18
139 Chapter 6 - Orí K÷fà | SHOP WITH ME OBJECTIVES: In this chapter you will learn: - The use of the interrogative ‘Eélòó - Oní-/Al-/¿l- /Æl- - How to haggle - Numbers 100-3000

Curso de Yoruba - Cap 6

Embed Size (px)

DESCRIPTION

Curso de Yoruba - Capítulo 6

Citation preview

Page 1: Curso de Yoruba - Cap 6

139

Chapter 6 - Orí K÷fà | SHOP WITH ME

OBJECTIVES:

In this chapter you will learn: - The use of the interrogative ‘Eélòó - Oní-/Al-/¿l- /Æl- - How to haggle - Numbers 100-3000

Page 2: Curso de Yoruba - Cap 6

Orí K÷fà (Chapter 6) Àwæn örö (Vocabulary)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 140 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Àwæn örö (Vocabulary)

Nouns aago clock/bell

àgbàdo corn

àgbë farmer

àgbò ram

àlùbôsà onion

àmàlà yam floured meal

a«æ cloth/clothing

ayò a game

ewúrê goat

fìlà hat

gààrí grain made from cassava

ìjögbön trouble

ilá okra/okro

ìpolówó advertisement

Ìrìn-àjò journey

irú locust bean

këkê bicycle

olóko farm owner

òróró peanut oil/vegetable oil

oúnj÷ food

ögëdë plantain

æjà market

æjô day

ækà / àmàlà meal made from yam flour

öla tomorrow

ælôjô periodic

màálù cow

méje-méje in sevens

sùúrù peace

wòsìwósì petty trading

Page 3: Curso de Yoruba - Cap 6

Orí K÷fà (Chapter 6) Àwæn örö (Vocabulary)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 141 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Noun Phrases àwæn æjà kan some markets

èlò ilé household items

ëkæ mímu pap

erè oko farm produce

ëyà ækö car parts

ìyá aláta female pepper seller

æjà oko farm market/ village market

Adjective tuntun new

Other Expressions ó súnmô It’s near

Page 4: Curso de Yoruba - Cap 6

Orí K÷fà (Chapter 6) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 142 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Lesson 1 - Ëkô Kìíní:

Interrogative: Eélòó

Interrogative ‘Eélòó’ implies ‘how much’. For example:

Buyer: Eélòó ni ata yìí? How much is this pepper?

Seller: Ogúnun náírà ni. It is twenty naira (¥20).

I«ê »í«e 1 Lo àp÷÷r÷ tí ò wà ní ìsàlë yìí láti fi dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí. Use the model below to answer the following questions.

Bí àp÷÷r÷:

Hat (¥ 50) Eélòó ni fìlà yìí? Àádôta náírà ni.

1. Shoe (¥ 70) 2. Pen (¥ 40) 3. Bag (¥ 65) 4. Onion (¥ 12) 5. Corn (¥ 20) 6. Hat (¥ 35) 7. Plantain (¥ 25) 8. Mango (¥ 18) 9. Okra (¥ 22) 10. Locust beans (¥ 15)

Page 5: Curso de Yoruba - Cap 6

Orí K÷fà (Chapter 6) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 143 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 2 Níná æjà Haggling Lo àp÷÷r÷ tí ò wà ní ìsàlë yìí láti fi dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí. Use the model below to answer the following questions.

Bí àp÷÷r÷:

A pair of pants (¥ 50) »é «òkòtò náà gba ogójì náírà? Rárá‚ kò gbà.

1. Shoe (¥ 70) 2. Dress (¥ 40) 3. Beans (¥ 15) 4. Onion (¥ 5) 5. Corn (¥ 8) 6. Banana (¥ 10) 7. Plantain (¥ 25) 8. Dictionary (¥ 49) 9. Okra (¥ 20) 10. Spinach (¥ 17)

I«ê »í«e 3 Wo àp÷÷r÷ tó wà lókè yìí‚ kæ ìsöröõgbèsì tí ó wáyé láàárin ìwæ àti ìyá ælôjà sílë. Má «e jê kí ó ju gbólóhùn mêwàá læ. Use the example above; write ten lines of dialogue between you and a market woman (haggling in the market).

Page 6: Curso de Yoruba - Cap 6

Orí K÷fà (Chapter 6) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 144 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Lesson 2 - Ëkô Kejì:

Oní-/Al-/¿l-/Æl-

Al-/¿l /Æl- are prefixes used to describe one who owns, one who does, one who sells, or one who has. They are derivatives of Oní-/. For example, oní + a«æ —> oná«æ—> alá«æ. n=l because they are allophones, and /i/ is elided with tone retention. The initial vowel /o/ takes the form of /a/ which is then copied. Note that al-, æl-, ÷l-, and el- are allomorphs of oní For example:

oní + ata aláta one who sells peppers

oní + æmæ ælômæ one who has a child

oní + ÷ran ÷lêran one who sells meat

oní + i«u oní«u one who sells yams

oní + aago aláago one who sells or fixes watches

Note the initial vowel copying in aláta, ælômæ, ÷lêran, and aláago.

Page 7: Curso de Yoruba - Cap 6

Orí K÷fà (Chapter 6) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 145 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 1 Use oní-, al-, ÷l-, or æl- 1. àmàlà =

2. gààrí =

3. irú =

4. àlùbôsà =

5. këkê =

6. wòsìwósì =

7. ilá =

8. a«æ =

9. òróró =

10. aago =

11. ækà =

12. ælá =

13. ayò =

14. fìlà =

15. sùúrù =

I«ê »í«e 2 Fi èyí tó bá y÷ dí àwæn àlàfo wönyí Fill in the spaces below with the appropriate words using oní-, al-, ÷l-, or æl-

Ní æjô kan‚ mo læ sí æjà láti læ ra a«æ lôwô ____________. Ní ibi tí mo ti ñ bá ____________

sörö lôwô ni mo ti rí ____________. Mo pè é‚ mo sì ra i«u m÷ta lôwô _______ láti fi gún iyán.

Bí mo «e fê máa læ ni mo tún rí ____________ àti ____________ tí wôn ñ polówó ata àti

÷ran. Mo pe àwæn náà‚ mo sì ra ata àti ÷ran pëlú.

Page 8: Curso de Yoruba - Cap 6

Orí K÷fà (Chapter 6) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 146 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Lesson 3 - Ëkô K÷ta:

Níná Æjà (Haggling)

Ìsöröngbèsì (Dialogue)

Nínú æjà (Inside the market)

Ìyá aláta àti oníbàárà Pepper seller and a buyer

Màmáa Tádé: Eélòó ni tàtàsée yín, ìyá aláta?

Ìyá Aláta: Èwo nínúu wæn?

Màmáa Tádé: Àwæn tí ó wà ni àárín y÷n?

Ìyá Aláta: Náírà márùnún ni àwæn y÷n.

Màmáa Tádé: Háà! Wôn ti wôn jù. N kò lè san náírà márùnún o. ¿ jê kí n san náírà mêta àbö.

Ìyá Aláta: Rárá, kò gbà. (Màmáa Tádé ñ læ.) Ó dára o. ¿ wá mú u ní náírà mêta àbö.

Màmáa Táde: ¿ gbà. Náírà márùnún nìyí o.

Ìyá Aláta: Ò dára o. ¿ gba náírà kan àti àádôta kôbö. ¿ padà wá o.

Page 9: Curso de Yoruba - Cap 6

Orí K÷fà (Chapter 6) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 147 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Màmáa Táde: Mo gbô o.

I«ê »í«e 1 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences.

1. Ìbéèrè wo ni màmáa Tádé bèèrè lôwô ìyá aláta? 2. Eélòó ni ìyá aláta pe tàtàsé fún màmáa Tádé? 3. Eélòó ni màmáa Tádé ní òun máa san? 4. Eélòó ni màmáa Tádé san ní ìgbëyìn? 5. »éñjì eélòó ni ìyá aláta fún màmáa Tádé?

Cultural vignette: ÆJÀ

Æjà jê ibi tí àwæn ènìyàn tí ñ tà tàbí tí wôn ti ñ ra nõkan. Àwæn æjà kan wà fún nñkan pàtó tí ènìyan bá fê. Bí àp÷÷r÷, æjà oúnj÷ yàtö sí æjà a«æ. Bêë ni æjà a«æ yààtö sí æjà ohun èlò ilé. Orí«irí«i æjà ni ó wà ní ilë÷ Yorùbá. Ní ìlù Ìbàdàn, æjà tí ó wà fún a«æ títà ni Æjàa Gbági tuntun àti Æjà Alê«inlôyê. Æjà Òjé, Æjà Orítamêrin àti Æjàa Bódìjà ni wæn ti máa ñ ta nõkan bíi oúnj÷ àti ohun èlò ilé. Æjàa Géètì ni wæn ti máa ñ ta àwæn ëyà ækö. Æjàa Mónìyà àti Æjà Örányàn ni ibi tí wôn ti máá ñ ta ÷ran ìso bíi àgbò, ewúrê àti màálù. Àwæn æjà mìíràn wà tí kì í «e olójoojúmô. Nígbà mìíràn, ó lè jê æjà ælôjô mêta-mêta, márùnún-márùnún tàbí méje-méje. Æja oko ni àwæn æja tí ó súnmæ oko tí àwæn àgbë ti máa ñ ko irè oko wæn wá fún títà.

I«ê »í«e 2 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí. Answer the following questions.

1. Irú àwæn æjà wo ni ó wà ní ilë÷ Yorùbá? 2. Dárúkæ àwæn æjà ìlú Ibàdàn tí a kà nínú àyækà yìí. 3. Àwæn æjà wo ni wôn ti ñ ta a«æ ní ìlú Ìbàdàn? 4. Kí ni wôn ñ ta æjà ni Æjàa Môníyà àti Æjà Örányàn? 5. Æjô mélòó – mélòó ni wôn sáábà máa ñ ná àwæn æjà ìyókù?

Page 10: Curso de Yoruba - Cap 6

Orí K÷fà (Chapter 6) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 148 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 3 Jê ká «e àfiwé à«à. Sæ fún wa nípa à«à æjà ní ìlúù r÷. Tell us about the market system in your country.

Ìsöröngbèsì (Dialogue)

Màmáa »adé àti Màmáa Fúnmi pàdé ní æjà. »adé’s mom and Fúnmi’s mom meet in the market.

Màmáa »adé: ¿ káàárö o, Màmáa Fúnmi

Màmáa Fúnmi: ¿ káàárö o, Màmáa »adé, a à jí bí?

Màmáa »adé: A jíire o. Gbogbo ilé ñkô?

Màmáa Fúnmi: A dúpê o. Dáadáà ni wôn wà. Bàbáa »adé ñkô? »é àlàáfíà ni wôn wà?

Màmáa »adé: A dúpê o. Bàbáa Fúnmi náà ñkô o?

Màmáa Fúnmi: Wôn wà o. Wôn mà ti læ sí ìrìn àjò.

Màmáa »adé: Dáadáa ni wæn yóò dé o. Mo mà fê ra ata rodo, ata «öõbö, tòmáàtì, àlùbôsà, iyö àti epo pupa.

Màmáa Fúnmi: Èmi náà fê ra ÷ja tútù àti «öõbö fún æbë ÷ja aláta ni.

Màmáa »adé: Mo máa ra ëfôæ «ækæ yökötö àti ëgúsí. Mo ní láti ra èlùbô fún àmàlà,

Page 11: Curso de Yoruba - Cap 6

Orí K÷fà (Chapter 6) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 149 CC – 2012 The University of Texas at Austin

fún oúnj÷ alê.

I«ê »í«e 4 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí. Answer the following questions.

1. Níbo ni Màmáa »adé àti Màmáa Fúnmi ti pàdé? 2. Kí ni ìdí tí Màmáa »adé fi kí Màmáa Fúnmi pé ‘a à jíbí’? 3. Ta ni ó læ sí ìrìn àjò? 4. Kí ní Màmáa »adé wá rà lôjà? 5. Kí ni Màmáa Fúnmi ní láti rà?

OWÓ NÍNÁ NÍNÚ ÆJÀ

Ìsöröngbèsì (Dialogue)

Two friends, Kúnlé and Ládi meet in the market.

− Háà Kúnlé, kí ni o wá «e ní æjà?

− Màmáa mí ní kí n wá ra ÷ran náírà mêwàá, ìr÷sìi náírà márùnún ààbö, ata rodo náírà kan, àlùbôsà náírà kan, èfôæ tëtë náírà méji. Wôn fún mi ní ogúnun náírà. Tí ì«irò r÷ bá péjú, eélòó ni ó y÷ kí n mú padà læ sí ilé?

− Kúnlé, «é o mö pé mo fêràn ì«irò! Wà á mú …..uhhhhh…… àádôta kôbö padà læ sí ilé fún màmáà r÷. Tí o kò bá «e bêë, o ti wæ ìjögbönæn màmáa rë nìy÷n.

− Ládi, èmi náà ti «írò iye tí ó y÷ ki n mú padà læ sí ilé, O mæ ì«irò gan-an ni o.

− Màmáa tèmi náà ní kí ñ ra ata tàtàsé ægôta kôbö, epo pupa náírà kan, àlùbôsà ægôrin kôbö, ëwà pupa náírà márùnún, gààrí náírà márùnún, nínúu náírà márùnúndínlógún. Èló lo rò wípé ó y÷ kí n mú padà læ sí ilé?

Page 12: Curso de Yoruba - Cap 6

Orí K÷fà (Chapter 6) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 150 CC – 2012 The University of Texas at Austin

− Náíra méjí ati ogóji kôbö.

− O gbà á. Ó dàbö o.

− Ó dàbö o.

I«ê »í«e 5 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí. Respond to the following questions.

True Òótô ni

False Òótô kô

1. Ládi àtí Kúnlé pàdé nílé ætí. ☐ ☐

2. Màmáa Kúnlé ní kí ó læ ra ÷ran ogúnun náírà. ☐ ☐

3. Ogúnun náírà ni wôn fún Kúnlé láti ilé. ☐ ☐

4. Ládi kò fêràn ì«irò rárá. ☐ ☐

5. Àádôta náírà ni Kúnlé máa mú padà læ sílé. ☐ ☐

6. Babáa Ládi ni ó rán an læ sí æjà. ☐ ☐

7. Èfôæ tëtë wà lára nõkan tí màmáa Kúnlé ní kí ó rà wálé. ☐ ☐

8. Àlùbôsà wà lára nõkan tí Ládi àti Kúnlé máa rà læ fún màmáa wæn.

☐ ☐

9. Kôbö mêrìndínlógún ni màmáa Ládi fún un. ☐ ☐

10. Kúnlé sæ iye owó tí Ládi máa mú padà læ fún màmáa rë. ☐ ☐

I«ê »í«e 6 Kæ ìsöröõgbèsì kan láàárínin iwæ àti örêë r÷ ti ÷ jæ pàdé nínúu æjà Write a dialogue between you and your friend you met in the market.

Page 13: Curso de Yoruba - Cap 6

Orí K÷fà (Chapter 6) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 151 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Á«à Ìpolówó Æjà (Advertisement)

Àgbàdo sísè: Láñgbé jíná o Örökún orí ebè Olóko ò gbowó

Ëwà sísè: Àdàlú elédé o

Awùsá: Awùsá gbó keke bí obì Ó gbó bí orógbó

I«u sísè: ¿lêntú dé o. Örê ìkëtê dé o Ó tú sépo múyê, Ó fàtàrí napo pê bê

¿kæ mímu Ómí ê ñ hó yeeyéè, Yeeyéè ní ñ hó o Ëyin æmæ àràbà mêta Odòokun, ¿ wa mu ún Yeeyéè ní ñ hó o

Àwæn orin Yorùbá nípa oúnj÷ (Song about food) Oní mæínmôín gbewá gbewá Mæínmôín epo »ó mepo »ó mepo «ìndìn Mæínmôín epo »o fedé si pëlálùbôsà Mæínmôín epo

Àwæn orin Yorùbá nípa oúnj÷ (Song about food) Oní dòdò oní mæínmôín Oní dòdò oní mæínmôín Nígbà tí ò tà ó gbé gbá kalë ¿ wá wò jà ní Láfíàji.

Page 14: Curso de Yoruba - Cap 6

Orí K÷fà (Chapter 6) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 152 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Lesson 4 - Ëkô K÷rin:

Nôñbà (Numbers)

Nôñbà 100-3000

100 ægôrùnún 300 öôdúnrún

110 àádôfà 400 irínwó

120 ægôfà 500 ëêdêgbëta

130 àádóje 600 ÷gbëta

140 ogóje 700 ëêdêgbërin

150 àádôjæ 800 ÷gbërin

160 ægôjæ 900 ëêdêgbërún

170 àádôsànán 1000 ÷gbërún

180 ægôsànán 1200 ÷gbëfà

190 àádôwàá 1400 egbèje

200 igba 1600 ÷gbëjæ

203 ÷êtàlénígba 2000 ÷gbëwá/÷gbàá

250 àádôtalénígba 2,200 ÷gbökànlá

2,800 ÷gbërìnlá

3,000 ÷gbëêdógún/ ëêdêgbàajì

More on Numbers

Àádô = ogún lônà ilôpo iye kan ó dín ÷êwàá (20 x ? - 10) Ëëdê = igba lônà ilôpo iye kan ó dín ægôrùnún (200 x ? - 100) Ëëdê + ÷gbàá = Ëêdêgbàá

i.e. ÷gbàá lônà ilôpo iye kan ó dín ÷gbërún (2,000 x ? -1,000)

Page 15: Curso de Yoruba - Cap 6

Orí K÷fà (Chapter 6) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 153 CC – 2012 The University of Texas at Austin

÷gbàáta = 6,000 (2000 x 3)

Therefore, ëêdêgbàáta = 5,000

÷gbàárin = 8,000

Therefore, ëêdêgbàárin = 7,000

÷gbàáwàá or ökê kan = 20,000

ökê méjì = 40,000

I«ê »í«e 1 Kæ ìdáhùn r÷ ní Yorùbá. Write your response in Yorùbá.

Bí àp÷÷r÷:

100 – 100 = òdo

1. 150 – 40 =

2. 200 – 60 =

3. 87 + 54 =

4. 45 x 3 =

5. 16 + 143 =

6. 78 + 125 =

7. 49 x 4 =

8. 169 – 53 =

9. 70 + 70 =

10. 200 – 132 =

Page 16: Curso de Yoruba - Cap 6

Orí K÷fà (Chapter 6) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 154 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 2 Kæ ìdáhùn r÷ ní Yorùbá. Write your response in Yorùbá .

Bí àp÷÷r÷:

Yæ àádôtalélôöôdúnrún kúrò nínú ÷gbëta. Kí ni ó kù? Ó ku àádôta.

1. Yæ ÷gbëta kúrò nínú ÷êtàdínlógúnlélêgbërin. Kí ni ó kù? 2. Yæ ëêdêgbërin kúrò nínú ÷gbërin . Kì ni ó kù? 3. Yæ ægôsànán kúrò nínú ÷gbërún. Kí ni ó kù? 4. Yæ ægôjæ kúrò nínú ægôsànán. Kí ni ó kù?

I«ê »í«e 3 Dí àwæn àlàfo wönyí. Fill in the blank spaces.

Bí àp÷÷r÷:

ogún x 3 = ægôta

1. x 4 = ægôrin

2. àád = 180-10

3. ægbön àti = 630

4. ëêdêgbësán dín = ÷gbëjæ

5. = 420

Page 17: Curso de Yoruba - Cap 6

Orí K÷fà (Chapter 6) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 155 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 4 So àwæn tí ó bara mu ni öwô A àti öwô B papö. Match the words in column A with those in column B.

A B

149 ÷êrìndínlôgöwá

196 oókàndínláàdôjæ

500 igba

200 ëëdêgbëta

2000 ÷gbëfà

1200 ÷gbàá

120 ÷gbëta

600 ægôfà

60 àádôsànán

170 ægôta

I«ê »í«e 5 Mú èyí tó bá tönà nínú àwæn wönyí. Circle the correct answer.

1. Yæ ÷êtàdínláàdóje kúrò nínú öôdúnrún, ó jê? a. ÷êtàléláàdôsànán b. ÷êtàlélógóje c. ÷êrìndínlôgöwá d. oókànléláàdôsànán

2. Yæ ÷êtàdínlógún kúrò nínú ÷êrìndínláàádôtalénígba, ó jê? a. oókàndínlôgbönlénígba b. ÷êtàdínlôgbönlélôödúnrún c. eéjìlélôgbönlénígba d. ÷êtàlénígba

3. Yæ ogún kúrò nínú ÷êtàlélægôjæ, ó jê? a. ÷êtàdínláàdóje b. ÷êtàlélógóje c. ÷êtàléláàdóje d. ÷êtàléláàdôsànán

Page 18: Curso de Yoruba - Cap 6

Orí K÷fà (Chapter 6) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 156 CC – 2012 The University of Texas at Austin

4. Aárùnúndínlôgôfà àti aárùnúndínláàádóje jê? a. ogójìlénígba b. ægbönlénígba c. aárùnúndínlógúnlénígba d. àádôtalénígba

5. Oókàndínláàádôta àti àádôfà jê? a. oókànlélôgôjæ b. eéjìléláàdôjæ c. ÷êtàlélôgôjæ d. oókàndínlôgôjæ

6. Eéjì lônà àádôfà jê? a. ogúnlénígba b. ÷êtàlénígba c. àádôtalénígba d. eéjìlénígba

7. ¿êrin lônà aárùnúnlélægôfà jê? a. ëêdêgbëta b. ÷gbëta c. öôdúnrún d. ëêdêgbërin

8. ¿êtà læna ægôrùnún jê? a. igba b. öôdúnrún c. irínwó d. ÷êtàlénígba

9. Fi èéjì pín irínwó, ó jê? a. eéjìlénirínwó b. öôdúnrún c. ëêdêgbëta d. igba

10. Fi aárùnún pín ogúnlélêëêdêgbëta, ó jê? a. ÷êrìnlélôgôrùnún b. ÷êrìnléláàdôfà c. ÷êrìndínlôgôrùnún d. ÷êrìnlélêëêdêgbëta