7
WWW WWW Roma Viterbo Rieti Latina Frosinone L’Integrazione Diventa Sistema. Amona awon ise iranlowo ati awon ibi iwifun fun awon eniyan ajoji ni Lazio YORUBA

YORUBAasap.lazio.it/asap/images/allegati/guida_servizi/YorubaGuida.pdf · YORUBA YORUBA Yiyan Dokita akoko fun o laye ati ni awon iwa rere fun idehun. AROJINLE ORO - STP Ti o ba je

  • Upload
    others

  • View
    9

  • Download
    1

Embed Size (px)

Citation preview

Page 1: YORUBAasap.lazio.it/asap/images/allegati/guida_servizi/YorubaGuida.pdf · YORUBA YORUBA Yiyan Dokita akoko fun o laye ati ni awon iwa rere fun idehun. AROJINLE ORO - STP Ti o ba je

WWWWWW

RomaViterbo

RietiLatina

Frosinone

L’Integrazione Diventa Sistema.

Amona awon ise iranlowo ati awon ibi iwifunfun awon eniyan ajoji ni Lazio

YORUBA

Page 2: YORUBAasap.lazio.it/asap/images/allegati/guida_servizi/YorubaGuida.pdf · YORUBA YORUBA Yiyan Dokita akoko fun o laye ati ni awon iwa rere fun idehun. AROJINLE ORO - STP Ti o ba je

YO

RU

BA

YO

RU

BA

“Amona awon ise iranlowo ati awon ibi iwifun fun awon eniyan ajoji niLazio” je iranlowo pataki fun awon eniyan ajoji ti ngbe ni agbegbe ilu latifi le gba iwifun ati awon ifihan pataki lati le yanju gbogbo nkan ti nwonnfe fun aiye oyaya ati olaju. Amon naa ni awon ibi ikowe si, awon iye eroibanisoro, akoko ati ona lati le fi gba awon ise iranlowo ati lati le de awonibi iwifun ti o wa ni awon ijoba ilu ti igberiko ibugbe ile ti Lazio pelu iyeeniyan ni ilu ti o ju 8.000 eniyan loo ati ni ilu Rome.Ni ibi iwifun ati iranlowo eniyan le bere, ti o ba wa, iranlowo awa laariinede ati asa.

Awon ori oro

WWWWWW

Gbigbe ni Itali

Akojo ofin owo Ati awon ise iranlowo ipese fun

Awon ise iranlowo ile ibura

Awon ise iranlowo ilera

Awon ise iranlowo ajosepo

Iwase

Ilo internet ati awon ikojopo iwe

A ti rin kakiri

Ile iwe

1.

2.

3.

4.

5.

6.

7.

8.

9.

Se o sese wo Itali fun ise tabi fun ebi? O ni ojo mejo lati le fi lo si SportelloUnico Immigrazione (SUI - Ile ise fun awon eniyan ajoji) ti Ufficio Territoriale delGoverno (Prefettura - UTG - Ile ise agbegbe ilu ti ijoba) ti o je oniyanju adugbo.Awon SUI ni awon orisirisi igba sisi gegebi nkan ti eniyan nfe, bi apere, lati gbaiwe igbelu fun iwe kiko tabi lati ba ebi gbe. Awon orisirisi ona naa lo wa: bi apere,fun ipade, pelu ero ibanisoro tabi pelu internet. Be naa ni awon Uffici Cittadinanza(UC - Ile ise fun awon eniyan ilu), ti o wa ninu awon Prefetture (Awon ile ise asojuijoba), nibi ti eniyan le lo lati bere bi nwon se ngba didi ara ilu itali.Se o wo Itali fun iwe kika, esin, ise tikara eni, gbigbe tabi o fe so dititun iwe igbelu re tabi o fe bere iwe igbelu ti CE (ti Europe) lati gbefun akoko ti o gun repete? O le se ibere iwe igbelu pelu iwe ti nwon se funlofe ni awon ile ifiwe ranse. Ti o ba fe ise iranlowo, o le bere iranlowo awonPatronato ti o sunmo adugbo re ti nwon sise pelu Ministri Intirio lati le koibere re lofe, isodi titun tabi iyipada iwe igbelu, lati ba o se ibere ase fun iweibagbe ebi, ibere lati gba eniyan si ise lati ile ajoji, ipade fun idanwo ede italilati le fi gba iwe igbelu CE fun awon ti o b afe gbe fun akoko ti o gun repete.Awon ibi ikowesi ti Patronati wa ni www.portaleimmigrazione.it.Fun awon nkan miran pelu iwe igbelu o le lo si Questura ti adugbo ibi ti o ngbe.

AROJINLE ORO - ADEHUN IDAPONi akoko ti o wo Itali nwon a ni ki o se ni Sportelli Unici per l’Immigrazione adehunidapo, ti nwon nbere lowo awon eniyan ilu ajoji ti o j uomo odun 16 loo, ni iwole akokoni Itali, ti nwon bere iwe igbelu ti o ju odun kan loo. Pelu ifowosile ni adehun naa,o ni eto fun awon iwa rere ti o ma posi ti o ba se awon ise kan (ti o ma dikunti nwon ba dajo pa e). Awon iwa rere naa yio jeki o le toju iwe igbelu re.

Gbigbe ni Itali

L’Integrazione Diventa Sistema

1

Page 3: YORUBAasap.lazio.it/asap/images/allegati/guida_servizi/YorubaGuida.pdf · YORUBA YORUBA Yiyan Dokita akoko fun o laye ati ni awon iwa rere fun idehun. AROJINLE ORO - STP Ti o ba je

YO

RU

BA

YO

RU

BA

Se o nfe akojo ofin owo? Akojo ofin owo, se pataki fun gbogbo nkan sisepelu ilei se ijoba ati, ni pataki, lati fi oruko sile fun ise iranlowo ilera ti gbogboidile, o le bere re ni awon Agenzie per le Entrate (AdE - Ile ise ijoba fun sakosoinawo), ni awon ilei se won ni adugbo re.O le wulo fun e iwe ISEE (Iwe ifihan oro owo eniyan) - Indicatore SituazioneEconomica Equivalente, ti o je iwe eri ti o kan oye owo ti o gba lodun kan ti o wulo,fun apere, lati bere owo pooku fun onje ile iwe awon omo re tabi fun owo ososuti awon oko igboro. Lati siro re o le lo si awon Centri di Assistenza Fiscale (CAF -Ile ise iranlowo fun akoso inawo) ti o w ani adugbo re. Awon CAF je iranlowoikoko, nibi ti awon afunni nise se ati awon osise nlo fun ise iranlowo nipa ofin owo.Fun awon ise iranlowo ipese fun - owo isimi lenu ise fun arugbo, fun agba,lalainiselowo - tabi iranlowo - owo isimi lenu ise fun abo ara, ailese, owo fun olomo- o gbodo lo si okan ninu awon ile ise INPS (Ile ise akoso fun abojuto awon eniyanisimi ise ati awon eniyan pelu abo ara), Istituto Nazionale Previdenza Sociale.

Se o nfe ibugbe tabi iwe ebi? Se o fe bere iwe oruko? Lo si ile ibura ti iluibugbe re. Awon Uffici Relazioni con il Pubblico (URP - Awon ile ise iwifun atiimoran fun awon ara ilu) ti awon ilu le fun o ni awon iwifun pataki nipa awonise iranlowo, awon akoko ati ona lati fi se il bere naa. Awon ilu miran le ni ileise ni ibomiran lati le je ki awon eniyan le ri ise iranlowo yi gba ni kiakia.

Awon ise iranlowo ile ibura3

Awon ise iranlowo ilera4

Akojo ofin owoAti awon ise iranlowo ipese fun

2

Bawo ni o se le gbadun iranlowo ilera? Bawo ni o se le se idehun funDokita ti o fe? Awon ASL (Ile ise ilera fun agbegbe ilu) - Azienda SanitariaLocale – ni awon ile ise ti ibugbe re fun awon ise iranlowo igba akoko, bawo nio se le fi oruko re sile fun ise iranlowo ilera ti gbogbo orile ede, lati yan Dokita,ise iranlowo akoko Dokita (fun apere, pelu ise iranlowo titi) ati idaduro aisan peluabere ajeara ati itoju awon eniyan ti ko lagbara.Ile ise URP (Ile ise iwifun ati imoran fun awon ara ilu) - Ufficio Relazioni con ilPubblico – je ise iranlowo lati le fun Ajo si alejo ati iwifun ati fun itoju eniyan. Awoniwifun ti o le gba lati URP le je nipa akoko ati ona lati le fi gba ise iranlowo naa,sugbon o le lo sibe fun itokasi tabi fun gbigba pada. Ise iranlowo CUP - (Ile ise fun

ipade) Centro Unico Prenotazione – wa fun idehun fun awon idanwo iwaju ati ijinle.Pelu telifonu o le se idehun fun ise iranlowo ni ile iwosan ti o wa ni agbegbe Lazio. Itesiwaju ise iranlowo CA (Itesiwaju iranlowo) (ex Guardia medica) mudaju,nigba kikanju, iranlowo ilera fun gbogbo eniyan agbegbe re (awon olugbe ati eniti ko nse olugbe) ni awon akoko igba ti Dokita akoko ko si ati Dokita fun awonomode ti o yan. Pelu ero ibanisoro o le se idehun ni awon akoko yi:- lati 20.00 titi de 08.00 ni gbogbo ojo- lati 10.00 titi de 20.00 ni gbogbo ojo siwaju odun- lati 08.00 titi de 20.00 ni gbogbo ojo odun.Ile ise PUA (Ibi ati ona a ti see) - Punto Unico di Accesso – je ile ise iranlowo tiawon ilu Lazio fun eniyan ti nwon se jejeje (arugbo ti ko le toju ara re, arugbojejeje, eniyan pelu abo ara, eniyan pelu aisan akanse tabi pataki, pelu wahala latikuro, ti nwon nfe iwosan akojopo, pelu otoju fun igba gigun tabi pelu orisirisiwahala ni aiye won). Awon ilei se PUA mudaju itoju awon eniyan, fun gbogbo igbaakojopo-ilera ati ise iranlowo, ati je ki irin naa loo gere pelu ise iranlowo. Nibi gbogbo agbegbe ise iranlowo 118 o nsise, o si yara: ti o b ape iye yi osise ileraijinle ojiji yi o dahun, yi o si se iwaju wahala ti o ni, yi o si ran, ti o ba se oranyan,oko igbesile ni kiakia.Awon ise iranlowo miran naa wa fun awon eniyan ajoji nikan:• Ile ise fun agbani nimoran nipa akojopo-ilera fun awon eniyan ajoji ni ile

iwosan Ospedale San Gallicano di Roma.• Istituto Nazionale per la promozione della salute delle popolazioni Migranti e per

il contrasto delle malattie della Povertà (INMP - Ile isona ti orile ede fun ileraawon eniyan ti o kuro ni orile ede won ati lati da awon aisan talaka duro) (Ile iseti orile ede fun ise iranlowo ilera fun eniyan irin ajo ati fun idaduro awon aisantalaka) pelu ohun afojusi lati toju, ninu ise iranlowo ilera ti gbogbo idile ede, ileraawon eniyan aini anfani, pelu fifun won orisirisi akojopo-ilera ti nwon nfe.

• SaMiFo (Ilera fun awon eniyan ti o kuro ni orile ede won ni dandan) (Saluteper Migranti Forzati) fun awon ti o nbere idi abo fun eniyan ti o sa kuro ni orileede re ati fun awon eniyan ti o sa lo si ile miran fun abo ti nwon wa ni Romepelu ifowosowopo pelu ile ise Associazione Centro Astalli e l'Azienda di SanitàPubblica ASL (Ile ise ilera fun ara ilu) RM A. Ile ise SaMiFo fun awon eniyan peluidaloro ise iranlowo agbari ati asinwin, ti nwon je eniyan ti o nlo ise iranlowo yi julo,ati ise iranlowo gege bi ofin ilera lati le ko sile awon iya idaloro ti nwon ni.

• Ile ise GrIS (Awon ile ise iranlowo fun ajoji ati ilera) - Gruppi locali Immigrazionee Salute pelu ohun afojusi lati gbe ga ati kojopo awon ise ilera lati ran awoneniyan ajoji ni Itali lowo.

Page 4: YORUBAasap.lazio.it/asap/images/allegati/guida_servizi/YorubaGuida.pdf · YORUBA YORUBA Yiyan Dokita akoko fun o laye ati ni awon iwa rere fun idehun. AROJINLE ORO - STP Ti o ba je

YO

RU

BA

YO

RU

BA

Yiyan Dokita akoko fun o laye ati ni awon iwa rere fun idehun.

AROJINLE ORO - STPTi o ba je eniyan ajoji ti ko wa pelu ofin pelu iwe igbelu, o ni eto fun awon ise iranlowoilera ojiji lati apa ise iranlowo ilera ti gbogbo orile ede, nipa fifun kaadi ilera ti o njeSTP (Ajoji fun akoko kekere) (Straniero Temporaneamente Presente), ti o mudaju:- awon iwora ni ile iwosan ojiji ati pataki, fun igba pipe pelu, fun aisan atiipalara;- iranlowo pelu ogun idaduro (awon ajeara – ogun idaduro agbaye ati fun aisanakoran) pelu kiyesi pataki fun awon omode;- itoju aboyun ati iya olomo.STP mudaju iforuko pamo, o si wa fun osu mefa (o se so di titun) o si se lo nigbogbo orile ede. Lati le gba kaadi naa, o gbodo lo si ASL nibi ti wa ti so orukore fun won. Ti o ba lowo, wa fi owo si iwe “ibura talaka” pelu eyi w ani itoju.Sugbon nwon le bere owo poku, bi gege ofin.

Awon ise iranlowo ajosepo5

Iwase6

Se obi nikan pelu omode ni o nse? Se o ni wahala pelu ebi re, omopelu isoro o si le ise ranlowo? O nfe ise iranlowo amoye ninu wahalati o si mo nkan ti o le se? O nfe ile ijoba? Bere ise iranlowo awon osiseajosepo ti ilu ibugbe re ti nwon yi o fihan o awon ise iranlowo agbegbe re tio le wulo fun o nwon yi o si gbe yewo gbogbo ona lati wa esi si wahala ebiati owo re.

Se o nwa ise? O ti pari eko agidi o ti to omo odun 16? O le fi oruko sile niCentro per l'Impiego (CPI - Ile ise fun iwase). Ile ise CPI ni ona labe ase lati waise, o w ani gbogbo agbegbe, ofe si ni. Lati fi oruko sile o gbodo di kaadi imoyan,iwe igbelu ati akojo ofin owo. Awon osise CPI yi o bere oye iwe ti o ka ati oye odunti o lo ni ile iwe ni Itali tabi ni orile ede re, ise ti o mo se, ti o ba le lo komputa,awon ede wo ni o mo, ati bebe lo. Gbogbo awon iwifun ni nwon yi o ko si iwetimotimo re, ti nwon yi o lo lati fi oruko re sile fun awon ise.Awon Centri per l’Impiego miran nsi fun awon eniyan pataki nikan: eleyi ni awonCentri per l’Impiego fun awon omo ile iwe univasiti ati/tabi awon ti o pari eko gigaati ilei se SILD (Ile ise iranlowo lati wa ise fun awon ailagbara) - Servizio inserimentolavorativo disabili ti onse Ise iranlowo nikan fun awon ti o fi oruko sile si iwe iniyanabe aabo: awon alailera, ise, ise iranlowo, ogun ati awon ti nwon n se ojagun, awon

afoju, awon eniyan ti o ni wahala ogbele tabi awon ti ko riran daradara, awon aditiati odi, awon eniyan aditi ati odi lati ibi tabi ki o to bere a ti ko ede siso. Nwon w ani ilu pelu awon Centri di Orientamento al Lavoro (COL - Ile ise imoran funeniyan ti o nwa ise) nibi ti o ti le ri awon amoye ti won le to si ona ise. Iru ise wo ni odara fun o? Nwon a yi o ran e lowo lati ko iwe iwase, ti o ba fe, o si le ka awon ifilo ise.Awon COL miran se ise iranlowo, ni pataki, lati se ajo a ti ko ise ni ile ise ijobaati egbe tabi a ti wa ise ati ise fun awon elewon ati eni ti o jade lewon. Awonapere meji yi ni a npe ni Col akose ati Col elewon.

Bawo ni o se le lo internet ti o bani internet ni ile re? Ninu awon ikojopo igberiko Lazio o le ri, bi o ba se ri, ise iranlowo Wi-Fi tabiinternet ni computer ti ikojopo iwe naa.Awon ikojopo iwe ti Rome, pelu ise iranlowo BiblioWiFi o je ki o se se, funawon ti o fi oruko sile si Bibliocard, lati lo lofe Internet pelu computer wonni awon ikojopo iwe ti o je ki o se se lati lo internet laini okun waya. Igberiko ti Roma, pelu julo, o se “Provincia Wi-Fi”, awon adugbo hot-spot tieniyan ti le lo internet ofe pelu iforuko sile. O le ri awon adugbo naa ni:www.mappawifi.provincia.roma.it. O se jupe ki o lo si awon adugbo yi pelucomputer, smartphone tabi ero ibanisoro ti o ni Wi-Fi.Ni awon ikojopo iwe ijoba o le ya ni ofe awon iwe, iwe irohin ati iwe iwifun,ni ede itali ati ni awon ede miran.

Ilo internet ati awon ikojopo iwe7WWWWWW

Page 5: YORUBAasap.lazio.it/asap/images/allegati/guida_servizi/YorubaGuida.pdf · YORUBA YORUBA Yiyan Dokita akoko fun o laye ati ni awon iwa rere fun idehun. AROJINLE ORO - STP Ti o ba je

YO

RU

BA

YO

RU

BA

Se nwa ile iwe? Den Lo si ibi yi lati ri, ni gbogbo igberiko Lazio: www.usrlazio.it.Awon omode ti nwon gbodo lo si ile iwe titi di omo odun 16. Iforuko sile funile iwe se se ni gbogbo odun ikawe ti o ba tile ni iwe fun eto/dandan a ti kawe,pelu igba ti ko se gege.Lati ni awon iwifun nipa ofin ati awon ona lati se ibere nipa “ibamu” ti awoniwe ipari eko lati awon orile ede yatosi Itali, lo si www.atpromaistruzione.it.

Ifi oruko sile ati lilo fun iwo ati awon omo re fun ile eko ati eko kika ni se pelumimo awon iwa rere fun Adehun idapo.

AROJINLE ORO - ILE IWEEto ile iwe itali bere lati awon omo kekere pelu awon ile asiwaju eko akoko ti o nsedandan fun awon omo titi de omo odun meta. Ni Rome nwon je ti ijoba ilu tabi tiikoko, awon egbe ikoko lo nse akoso won pelu adehun pelu ijoba ilu. Lati omo odun3 o le fi oruko omo re sile fun ile eko omode ti o wa fun gbogbo awon omode latiomo odun meta titi de omo odun marun siwaju ojo 31 ti osu kejila odun (disemba).O si npari ni odun meta, eleyi naa, ki se dandan. Fun iwifun idapo nipa a ti fi omore si ile asiwaju eko tabi ile eko omode, lo si ilei se URP ti ijoba ilu re.Lati omo odun 6 o gbodo fi oruko omo re sile fun eko akoko ti nwon pin si onameji ona ekeji lehin ipari ti ona akoko awon mejeji se dandan:- ile iwe akoko, fun odun marun;- ile eko keji ti ipo akoko, fun odun meta.Eto akoko eko pari pelu idanwo ijoba (licenza media), eni ti o se yoge ni eto latibere ile eko ti ipo keji tabi awon ile eko agbegbe. Nwon pin eto keji eko si awonLicei, Istituti Tecnici ati Istituti Professionali.Lehin eto keji eko eniyan le lo si ile eko giga ti Univasiti tabi ile eko IstruzioneTecnica Superiore (ITS - Ile eko ise owo ijinle).

Awon Centri Territoriali Permanenti per l’Educazione degli Adulti (CTP/CPIA- Awon ile ise agbegbe fun eko awon agba) je ile eko ijoba, nwon si wa nigbogbo agbegbe, fune ko awon eniyan agba lati le fi ni iwe ipari eko ati iweijeri fun imo pataki fun ibere eko/eko kika ati fun ise.Awon eko CTP je ofe, nwon si wa fun awon odomode ati awon agba, awonokunrin ati obinrin, eni ti o nse ise ati eni ti ko ni ise, pelu afojusi ibere ise atiidapo ati titunse imo re. Nwon je: imura ati gbigba iwe ipari eko ti eto akokoeko (licenza media), awon eko olaju, Idanwo fun mimo asa olaju, eko ede atiolaju Itali, Idanwo L2, idanwo fun iwe ipari eko ede ati awon eko miran. Ni awon CTP o le ri iwifun ati awon ibi ikowe si ti awon ile eko ti o nse eko edeitali ni agbegbe re, pelu adehun pelu awon CTP, ni akoko daradara ati ile ekofun itelorun re, ti ile eko CTP ba jina si ibi ti o ngbe tabi ibi ti o ti nsise.

Ilosi awon eko ede, asa ati olaju itali yi o je ki o ni awon iwa rere fun adehunidapo ati lati ma se awon idanwo ijerisi.Iwe A1- A2- B1, pelu ifowosiwe oga CTP gegebi iwe gbogbo orile ede atiagbegbe, fun ni eto lati ma se idanwo ede itali fun fifun iwe igbelu ti igba ti ogun pupo ati fifun awon iwa rere ti o wulo fun adehun idapo.

Ile iwe9

Se o nfe iwifun lati gba iwe awako tabi o fe yipada eleyi ti o gba ni ileajoji? Lo si ile ise awon Motorizzazione Civile (MC - Awon ile ise fun iwe awako)ti ibugbe re. Awon iye ero ibanisoro ofe wa nibi ti o ti le ri iwifun nipa iweawako, iru bakanna tabi titunse iwe awako, yiyipada ibugbe ati iwe irin.Se o fe rin kakiri pelu oko ijoba? O le lo ise iranlowo reluwe ti Trenitalia:o le ri ni www.trenitalia.com awon akoko, oye owo ati awon miran ti o fe monipa irin ajo pelu reluwe.Yato si awon oko oju irin o le lo awon ise iranlowo ti oko ni ori titi ti awonegbe irin pelu oko ti ilu adugbo re. Ni agbegbe yi a ni egbe Co.Tra.L. Lo siwww.cotralspa.it/ lati mo iwifun nipa akoko, iye owo ati ona irin.Awon ise iranlowo igberiko ati ilu:• Ni Rome a ni egbe ATAC (www.atac.roma.it/) ti o nse akoso gbogbo awon

oko ori titi (oko akero, oko akero ti itanna, oko akero ori irin, oko miranti itanna), igboro ilu, oko ori irin agbegbe, fun apere Rome-Viterbo, atiaswon ise iranlowo miran. Nibi internet won wa ri iwifun nipa iye owo iweirin ajo ni kiakia ati fun ososu, akoko ise, ona irin ati bebe loo.

• Ni Rieti awon ti o nse akoso gbogbo awon oko ori titi ni egbe ASM. Nibiinternet won www.asmrieti.it/azienda/servizi.asp wa ri ona irin, akokoati iye owo.

• Ni Frosinone, egbe GEAF ni o nse akoso gbogbo awon oko orititi:www.geafautoservizi.it/siamo.htm. Awon omo ile iwe, awon arugboati awon alabo ara nse irin ajo pelu iye owo poku: bere nibe!

• Ni Viterbo ati igberiko awon ti o nse akoso ni egbe Francigena S.R.L.,awon lo nse akoso oko ori titi nwon si ngba iye owo poku lowo awoneniyan abe aabo: fun iwifun bere lowo [email protected] www.francigena.vt.it/.

• Ni Latina ati agbegbe egbe Atral Lazio ni oko lati Ciampinoaeroporto(papa oko ofurufu) ati lati stazione (idi oko) Anagnina lo si Rome iwifunwa ni www.atral-lazio.com/.

Ni internet awon egbe oko ori titi ijoba o le ri irin ise lati le mo ona ati akokoirin fun awon oko ijoba ati ti ikoko.

AROJINLE ORO - AWON IDAKERE IYE OWO OKO O se pataki lati mo wipe ni gbogbo agbegbe idakere iye owo oko wa fun eni ti ko toomo odun 30 ati fun owo ISEE ti o kere si 20.000 euro. Awon idakere iye owo okomiran wa fun awon ti nwon ni isoro ebi tabi ti oyaya. Awon idakere bi o se kan awonoko ori irin ni o se kan awon oko ori titi. O le ni iwifun si ni: www.regione.lazio.it.Ni Roma Metrebus, egbe ti ATAC nse apa kan, gba iye owo ososu, ni owo poku,fun awon eni ti o salo si miran fun abo ogbon iselu, awon ti o ni wahala iwa ikorira,awon onifarapa ipaya, ti nwon ni ibugbe ni Roma Capitale, pelu owo ISEE titi di20.000 euro. Awon iwe irin ajo ati awon ti ososu ti egbe Metrebus se lo lati rin ninuRoma Capitale ninu bus, tram e filobus; ninu bus Cotral ni igboro; ni igboro ilu;ninu awon reluwe agbegbe Roma-Lido, Roma-Viterbo, Roma-Giardinetti ati,nipari, ninu awon ori irin agbegbe Trenitalia - 2°classe ninu igboro.

A ti rin kakiri8

Page 6: YORUBAasap.lazio.it/asap/images/allegati/guida_servizi/YorubaGuida.pdf · YORUBA YORUBA Yiyan Dokita akoko fun o laye ati ni awon iwa rere fun idehun. AROJINLE ORO - STP Ti o ba je

�� YO

RU

BA

YO

RU

BA

Page 7: YORUBAasap.lazio.it/asap/images/allegati/guida_servizi/YorubaGuida.pdf · YORUBA YORUBA Yiyan Dokita akoko fun o laye ati ni awon iwa rere fun idehun. AROJINLE ORO - STP Ti o ba je

PRILS LazioPiano regionale d’integrazione linguistica e sociale degli stranieri nel Lazio

(n. 2012/FEI/PROG.-104528)

L’Integrazione Diventa Sistema.

DIREZIONE POLITICHE SOCIALI, AUTONOMIE, SICUREZZA E SPORTwww.regione.lazio.it - www.socialelazio.it