johnson.i Awyn ti ko le wa :— M. D. Ogunbayyde, • C- J- Meffle ati T. H. Johnson.I L?hin eyi ni Qgbyni Alakoso, j . Ally 'Johnson wa byry nipa sisy ( bun to 11m wa wa bi, ory n; to so 0 py to iwyn aby- iwakati, nipa didupy lywy a\mn eni O'lyrun bi gwyn Ogbyni, Wicliffe, Akiogyn, • Otygbyla; T. II Scott to da ijy yi silo ni ile' Isaac [Williams ki O-uwa bo ran ijy yi lywy, ki [a"'on 9my ti ati bi ki won le ma fi 9W9 so iaiva won, wipe Ile-'sin omo iIdle ni eyi. ■ Edo Oyinbo lo sy q.| Awyn to syry ni Ipade yi ni wynyi:— N. S Oke, S. A. Allen, C. L. Odybiyi, [E. Victor Watson, O. J E. Okuyiga, EH. 0 Williams|i A won to wu_.nl lort nipa kiky a lean so orin jti ati te oruky fryn si inu iwe eto Isin y i : — pjgbeni C. !.. Odybiyi enili o kyrin nigba feyta ni ede Ovinbc ati Yoruba, eniti a le sy [Wipe nipa ohun durury ykan lo jo ni Ibadan fopylypy enia le my Qgbyni yi.ni ile Eni-owy J. R. Williams ti ijy Baptist 1' Elso nipa tolnin re ati awyn Qgbyni meji A. E . Smith

j i dun.

• led!

won ymti o mu ipaoe

pade yi jy iwyn pyun

: nipa gbigba aduraAlakoso. pAr-----1U 9!*.. re wipe Ue-lsin U a m ni ag,>

n sa, yio di ( Cathedral) die Qlyrun ma

I.Ogbyni C T . Dixon wa dupe fun Alakoso |pa wiwa ati alakoso to jy

JaQ p ylyp y enia lo wa, gbogbo ile ati ita [0 kim fun ero, akowe ygbyni Lyya Shyngle jyykai. ninu awyn alejo to wa.

Ebcnezer Qlorun wa peiu Ry.Ipade yi pari ni nkan ago marun aby

O PEN L E T T E R S . No. 3 .

/EENMENT HOUSE, LAGOS.

Govermaitburst of popular

Dependency : this

lerfeit, imanifested, was neater sham nor__...........it has its inception in the ‘‘big?’ reputation arising from your humane yet Firm system of government with which your great name was usually .always associated, whilst you held the Governorship of out sister colony of the Gold Coast, and of which

Unhappily, no'sooner Your Excellency assumed ity m our midst in real earnest, than the Eleko ibroolio intervened like “ a bolt fiom the blue” d brought in its train, many heart-burnings and ief to this Community as never before.

o appeal to Your Excellency a ' Devoted Cat’

hicli, we are told, is the very

le Fundamental Teachings of <ti hich Your Excellency has die hono

a this ground alone.»,Or Excellency in the matter, humbly and meStly praying that your Prerogative of Mekcy, becomes a Godly Catholic, may be extended ICE MORE to the ill-fated Prince, who, -to? my

ijy ale.A LAO.

Page 4: EKO AKETE. - ir.library.ui.edu.ng

E K O A K E T E .E kO, SATURDAY OcfOBKR, 28, 1922.

IJO -KI-'JO M B $ L ’ EH IN G B ET I.Jesuit p itaki ti awyn Oyinbo nil awa Ehia

Dudu sun nigbakugba ni pe 0 \va lati ma a sin wyn jy ninu nkan pupo lalai ni lakaye ati da nkan se fun ’ra w a .- ykan ninu ohun ti a nsin awyn Oyinbo jy niyato lati ypylopy ydun sehin wa, titi ii di oni, ni I jo wyn ti a npe ni B a l l : ti a ba by itumy Ijo yi wo, ykan ninu ohuu pataki ti aw9n Oyinbo ft da sile fun ni llu won, ni pe lati ma fi g iyn otutu nu, ni akoko re : l9na bayi o je iyydaly won pe ki 9kunrin ati obinrin ma di m9 ara wyn ni lie-1 jo (Ball-Room.) A ko side ba won wi si eyi, nitori aya ilu W9n n i; “ ldtt’lu ni ye ’lu.,” $ugbyn nigbati awa Enia Dudj apa ibi gba asa yi nay, bi 91b gba igba-oti. oniruru iwa-ibi ky ]o bi sarin wa ? lji 19 ki a wo 9r9 yi ni orisi ona myta na. Ekini. Melomeio ni a won ydymy- kunrin wa ti nw9n ii nfi owo-iyy Oyu won tafala fnn ipalemy Ijo-Oyibiri-lagogo yi, nigbakugbrt ti a ba te iwe sode pe Ijo na ya, nibiti gbogbo wa my pe nwyn ma njo o lie Irati Afari Ogun ( Glover Memorial H all,) o yoro ki a to ri ydymykunrin miran pe ki o I9 si Ipade Ory-Asyye t,ia tile nae lyfy (A free LectureJ tun rere ara re : sugbyn e jy ki a ta lickct Ijo B all kan ni Sile mywa- abo tabi ni poun klTh sde lean, nffafa iwo yio ri ogun lygy odomokunrin ti mvyn yio si gan-ngan lo si hi Ijo na. A tanma pe ko si ohun meji to ngbenwyn io si by ju ati ri aye lati ba pupo awyn ydy-ybinrin ti nwon ko my ri jo , ati pe Iona bayi, lati wa aye ati ba pupy ninu irufy awon omodan be lorijy.

A ko S9pei ohun pataki ti awyn oni- nkan yi (Awon Oyinbo-.) fi da Ijo na si je ni eyi; yvjgbon iwa aito ti pupy oktinrin miran nhu si awon obinrin Iona bavi nigbyhin-gbyhin ki 1 se die.

EkejL Iwa yyaiu ati' infin ii Ijo na nn.u wa^ko kero: ti «idymokuhT;n kan ba so si r: aya A: .go.-, kan bajo ni ile Ijo (Bah Room) trokero' kolfTj&i ‘gba ..kan

irufe odomokunrin by kan lati wa ynac pe ki irufe ava-alaya by le wa ni aryWyto.oij ; nijomiran nigbati ijo B all ba tun kan; %

je ki a fi ero lu ohun ti o le ti idi irufe -J iwa wamytipe bayi jade.

Kketa. * Ijo na si nko awyn ymybht^ wa ni iwa asa ti yio ma ye olukuluku A n'.tqripe kosi ydomybinrin ti yio “ saba’’ ati ‘ ma ly si all ti ko ni h “ gygy fa ” ohuy ti ywy ry ko ti to : ti ko ba ni ipa ati ra nkan na, ko ha di pe ko wa “ woryko fi y’ ada"; ati wa yna ati tyro owo lydy y unrin? Iredi ry nky? Ki o ma ye y ! Nitoty,'; alawyse ni a jy ninu asa Oyinbo yi, tiwa si “ buaya1' bi enipe awa papa ko ni Ijo ? tiwa gygebi Orily-ede ti a le tunye fun . idaraya wa ; o tile d- yni, 0 d' eji, o di emelo ni a nri awon Oyinbo ti nwyn njo Ijo lie wa p ap a; awyn bi ijo Batakoto, § y k ^ | Dudun at oniruru Ilu bawyrrr? Anu se ni l pe pupy ninu wa jy “ Adagba-mada-’n u ^ a ko gbody ni ero ati gbe ohun ti HyAhR niyi, die, afibi a wo-nkoko ti asa-fdaygll laiye ylypa Ido ti o nmu awon oni “ Bicvctlfm nimukumu a sy ara wa di “ Ojo-Wifel nkoko ” ! ! ! ni irufe ona bayi, loju tfa.'Jjo > B all ti di Ijo-kijo: a kosi ni ma a ni yvyy* ninu gbigbe-h-nko re my lati oni lo. B jy ki a mo pe o to asiko ati ma tun nkan wa ?e ki a si ma a gbe niyi: Aiye ijyun ko jy-?; tisyyi.“ O r u k o ERU KO BA WA m u .” Awon

oni lakaye ni a mbawi.,

1GBK 1/ OWO WA.E k i ;ro.

Bi awyn oyinbo iie-bwbwynyi ti gba (ha •( Produce) 1’ osy yi ni eyi. 1

Egbe Idapo-Owo ( A. & E- T. A.) ti-J i r io 10 de ^ ;i0 15 fun ton k.tn '

Egbe Odo-Qya ( Niger Co,) oakanna 1 Oyinbo Agbera ( Lagos Stores ) - do 1 Miller d o v

£ 2 1 ni gbogbo awyn Egby oyinbo ti 3 darukc wonvi gba ton kan. '

0 . coaLati ^25 de ^,27 fun ton kan bakanna.

Page 5: EKO AKETE. - ir.library.ui.edu.ng

| AWQN QMQWE I L ? WA.

■ Gbogbo enia lo nkigbe awpn 9m9we wa f : nl1? y\ fun pe Pgplppp wpn ni iwa wpn' ko ' dara, ti won kp si nbikita ati ti pmp pnikeji t sinu koto lati gbe ara wpn ga. Njnu&; ’?? buruku yi, ko si ohun ti o jp pe wpn ko L *° at‘ rj p- iwa ika yi pe. Ni ilu p A " any a r' bi o ti jepe awpn onibaje wa I:. n,b?> aw,.,r} ti o j? pe gbogbo Qba ilu ni lati

ie kuro ninu Ajp ilu wpn, ohun ti o pe ni I lanu ninu rp ni pe Onigbagbp ni won, ko |‘: s> ninu wpn, beni ko si si abpripag : PVIu L Bp si ni ni ilu wa yi pplu, ninu ohun

gbogbo ti o buruju, awpn Onigbagbp yi kp a . ni o hanjp apiwaju, awpn ti o jp pe gpgp bi r‘: ilaju wpn ati pkp wpn ; o yp ki nwpn ki olma i;Tr fi apprp olukp wpn han ni pna gbogbo ; ko -f ba to akoko fun wa lati berp si inu ro pe

kini se ti o ri bayi, iha pe iwe ti a inp, tabi f.; isin ti a gba lo nmu iwa wa ri bayi, tabi j| Jlaju ti a gba pplu rp ni. i? Nigbati a ba sakiyesi pe awpn Onigbagbp I lo ppju ninu awpn pmowe wa, ti nwpn mp I' ede ati apa Oyinbo daradara ju awpn isin ti I 0 ku Ip anu ko Je pe ki o rna pe ni lati ri pe

ami Olukp wpn ko risi ninu iwa won, eyiti | a sp pe o ngbe orilp-ede soke.

1£ je ki a wo awpn Iwe-irohin wa ni ile j yi, nitoripe iypn dabi Awo-jiji ti o nfi iwa ati

ekp awpn ti o npehan; awpn ti o nka wpn yio ma pakiyesi pe ninu ikan tabi meji, ohun

, ti a nri ka ninu rp ko jp eyiti 0 .yp pniti o la’ju ti o si jp pmpwe ati Onigbagbp lati ma ko prp aini ibpwp fun Qba ilu wpn, ede acfekandeke, ati ki a si ma bu' pniti o ba di wpn lpwp ti ko ba jp kiero inu won pp; ki a fi orp Eleko papprp, tani ko mp pe ohun ti Eleko pe, ka tilp sp pe o pe Ijpba, ko to nkan ti o le mu gbogbo ro-gbo-di-yan wpnyi wa, awon tani ha wa ni idi rukerudo yi, bikope awpn pmpwe ti o jp Onigbagbp; ninu iwe-irohin “ West Africa'' ni a pepp wa ri idi ija yi pe ede aiyede ti o wa ki pe larin Ijpba ati Eleko, pugbpn larin Eleko ati awpn Dr. R an d le ni, bi a ba si ro daradara, a o ri gbangba pe Qgbeni Onipegun yi pplu awpn pmplehin rp lo ti ngbidanwo pupp pe ki prp yi ma loju; a ko mp ewo lo ‘kan

wpn ninu pro yi, a ko mp bawo ni prp ilu cmlu pe ya 1' apo wpn, psppp ni iwe irohin wpn fi nsprp alufapa si Qba ilu, bpni prp ylprun sp pe ‘ ki a ma bpwp fun Qba ati Ijoye re,” pkan ninu awpn oniwe irohin ti o npe ohun alebu yi si Qba wa, sp ninu iwe irohin rp kan, nigbati o nda pmpluwabi kan lohun, pniti 0 fi orp Qlprun kp Gomina wa lprun nipa prp ti Eleko yi, 0 ni " a ko nfi prp Qlprun pe ilu ” bi eyi ba je otitp ilu Gpsi kc ni ri bi o ti ri loni yi, ijpba Gpsi eyiti o jp alabo wa ni ilp yi lori prp Qlprun n' Ijpba wpn duro le, Onigbagbp enia dudu ti apa ihin ni prp Qlprun ko han ninu iwa wpn. .

<( Nigbati awpn agbalagba kan, awpn ti o n ifpn, ti o sin 1’ ekanna ” ngbidanwo ati;

sa pa wpn pe prp Eleko yi ko' to ohun ti a ' le fun ’ka mp lati se ohunkohun, ti nwpn si pe gbogbo ara ilu lati fi 9W9 si iwe yi lati tun prp yi la fun Gomina, ko si ohun ti awpn iwe irohin yi ko sp tan, nigbati nwpn ri pe awpn ara ilu ko bikita ati gbp tiwpn, nwpn wa bprp si awpn agbagba yi bi nikan o jpkanl nwpn ni nitori ati ri owo gba jpun ni nwpn pe sp pe awpn ma kp iwe si Ijpba nip.-ise Eleko, Gomina ko ni gba, ati iru nkan bawonni, ohun kan ni a fp ki awpn ti o nkp iwe irohin yi mp, on ni pe, iwe ti gbogbo wa nfi pwp si yi, a o fi ppwp si Gomina lati mp pe ppplppp wa lo fp Eleko yi a ko si le rp 9 loye yi tabi ka ni ki 0 lp sun gpgp bi awpn oniwe irohin yi ti nfp.

Lati igbati a ti nka iwe irohin ti ilu Oyinbo irufp ki a ma sp ispkusp si enia tabi ki a ma bu enia ppwpn pupo, a fi eyiti iwe irohin di nkan miran lpdp enia dudu ti Eko nihin, irufp prp ti awpn iwe irohin wpnyi nsp si Adamu fihan pe pkp wpn ko pe wpn lore rara, bi ko ba ?e be, kini kan wpn pelu A damu ; bnvo ni ija isin onisin pe di tiwpn, a ni ireti pe nitori ati tubp ni ilaju si i, ati lati mp; bi a ti pe 'sprp pplu ede pmp­luwabi ni a pe nran pmp Ip.si ile i w e a le bere pe kini A damu se ti awpn pmpvve Onigbagbp yi fi nwa isubu rp, A damu yi jp pataki ninu awpn Ijp Musulumi ti o wa Iphin Lempmu BuRAlMp, nigbati ija wa

Page 6: EKO AKETE. - ir.library.ui.edu.ng

EKO ARETE [ October

krin wpn, o wa ninu awpn ti o ba Lemomu se awo, o 1119 kewu pupo, o si ri oye iwe die ; pplu diena, o mu pan?an akere-koro ni, enia kekere ko §e gbe, awpn Janma fi j ' 0ye.-Ak.9Ve, on si ni nwpn si fi i e ran lati ma fihan riigba gbOgbo ija isin wpn ni nwpn nja, ati pe ko si pro ti ily ninu re, o je alore fun awpn enia re ti o fi jp oye, o si nlo iba ipa ati oye rp lati ri pe prp nwpn ypri si dada. 0 pe isp rp dada tobp ti gbogbo koto ti awpn pta nwa fun wpn, awpn janma ko ko sinu re ; eyi dun awon pmpwe Onigba- gbp yi pupp debi gongo, pe A damu ke! iwe wo lo mp, awpn ndi nkan, o si ntu u, njp o di karewa, nwpn mu u ]p si A jo. Igbimp ti Apofin I jpba, Olori Ajo ni on ko ri si i, o ni ki nwpn wa oiviran §9, ko si pna ti nwpn ko pba tan lati ri pe ife wpn pe, ko si ebu ti nwpn ko fi bu u tan, nwon gbagbe prp orin Akewi funfun kan ti o ni :—

Qla ati itiju, ko ti ipo kan dide,$e ipp re daradara, nibp ni gbogbo pla wa.

Nitotp A dAmu AwiMApAUN kb gun, bpni ko sanra, pugbpn pda ti Olprun rp fi da nj yi, bi o si ti wu Qba A d’ $d a lo np’ ebu rp. Mose, Anabi Olprun, akololo ni, sugbon ‘ ‘ Oripa ri ’yun nilp, ko to yan spse efun 1’ ayq,” Qlprun lo nlo A damu fun awpn enia re lati ko wpn jp lcuro ninu ikekun awpn ppiyp-ppiyp.

Awpn ti Qlurun fun 1’ aye ati ma wa ire awpn arailu wpn laika ohun li awpn pmpwe wpnyi.nsp si wpn lara si, o, yp ki a ma gba- dura fun won, ki a ma ranti pe, ko si ohun li iru awpn pmpwe wpnyi ko le da si arin enia ti o re meji, ko si arosp aff aheso ti nwpp ko le ju silo, ko si si pgbpn pro ti nwpn ko le lo lati fi da inu aikonu silp; 0 yp ki a mafeti si isokuso won, sugbon ki a kp oju wa si -ona kanna ti a ti nba bp, ki a si ma sa gbogbo ipa wa ni pna ti o dara lati ri pe ohun ti a nfe te wa Ipwp.

FANOICUN.

S c rip tu re C o lu m n .“ ALL THAT GOD DOES, IS DOI^E WELlji,

( By M. Bankole Fadipe.)Rabbi Akiba was once travelling through

country, and he had with him an a! "

At night fall, he reached a village wherei sought shelter for the night without successfcf

“ All that God does, is done well,” said5 Rabbi, and proceeding towards the forest,*3

God does, is the rooster v still he said

> devoured by wild beasts; yet more than “ All that God'does,.-

; j llearned that a troop of

re said again, “ All that God does, is done v.el!.The Talmud Page 266.

The fool hath said, in his heart, there is no . Sod. Tsalm xiv. /.

Is anything too hard for the Lord ?

“ Thy yesterday is thy past; thy to-day thy future ; thy to-morrow is a secret” .ffira

SI AEABOJUTO “ EKO AKETlv-” LATI QWQ ALAFIA.

Inu ini dun lopplppp nigliati mo ri iwe “ Efcpy \kete” ekini to jade. §uglk>n g?gpbioti#W. np ni ninu, bpni o'ba mi Iprii to, nitori nigbati mo

i .gba i kpja, 1 ; gbogbo r

Awa ara Eko ko gbokanle. Bi a ba ri tun ryly gygy bi igbi

ii oke fun sT orriT ... .0_. __ _____ Eniti o ba fp ntgirohiu fun ilu rp yio joye “ Ojo ko ba pnikai. yio jp olotp enia ; pitorira mylpmyli?

Ti 6 ba fy ki iwe rp ?e ilu yi ni ore, 0: WSv,0 ti otitp, lpsan loru ati ni abusudaji. Ma If »vo nui p purp, ma jy ki o mu p sp asydun, ;>rp ba ti ri gari, bpni ki o ma sp. Ki Ql9rl,Q1 ran y lpwp lati ?e rere fun ilu wa yi g?6? §? 0gbidanwo lati §e lati iyiwaju. V!^j8|Igo ma gbidanwo lati ran prp diydi? si <? 1 oniruru nlcan ti mo ro pe o nfy ibysvomo si tanma pe prp mi ki yio muly mofo.

Page 7: EKO AKETE. - ir.library.ui.edu.ng

dampran, pugbpn nibiti ;mo-mptan enia ba wa, ti eke ati agabagcbe ba wa, ti onigberaga ati anigbera-ppnlp ba wa, ti wpbia ba wa, ati ti alaipotp ati onibitibiti ba wa. nibiti ikorira ara pni ba wa, njp eyi ha le pe ?e ? A ha

| ie dampran ohun kan. E jp ki a yp ara wa wo. gnyin agbagba ti o nba pmpde wi pe ija ko dara iije pnyin papa ko ti di atppp-ija-jp bayi ? Arunti ;.o mu iwpnyi wa ni mo ti sp siWaju. Kini le wo

ip|irun wpnyi san. Ife ilu wa, Nigbati a ba tan [fsiwaju, ti a ba tan sphin, nko ro pe a le ri pnikpni ti

le fpwp sp aiv i pe on fpran ilu yi nitotp. Bi irurp

| “ oliuu ti a ba gb.in ni a c

pe ohunkohun ti a ba

I a j q j g b i m q i l u t i t u n t i a f eDA S I L $ NI N IG E R IA . ,

I Eyi yio je ayipada, tabi ohun titun larin wa, ti a | si ro ne yio mu ire wa ba iln wa dandan. $ugbpn | i-wu nla ni ubp ninu rp bin awa ara Eko. Awpn I plomiran ro pc a ko iti dagba to lati ni iru igbimp I bayi, fritori oju ko iti la to, pugbpn awpn mi ran ro r pe o to akoko ti o yp ka fiuj Eko ni iru anfaui ti a I fp lati fun. Ti pmpde ba to’ni apoani apo. 0 di I pspta pdun ti Ijpba Gpsi ti gba.itpju il? yi spwp I won. Qpplppp ohim ni wpn si ti pe fun ilpsiwa* I ilu yi, bpni pgprp nkan ni nwpn ti pe ti ko dumr.p I awa ara Eko ninu. O le jp pe wpn npe ohun I mi ran ti won ro pe,yio pe wa ni ire nigbamiran ti.| a ko mp, ti a si ml npe ni ibi, pugbpn a ko lc fp

iru ohun bayi ku Ajp-Igbimp titun yi pa yio jp fun I ilpsiwaju ilu wa. §ugbpn ki ilia pe ohun ti awa

ara Eko yio fi jplpnkp .pe o. Nko jp ba awpn ti 0 ! so wipe a ko iti to ni iru anfani bp wi puppjo.

fin ui „b.i wpn! Arpba-s. ko ma ?ojo. Stop, ''MP lean :u igi in' oju-ina." A ha le ma fa ni ni •pip tiii „iyc\ pjpki awa. na gbidamvo 1ati tin

Oepta <>dnn ha npe pinpde pdun bi f

Eto sinu lgbim qy,. y a l» fi ojq-Ljq'Jan' won mpta wpnyi, ara wa la ma npe o. A ni lati yanawpn ti yio to lati gba pra

$i pugbon

ti yio sp otitp fun wa, ki pe awpn ti o fp lasan, ki pe ipe awpn ti o nspro aliipa-

o. Ninu rogbodiyau ihiru awpn enia ti o yp lati yan si igbimp wa Ipfun wpn si wa losi, nitorina nigbati o ba ya, a ni lati woye daradara ki a to yan wpn. Ilu ti o ba da si pna tneji ko male duro ! Ilu Eko kole toro ti a ko ba dawppp ti a ko ba si damppp. Eyiti a gbogim K nr, o ha tp ? $ jpki a bp ;

dpwo r

ORIN ILU WA NI IL E -? S INO jp ohun ti o dun mo ni lppplppp lati ri pe

awpn Ijp ti o wa ni abp itpju awa enta dudu npe orin ilu wa ti a nkp ni ile-psin. Eyi jp ohun ti o dara lppplopp, o si fun ni ipiri. Nitori nigbati a ba ni ohun bp, o fi hanni gbangba pe gpgp bi orile- ede, awa na ni ohun tiwa, a si ni lakaye. O jp apa wa, pataki larin awpn apppp dide wa, lati ma pata ohunkohun ti o ba ti jp ti ilu wa. pugbpn

E jp ki a mu ohun ti o dara ni tilu wa dani giri- giri, ki a kp ohun ti ko dara ninu rp silp patapata. A kiyesi pe bi awpn ti o npe orin wpnyi ti ngbidauwo. to yi, o ku dip ko to. Nigbati a ba fp pe iiu orin psan .buwpnyi o yp ki a ma ro jin Ip daradaca. A ni lati mu ohun irplp ati pbp kp orin ti prp rp jpy ti pbp ati irplp, eyiti o ba si jp prp ayp, o yp ki a ma fi ohun ayp ko, nigbati a ba mu ohun ayp ti a ba fi pkp prp pdun, yio di amulu-mala. Eyi ko dara. Nisisiyi, a ri pe ohun ti o ba wun wa pa ni a fi nkp p, ti o ba sa ti ndun yungba a ko bere. E jp ki a

Nigbana ni ao le gbadun ipp pwp wpn.*

MAMMY R E ’ LE O, ILE LO LQ KO $INA.

A ba Alufa J. M. Ologundudu ti Ilu Sapeli, ati Mrs. 0 . A/ Rieff ti No 2 Ita Rieff, l’ Eko daro of9 to sje won ni Monday ose yi nipase iku iya wpo SARAH F ato ku nI

K ’ Oluwa dp ’lp fun u. i ; -----------]---------------------

Page 8: EKO AKETE. - ir.library.ui.edu.ng
Page 9: EKO AKETE. - ir.library.ui.edu.ng

; TH E “ A JE N IF U J A ” SEW IN G MACHINES.

$ These Machines are .German Manufactured. Constructed of the best matetials and skilful workmanship, very splendid in appearance, quick

..action and noiseless. No confusion, simple to ;• 'thread, easy to operate, Durability Guaranteed ■ will last almost life time, call for one at Ori-ade \ Stork 97 & 109, Broad Street Lagos, Needles,

Shuttles, etc., etc. in stock. Prices on application.VIDAL R. COLE,

Sole Agent.

I " 0 $EW QN1 !” ( FA IR W A RN IN G)i O.ebfni A. W. Olukolu Onigbanjo to gba A§p a?do Ijpba Nigeria, nta ori?iri$i oja ni Gbanjo,

pile Gbanjo ry ni 2, Isalcgangan Street, I’Eko.O si nta ile ati ile p?lu.

: Awpa ojp pja-tita ni iwpnyi. Monday, ati Thursday, lagogo m$ta Qsan. Saturday, Iagogo

; ,mysan arq, I9S9SC. O ntete san owo pja fun enia. ?rMn pja 1$ I? si bp.

N. V. HANDELMATTSCHAPPIJ V. H.J . F. S IC K ati Awpn Egbe.

I No. 7, Ita lbode lailai, 1’ eti Glover Memorial Hall ( Customs Street, ) EKO.

1 Awpn Oyinbo oni$owo yi nran$9 Ma$ini-Aran'$o ti a npe ni VESTA Nos. 1-4 t' 9I9W9 ati t’ flfs? ni

■ owo to rpju, a le ft iye-owo wpn han enikijni to | ba Ip si Ile-Owo yi.

N'wpii mura tan lati $e Adehun pataki pylu . cnikcui to ba (f mn$o Mejila tabi ju bf Ip ninu S Marini na.

Awpn Oyinbo yi n$e ori$iri$i Ilcky alarabara,■ Nwpn si nran?? (Cemet) ati panu kikple to nipon, ati . ?ja Abomafo ati Ori?iri?i pia.\ llpBtm lie awon Oyinbo vi $t nigbanugba ti ema' f ba hf lati lq ba wpn s<?rQ A$iri nipa Owo. Ikohin \ KO TO AFOJUBA.

lie Ita Egb ogi ti M a cau la y .( Macaulay’s Household Dispensary.)

:: A nta ori?m$i ogun Ilera ni Ile-oja yi, to wa niI popo-nla ( Broad Sired,) 1’ Eko ni owo po 9- I A won Ogun bi Oku, Painkiller, Ogun Inarun,t Ogun Lakuregbe, Ogun Kuruua, Oguu Aran to | data Ogun ?da, Ogun Arcmo-

| Qgbpui S. A. Q. Macaulay ?niti oni He-Egbogi | yi )e yniti o gba A$y ogun pipo (Certificated p Dope-user.f lpwo Ijpbii Nigeria'.' E LQ DAN A WO, Ogun r? jy b. idan.

ILE OWOiyjA RIRAN^S T t AWON ? G B S OYINBO C. F. HUTHCHINSON

Nt ILU OYINBO.

CebCTi na >i ni awjn Akfl, (F'U) Bala Fuafun ati awon nkan tniran dlradara pylu ni tita ti owo W911 ko ta enia laiya..

1? lo dan a wo ni lle-Owo r? ni Ita Tinubu, t’ o . kpjusi Kotu, 1' Eko.

9 GBI?Nl DURO: THOMAS.ONI$OWO PATAKI.

Ti 55, ita Faji, l'Eko, ni oripiri i Qja to de fun lati Ilu Germany fun tjta: aw9n nkan Awo Abpmafp, Cement, Akara, ati 9P9I9P9 pja miran.

ljl I9 de ibp, Igbo-Akan ’mppa ni ohun

Bi 9 ba fe, 9 k9\ve si i, Number Apoti-Iwe r9 ni Ile ipin iwe ( General Post Office) ni 374. Number fifi-erp manamana ba a sprp ( Telephone ) ni 243.

IL E EGBOG1 I$E OLODUMARE.

A *i ile Egbogi kan ti a npe ni I59 Olodumare si Qja Qbun Eko ni ile kyta si Iga Oloye Aromiry. Nib? ni a le ri ori$iri?i iwos.m fun oniruru aisan,

Iba e fun Orififo. Inurirun, I£da, Inarun, Aran Ktnni?a, Iko. Ipa. Qryry, Q?9 Egbogi, Egbogi Oju, ati awon Oniruru ti a ko le to sihin tau

Kin de be ki o. wo o. Irohin kb to afojuba. Iwp ko til? gb9 orulto rp ndan ?

I$p Olodutunare ! ! 1Joshua O. Adb: Craig,

Alabojulo.

Vixtoka, A,0)u a„o„ g Sbe

slo awon Arango, ati oniruru 1 odp awpn Oyinbo rp ni Ilu

Page 10: EKO AKETE. - ir.library.ui.edu.ng

Oruko adugbo awpn oyinbo onijowo yj 'ire ti\ STEINAFRIK. Hamburg vp

G ID 'O BO ' G ID T fRO ' ! 11 EYA.i l I

/ N D U S T R Y

> Bata ni yppku yyyku. Kowe sown i ede Yoruba tabi ti Gosi pelu owo si:—

E. B UEYIQKU-ALAS5 , 108, Moloney Bridge St.P. O. Box 368, Lagos, Nigeria.

R E A D Y.C h u rch a n d P o litics.

( A L e c t u r e )

OF THE Cl.KKGY TO Till' LaBy Prof : DENIGA.

it 34 Williams Street, Lagos. 3d. a copy.

SOLD

‘(Tika-Tore” Printing Works,

Advertisements.* ’ •! POLO WO QJA.

A L A S E L E A T H E R FA C T O R Y

, ' I L E A L A WO.”

Sole-Leather tanned in a most modern style .and' Upper-Leather prepared in all colours, namely:— Black, White, R e d , Yellow, apd Green, are obtainable at very cheap prices

Awon Emm Oyineo Onisowo iK. H. STEIN ARA HAMBURG. ;

Necerwall 16 r8.-Germany.Je Awpn oni§o\yo ti Ily Enia Dndu, nwi,

nran?? Qja fun enik?ni to bji f?'iha?e Qja ti llu'l tabiti.awpn Ilu oyinbo miran t)England ati Germany.

Nwpn si nba enia'ta Qja bi Epo tabi Rkor ba ti ran$?si wpn si llu a wpn oyinbo ( £ ni owo ti o jo cnia loju. '

Kosi ewu kankan ni li li Qja-kpjii ran?? si v lati Eko tabi llu miran ni Siberia. if-

Ki pnikpni to ba fp ba awpn Oyinbo yi jov tabi ki o kowe si A?oju won nilti Osbeni l Kotun ti ita Qba Dosunmti No 3, tabi ni r? (Office) ni Opopo-nla (Broad Slreel?j ibi-ili Qja panip si (J-orto-novo Market Sit Eko.

Rnik^ni le kpwe ni ede Gpsi, niti German I

Awon R E C O R D S to nkorin lpde. YO R tJBA po lo wybu ni ile o$o.T$s|

MANN POOLE & CO M PA N Y LTD. 8, T inubu SqQare, Lagoss^

Ki la ti mj' oku I' nrun Ki la ti ns’ ori nile ikti

Tutu tabi Gbigbe ? 9p9kuyoku si ni, wa sa eyi to \i

8, T lh UBU SQ U A RE, LAGOSi 1